Sentence view Universal Dependencies - Yoruba - YTB Language Yoruba Project YTB Corpus Part test Annotation Olúòkun, Adédayọ̀; Zeman, Daniel; Williams, Seyi; Ishola, Ọlájídé
Text: Transcription Written form - Colors
showing 1 - 100 of 118 • next
Ẹ̀gbà ọrùn bí ìbòju tí Benin jẹ́ ẹ̀gbà ọrùn tí wọ́n gbẹ́ lére tí ó sì jẹ́ àwòrán akọni obìrin tí a mọ̀ si ìyá wa Olorì Idia ti ọ̀rundún mẹ́rìndínlógún ṣẹ́yìn .
s-1
wiki0001
Ẹ̀gbà ọrùn bí ìbòju tí Benin jẹ́ ẹ̀gbà ọrùn tí wọ́n gbẹ́ lére tí ó sì jẹ́ àwòrán akọni obìrin tí a mọ̀ si ìyá wa Olorì Idia ti ọ̀rundún mẹ́rìndínlógún ṣẹ́yìn.
Ọmọ rẹ̀ Esigie tí ó jẹ́ ọba ti Benin maa ń wọ́ èyí tí ó jọọ́ fún àwọn ọmọ ogun ẹ̀yìn ìya olorì .
s-2
wiki0002
Ọmọ rẹ̀ Esigie tí ó jẹ́ ọba ti Benin maa ń wọ́ èyí tí ó jọọ́ fún àwọn ọmọ ogun ẹ̀yìn ìya olorì.
Ibojú yìí pé méjì tí ó jọ ara wọn : Ìkan wà ní Ilé ọnà ti a mọ̀ sí British Museum ní ìlú London tí ìkejì sì wà ní ilé ọnà tí a mọ̀ sí Metropolitan Museum of Art ní ìlú New York .
s-3
wiki0003
Ibojú yìí pé méjì tí ó jọ ara wọn: Ìkan wà ní Ilé ọnà ti a mọ̀ sí British Museum ní ìlú London tí ìkejì sì wà ní ilé ọnà tí a mọ̀ sí Metropolitan Museum of Art ní ìlú New York.
Àwọn àpẹẹrẹ rẹ̀ lórí àkọ́lé kan náà wà ní Seattle Art Museum àti Linden Museum , tí ìkan ná sì wà ní ilé ibi tí wọ́n kò gba òpò eniyan láyè láti wọ̀ , gbogbo rẹ̀ ní wọ́n kó nígbà ìwádí lọ sí ìlú Benin ní ọdún 1897 .
s-4
wiki0004
Àwọn àpẹẹrẹ rẹ̀ lórí àkọ́lé kan náà wà ní Seattle Art Museum àti Linden Museum, tí ìkan ná sì wà ní ilé ibi tí wọ́n kò gba òpò eniyan láyè láti wọ̀, gbogbo rẹ̀ ní wọ́n kó nígbà ìwádí lọ sí ìlú Benin ní ọdún 1897.
Ìbojú yìí ti di àmì ìdánimọ̀ lóde òní ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti ìgbà ìpéjọ - pọ̀ kan tí a mọ̀ sí FESTA C 77 tí ó wáyé ní ọdún 1977 .
s-5
wiki0005
Ìbojú yìí ti di àmì ìdánimọ̀ lóde òní ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti ìgbà ìpéjọ-pọ̀ kan tí a mọ̀ sí FESTAC 77 tí ó wáyé ní ọdún 1977.
Ìrísí àti Ìwúlò rẹ̀ .
s-6
wiki0006
Ìrísí àti Ìwúlò rẹ̀.
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó ní ìrísí èyí tí ó jọ Ìbojú Ìbílẹ̀ Aláwọ̀dúdú , ībòjú kékeré òhún tí kò gígùn rẹ̀ kò ju ìwòn 24cm lọ kìí ṣé fún wíwọ̀ sójú , Ọba lè wọ̀ọ́ sọ́rùn ( tí ó sì maa bá mu ) tàbí bi ' ìlẹ̀kẹ̀ ìbàdí ' ( èyí tí ó sì maa bá ayẹyẹ tí ó fẹ́ sẹe mu ) .
s-7
wiki0007
Bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó ní ìrísí èyí tí ó jọ Ìbojú Ìbílẹ̀ Aláwọ̀dúdú, ībòjú kékeré òhún tí kò gígùn rẹ̀ kò ju ìwòn 24cm lọ kìí ṣé fún wíwọ̀ sójú, Ọba lè wọ̀ọ́ sọ́rùn (tí ó sì maa bá mu) tàbí bi 'ìlẹ̀kẹ̀ ìbàdí' (èyí tí ó sì maa bá ayẹyẹ tí ó fẹ́ sẹe mu).
Èyí tí ó wà ní ilé ọnà Met àti èyí tí ó wà ní ilé ọnà British fẹ́ jọ ara wọn , méjèèjì ni ó jẹ́ àwòràn Olorì Idia .
s-8
wiki0008
Èyí tí ó wà ní ilé ọnà Met àti èyí tí ó wà ní ilé ọnà British fẹ́ jọ ara wọn, méjèèjì ni ó jẹ́ àwòràn Olorì Idia.
Wọn dárà ìlẹ̀kẹ̀ si lórí , lọ́rùn , ègbẹ́ níwájú orí àti gbígbẹ́ èyí tí ó fàyè ọ̀nà méjì tí wọ́n lè fi ẹ̀gbà kọ́ .
s-9
wiki0009
Wọn dárà ìlẹ̀kẹ̀ si lórí, lọ́rùn, ègbẹ́ níwájú orí àti gbígbẹ́ èyí tí ó fàyè ọ̀nà méjì tí wọ́n lè fi ẹ̀gbà kọ́.
Lóde òní àwọn ènìyàn máa ń gbé onírú irú àworan tí ó jọ́ọ níbi ayẹyẹ láti lé ẹbọra búrúkú , ṣùgbọ́n ní bí ọrundún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn , wọ́n lè maa lòó fún ayẹyẹ ìya ọba .
s-10
wiki0010
Lóde òní àwọn ènìyàn máa ń gbé onírú irú àworan tí ó jọ́ọ níbi ayẹyẹ láti lé ẹbọra búrúkú, ṣùgbọ́n ní bí ọrundún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn, wọ́n lè maa lòó fún ayẹyẹ ìya ọba.
Ó dàbí wípé ní bí ìbẹ̀rẹ̀ ọrúndún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn ni wọ́n gbẹ́ àwọn Ìbòjú méjèèjì , bóya ní ọdún 1520 , nígbà tí Olorì Idia , ìyá ọba Oba Esigie , jẹ́ aládájọ́ ní ilé ẹjọ́ ti Benin .
s-11
wiki0011
Ó dàbí wípé ní bí ìbẹ̀rẹ̀ ọrúndún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn ni wọ́n gbẹ́ àwọn Ìbòjú méjèèjì, bóya ní ọdún 1520, nígbà tí Olorì Idia, ìyá ọba Oba Esigie, jẹ́ aládájọ́ ní ilé ẹjọ́ ti Benin.
Akọni obìnrin .
s-12
wiki0012
Akọni obìnrin.
Irú àwòrán yìí kò wọ́pọ̀ ní iṣẹ́ ọnà ilẹ̀ Benin , àti pé ipò Idia , tí iṣẹ̀ṣe àwọn Edo mọ̀ sí ' obìnrin kan ṣoṣo tó lọ sógun ' , tí ó da yàtọ̀ , tí wọ́n sí dá oyèIyoba tàbí Ìyá Olori ̀́n sílẹ̀ fun Ìwérí rẹ̀ jẹ́ ara irú irun tí wọ́n ń pè ní ẹnu àparò , tí a lè rí dáadára ní àfihàn orí edẹ Olorì Idia .
s-13
wiki0013
Irú àwòrán yìí kò wọ́pọ̀ ní iṣẹ́ ọnà ilẹ̀ Benin, àti pé ipò Idia, tí iṣẹ̀ṣe àwọn Edo mọ̀ sí 'obìnrin kan ṣoṣo tó lọ sógun', tí ó da yàtọ̀, tí wọ́n sí dá oyèIyoba tàbí Ìyá Olori ̀́n sílẹ̀ fun Ìwérí rẹ̀ jẹ́ ara irú irun tí wọ́n ń pè ní ẹnu àparò, tí a lè rí dáadára ní àfihàn orí edẹ Olorì Idia.
Ìwérí rẹ̀ tí ó rẹwà àti ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn rẹ̀ bí ìlẹ̀kẹ̀ roboto ( ' ọlà ' ) , tí wọ́n fún ìya wa olorì láàfàní láti máa wọ̀ , léyí tí ó jẹ́ pé olóyè ni ówà fún .
s-14
wiki0014
Ìwérí rẹ̀ tí ó rẹwà àti ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn rẹ̀ bí ìlẹ̀kẹ̀ roboto ('ọlà'), tí wọ́n fún ìya wa olorì láàfàní láti máa wọ̀, léyí tí ó jẹ́ pé olóyè ni ówà fún.
Ìlẹ̀kẹ̀ pupa yìí àti aṣọ pupa , ti fìgbàkan wà fún àwọn olókìkí , tí wọ́n sì ti ri lóde òní gẹ́gẹ́ bi ara imùra ìbílẹ̀ ní Edo .
s-15
wiki0015
Ìlẹ̀kẹ̀ pupa yìí àti aṣọ pupa, ti fìgbàkan wà fún àwọn olókìkí, tí wọ́n sì ti ri lóde òní gẹ́gẹ́ bi ara imùra ìbílẹ̀ ní Edo.
Ní iwájú orí ìbòjú méjì yìí , ìlà mẹ́rin wà níbẹ̀ , tí ó sì dúro ṣangílítí sí òkè ojú kànkan , irin méjì sì ṣe àpèjúwe ilà yìí .
s-16
wiki0016
Ní iwájú orí ìbòjú méjì yìí, ìlà mẹ́rin wà níbẹ̀, tí ó sì dúro ṣangílítí sí òkè ojú kànkan, irin méjì sì ṣe àpèjúwe ilà yìí.
Irin ni wọ́n fi ṣe ibi ojú rẹ̀ .
s-17
wiki0017
Irin ni wọ́n fi ṣe ibi ojú rẹ̀.
Àmì fún okùn òwò .
s-18
wiki0018
Àmì fún okùn òwò.
Ibi funfun ìwò ẹ̀fọ̀ tí wọ́n fi ṣe ìwòjú yìí jẹ́ àpẹẹrẹ òòṣà Olokun .
s-19
wiki0019
Ibi funfun ìwò ẹ̀fọ̀ tí wọ́n fi ṣe ìwòjú yìí jẹ́ àpẹẹrẹ òòṣà Olokun.
Bí ó ṣe rí yìí , kò wọ́n nìkan nítórí wọ́n lọ ìwo ẹfọ̀ tí ó wúlò tí ó sì ṣeétà lówó gọbọhi , ṣùgbọ́n àwọ̀ rẹ̀ tún jẹ́ àpẹ́ẹrẹ òòṣà tí ó ní ṣ pẹ̀lú olá Oba Benin .
s-20
wiki0020
Bí ó ṣe rí yìí, kò wọ́n nìkan nítórí wọ́n lọ ìwo ẹfọ̀ tí ó wúlò tí ó sì ṣeétà lówó gọbọhi, ṣùgbọ́n àwọ̀ rẹ̀ tún jẹ́ àpẹ́ẹrẹ òòṣà tí ó ní ṣ pẹ̀lú olá Oba Benin.
Ihò tí ó wà ní ibi oun ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ àti ibi ọrùn rẹ̀ jẹ́ àpẹẹrẹ ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn tí àwọn ọkùnrin Àgùdà maa ń fi ṣẹ̀ṣọ́ , tí ó sì jẹ́ wípé àwòrán mọ́kànlá bẹ́ẹ̀ wà ní ilé ọnà ìbòjú tí Bìrìtìkó àti pé mẹ́tàlá wà ní ilé ọnà Met tí ó ṣe àfihàn àwọn ọkùnrin Àgùdá tí wọ́n múra bí àwọn ènìyàn dúdú .
s-21
wiki0021
Ihò tí ó wà ní ibi oun ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ àti ibi ọrùn rẹ̀ jẹ́ àpẹẹrẹ ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn tí àwọn ọkùnrin Àgùdà maa ń fi ṣẹ̀ṣọ́, tí ó sì jẹ́ wípé àwòrán mọ́kànlá bẹ́ẹ̀ wà ní ilé ọnà ìbòjú tí Bìrìtìkó àti pé mẹ́tàlá wà ní ilé ọnà Met tí ó ṣe àfihàn àwọn ọkùnrin Àgùdá tí wọ́n múra bí àwọn ènìyàn dúdú.
Orùn ìwòjú tí ó wà ní ilé ọnà Metropolitant ( Met ) jọ mọ́ èyí tí wọ́n fi àwọn ọkùnrin Àgùdà ṣẹ̀ṣọ́ rẹ̀ ( ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ti bàjẹ́ díẹ̀ ) , Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé , ọrùn ìwòjú èyí tí ó wà ní ilé ọnà Bìrìtìkó jẹ́ èyí tí wọ́n fi igi tàbí irin gbẹ́ .
s-22
wiki0022
Orùn ìwòjú tí ó wà ní ilé ọnà Metropolitant (Met) jọ mọ́ èyí tí wọ́n fi àwọn ọkùnrin Àgùdà ṣẹ̀ṣọ́ rẹ̀ (ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ti bàjẹ́ díẹ̀), Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé, ọrùn ìwòjú èyí tí ó wà ní ilé ọnà Bìrìtìkó jẹ́ èyí tí wọ́n fi igi tàbí irin gbẹ́.
Àwọn Àgùdà jẹ́ oníṣòwò pẹ̀lú àwọn Benin nígbàyẹn gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣàpèjúwe rẹ̀ , ó jẹ́ àpẹrẹ́ àjọṣepọ̀ láàrin omi àti ilẹ̀ .
s-23
wiki0023
Àwọn Àgùdà jẹ́ oníṣòwò pẹ̀lú àwọn Benin nígbàyẹn gẹ́gẹ́ bí wọ́n ti ṣàpèjúwe rẹ̀, ó jẹ́ àpẹrẹ́ àjọṣepọ̀ láàrin omi àti ilẹ̀.
Ẹ ti tẹ̀lé ìjápọ̀ mọ́ ojúewé tí kò sí .
s-24
wiki0024
Ẹ ti tẹ̀lé ìjápọ̀ mọ́ ojúewé tí kò sí.
Láti dá ojúewé yí ẹ bẹ̀rẹ̀ síní tẹ́kọ sí inú àpótí ìsàlẹ̀ yí ( ẹ wo ojúewé ìrànlọ́wọ́ fun ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ) .
s-25
wiki0025
Láti dá ojúewé yí ẹ bẹ̀rẹ̀ síní tẹ́kọ sí inú àpótí ìsàlẹ̀ yí (ẹ wo ojúewé ìrànlọ́wọ́ fun ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ).
T' óbá sepé àsìse ló gbé yin dé bi , ẹ kọn bọ́tìnì ìpadàsẹ́yìn .
s-26
wiki0026
T'óbá sepé àsìse ló gbé yin dé bi, ẹ kọn bọ́tìnì ìpadàsẹ́yìn.
Orúkọ dàbí àmì ìdánimọ̀ tí a fi ń dá ẹnìkọ̀ọ̀kan mọ̀ orúkọ ló jẹ́ kí á dá Táyé mọ̀ yàtọ̀ sí Kẹ́hìndé , káàkiri àgbáyé ní a sì tí ń lo orúkọ , ní ọ̀pọ̀ ìgbà orúkọ sì máa ń fi bí ènìyàn ṣe jẹ́ láwùjọ hàn àti wí pe orúkọ ẹni le buyì fún ènìyàn láwùjọ .
s-27
wiki0027
Orúkọ dàbí àmì ìdánimọ̀ tí a fi ń dá ẹnìkọ̀ọ̀kan mọ̀ orúkọ ló jẹ́ kí á dá Táyé mọ̀ yàtọ̀ sí Kẹ́hìndé, káàkiri àgbáyé ní a sì tí ń lo orúkọ, ní ọ̀pọ̀ ìgbà orúkọ sì máa ń fi bí ènìyàn ṣe jẹ́ láwùjọ hàn àti wí pe orúkọ ẹni le buyì fún ènìyàn láwùjọ.
Ìṣọmọlórúkọ láàárín àwọn Yorùbá dàbí ìgbà tí a ń ṣe ọdún ní torí pé tọmọ , taya , tẹbí , tará , tìyekan àti àwọn alábáse gbogbo ní yóò pésẹ̀ sí ibẹ̀ .
s-28
wiki0028
Ìṣọmọlórúkọ láàárín àwọn Yorùbá dàbí ìgbà tí a ń ṣe ọdún ní torí pé tọmọ, taya, tẹbí, tará, tìyekan àti àwọn alábáse gbogbo ní yóò pésẹ̀ sí ibẹ̀.
Láyé àtijọ́ ọjọ́ keje ní wọ́n máa ń sọ ọmọ obìnrin lórúkọ nígbà tí tọmọ kùnrin sì jẹ́ ọjọ́ kẹsàn - án èyí wà ní ìbámu pẹ̀lú èrò àti ìgbàgbọ́ wọn pé eegun méje ni obìnrin ní nígbà tí tọkùnrin jẹ́ mẹ́sàn-án .
s-29
wiki0029
Láyé àtijọ́ ọjọ́ keje ní wọ́n máa ń sọ ọmọ obìnrin lórúkọ nígbà tí tọmọ kùnrin sì jẹ́ ọjọ́ kẹsàn-án èyí wà ní ìbámu pẹ̀lú èrò àti ìgbàgbọ́ wọn pé eegun méje ni obìnrin ní nígbà tí tọkùnrin jẹ́ mẹ́sàn-án.
ṣùgbọ́n lóde - òní ohun gbogbo ti yí padà àti obìnrin àti ọkùnrin ni wọ́n ń sọ lórúkọ lọ́jẹ́ kẹjọ .
s-30
wiki0030
ṣùgbọ́n lóde-òní ohun gbogbo ti yí padà àti obìnrin àti ọkùnrin ni wọ́n ń sọ lórúkọ lọ́jẹ́ kẹjọ.
Bí a ṣe ń ṣe ìṣọmọlórúkọ yàtọ̀ láti idílẹ́ sí ìdílé ṣùgbọ́n ní ọjọ́ ìṣọmọlórúkọ yìí àgbà ilé lóbìnrin yóò gbé ọmọ yìí lọ́wọ́ yóò sì fí ẹsẹ̀ rẹ̀ tẹ ilẹ̀ .
s-31
wiki0031
Bí a ṣe ń ṣe ìṣọmọlórúkọ yàtọ̀ láti idílẹ́ sí ìdílé ṣùgbọ́n ní ọjọ́ ìṣọmọlórúkọ yìí àgbà ilé lóbìnrin yóò gbé ọmọ yìí lọ́wọ́ yóò sì fí ẹsẹ̀ rẹ̀ tẹ ilẹ̀.
Orísìírísìí nǹkan ní wọ́n ń lò níbi ìsọmọlórúkọ bíi Oyin , Epo , Iṣu , Ẹja ,
s-32
wiki0032
Orísìírísìí nǹkan ní wọ́n ń lò níbi ìsọmọlórúkọ bíi Oyin, Epo, Iṣu, Ẹja,
Iyọ̀ , Omi , abbl láti jẹ́ kí ọmọ yìí mọ bí ayé se rí wọn yóò fí gbogbo ohun tí a kà sókè yìí tọ́ ọmọ lẹ́nu wò , wọ́n sì máa ń wọ́n omi sí ọmọ yìí lára tàbí kí wọ́n da omi sí orí páànù kí wọn ó wá jẹ́ kí ó kán si ọmọ yìí lára .
s-33
wiki0033
Iyọ̀, Omi, abbl láti jẹ́ kí ọmọ yìí mọ bí ayé se rí wọn yóò fí gbogbo ohun tí a kà sókè yìí tọ́ ọmọ lẹ́nu wò, wọ́n sì máa ń wọ́n omi sí ọmọ yìí lára tàbí kí wọ́n da omi sí orí páànù kí wọn ó wá jẹ́ kí ó kán si ọmọ yìí lára.
Orúkọ dabí fèrèsé tí ó fi ÀṢÀ, Èsìn , Iṣé àti ìgbàgbọ́ àwọn Yorùbá hàn .
s-34
wiki0034
Orúkọ dabí fèrèsé tí ó fi ÀṢÀ, Èsìn, Iṣé àti ìgbàgbọ́ àwọn Yorùbá hàn.
Oríṣìíríṣìí nǹkan la fi ń sọmọ lórúkọ bíi OYIN, EPO , IYỌ , ẸJA , OMI abbl .
s-35
wiki0035
Oríṣìíríṣìí nǹkan la fi ń sọmọ lórúkọ bíi OYIN, EPO, IYỌ, ẸJA, OMI abbl.
Oríṣìíríṣìí nǹkan ló le yọrí sí orúkọ tí a sọ ọmọ .
s-36
wiki0036
Oríṣìíríṣìí nǹkan ló le yọrí sí orúkọ tí a sọ ọmọ.
Genevieve Nnaji ọjọ́ ìbí May 3 , 1979 ní Mbaise , Ipinle Imo , jẹ́ òṣeré filmu ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà .
s-37
wiki0037
Genevieve Nnaji ọjọ́ ìbí May 3, 1979 ní Mbaise, Ipinle Imo, jẹ́ òṣeré filmu ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà.
Ní 2005 ó gba Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà gẹ́gẹ́ bíi Òṣeré Obìnrin Dídárajùlọ .
s-38
wiki0038
Ní 2005 ó gba Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà gẹ́gẹ́ bíi Òṣeré Obìnrin Dídárajùlọ.
Ìgbà èwe : Ìlú Èkó ni Genevieve Nnaji ti dàgbà .
s-39
wiki0039
Ìgbà èwe: Ìlú Èkó ni Genevieve Nnaji ti dàgbà.
Ìkẹrin nínú àwọn ọmọ méjọ , ọ̀mọ̀wé ni àwọn òbí rẹ̀ .
s-40
wiki0040
Ìkẹrin nínú àwọn ọmọ méjọ, ọ̀mọ̀wé ni àwọn òbí rẹ̀.
Bàbá rẹ̀ siṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi onímọ̀ iṣẹ́ - ẹ̀rọ ( engineer) nígbàtí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ olùkọ́ .
s-41
wiki0041
Bàbá rẹ̀ siṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi onímọ̀ iṣẹ́-ẹ̀rọ (engineer) nígbàtí ìyá rẹ̀ sì jẹ́ olùkọ́.
Ò lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Methodist Girls College ní Yaba , lẹ́yìn rẹ̀ ó tẹrísí Yunifásítì ìlú Èkó .
s-42
wiki0042
Ò lọ sí ilé ẹ̀kọ́ Methodist Girls College ní Yaba, lẹ́yìn rẹ̀ ó tẹrísí Yunifásítì ìlú Èkó.
Níbẹ̀ lówà tó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ díèdíẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré ni Nollywood .
s-43
wiki0043
Níbẹ̀ lówà tó ti bẹ̀rẹ̀ sí ní ṣiṣẹ́ díèdíẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré ni Nollywood.
Nnaji bẹ̀rẹ̀ ìṣèré rẹ̀ láti ọmọdé ninu eré tẹlifísọ̀n Ripples nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 8 .
s-44
wiki0044
Nnaji bẹ̀rẹ̀ ìṣèré rẹ̀ láti ọmọdé ninu eré tẹlifísọ̀n Ripples nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 8.
Ó tún ṣe ìpolówó ọjà bíi méèló kan nínú èyí tó jẹ́ fún Pronto àti ọṣẹ ìfọsọ Omo .
s-45
wiki0045
Ó tún ṣe ìpolówó ọjà bíi méèló kan nínú èyí tó jẹ́ fún Pronto àti ọṣẹ ìfọsọ Omo.
Ní 2004 ó di aṣojú fún ọsẹ ìwẹ̀ Lux , ìbáṣe ìgbọ̀wọ́ tọ́ fa èrè ínlá wá fun .
s-46
wiki0046
Ní 2004 ó di aṣojú fún ọsẹ ìwẹ̀ Lux, ìbáṣe ìgbọ̀wọ́ tọ́ fa èrè ínlá wá fun.
Ni 1998 nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 19 wọn ṣe àmúhàn rẹ̀ sí àwọn olólùfẹ́ filmu ni Naijiria pẹ̀lú filmu tó ún jẹ́ Most Wanted .
s-47
wiki0047
Ni 1998 nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 19 wọn ṣe àmúhàn rẹ̀ sí àwọn olólùfẹ́ filmu ni Naijiria pẹ̀lú filmu tó ún jẹ́ Most Wanted.
Lẹ́yìn rẹ̀ ó tún ṣe àwọn filmu bíi Last Party , Mark of the Beast àti Ijele .
s-48
wiki0048
Lẹ́yìn rẹ̀ ó tún ṣe àwọn filmu bíi Last Party, Mark of the Beast àti Ijele.
Ó ti kópa nínúu filmu tó tó 80 ni Nollywood .
s-49
wiki0049
Ó ti kópa nínúu filmu tó tó 80 ni Nollywood.
Nnaji ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn fún iṣẹ́ rẹ̀ ìkan nínú wọn jẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré obìnrin tó dára jùlọ fún 2001 ní City People Awards , ó sì tún gba ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bíi Òṣèré Obìnrin Tódárajùlọ ní 2005 nínú àwọn Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà .
s-50
wiki0050
Nnaji ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn fún iṣẹ́ rẹ̀ ìkan nínú wọn jẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré obìnrin tó dára jùlọ fún 2001 ní City People Awards, ó sì tún gba ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bíi Òṣèré Obìnrin Tódárajùlọ ní 2005 nínú àwọn Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà.
Ní 2004 , ó tọwọ́bọ̀wé pẹ̀lú ilé ìṣẹ́ àwo - orin ilẹ̀ Ghana , EKB Records láti gbé àwo - orin àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde tó ún jẹ́ One Logologo Line , àdàlú orin R&B , Hip- Hop àti Urban .
s-51
wiki0051
Ní 2004, ó tọwọ́bọ̀wé pẹ̀lú ilé ìṣẹ́ àwo-orin ilẹ̀ Ghana, EKB Records láti gbé àwo-orin àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde tó ún jẹ́ One Logologo Line, àdàlú orin R&B, Hip-Hop àti Urban.
Ní 2008 ni ó ṣí ilé ìránsọ rẹ̀ tó ún jẹ́ ' St .
s-52
wiki0052
Ní 2008 ni ó ṣí ilé ìránsọ rẹ̀ tó ún jẹ́ 'St.
Genevieve ' , èyí tó ún ṣọrẹ ìdámẹ́ẹ̀wá èrè rẹ̀ .
s-53
wiki0053
Genevieve', èyí tó ún ṣọrẹ ìdámẹ́ẹ̀wá èrè rẹ̀.
Ní Nollywood, Genevieve Nnaji jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn tí owó iṣẹ́ wọn pọ̀jùlọ .
s-54
wiki0054
Ní Nollywood, Genevieve Nnaji jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn tí owó iṣẹ́ wọn pọ̀jùlọ.
Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè àti àṣà Yorùbá jẹ́ àgbárí- jọ- pọ Àwọn olùkọ́ nílé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ , girama àti ilé ẹ̀kọ́ fásitì ti ìjọba pẹ̀lú aládàáni jákè jádò ilẹ̀ Nàjíríà .
s-55
wiki0055
Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè àti àṣà Yorùbá jẹ́ àgbárí-jọ-pọ Àwọn olùkọ́ nílé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀, girama àti ilé ẹ̀kọ́ fásitì ti ìjọba pẹ̀lú aládàáni jákè jádò ilẹ̀ Nàjíríà.
Ẹgbẹ́ yìí ń ṣojú Yorùbá níbi ìgbé lárugẹ èdè , àṣà àti ìdàgbà sókè ìṣèṣe Yorùbá .
s-56
wiki0056
Ẹgbẹ́ yìí ń ṣojú Yorùbá níbi ìgbé lárugẹ èdè, àṣà àti ìdàgbà sókè ìṣèṣe Yorùbá.
Alhaji Lukman Ẹ̀bùn Olóyèdé Ọláìyá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Igwe jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti òṣèré sinimá àgbéléwò .
s-57
wiki0057
Alhaji Lukman Ẹ̀bùn Olóyèdé Ọláìyá tí gbogbo ènìyàn mọ̀ sí Igwe jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti òṣèré sinimá àgbéléwò.
Wọ́n bí Ẹ̀bùn Olóyèdé ní ilú Kẹ́nta , Òkè - Èjìgbò Abẹ́òkúta .
s-58
wiki0058
Wọ́n bí Ẹ̀bùn Olóyèdé ní ilú Kẹ́nta, Òkè-Èjìgbò Abẹ́òkúta.
Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀ : Ọláìyá lọ sí ilé ìwé alákọ̀ọ́bọẹ̀rẹ̀ St.Judes ní ìlú Abẹòkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn , tí ó sì tún tè síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ìwé girama ( Premier) ní Abẹ́òkúta .
s-59
wiki0059
Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀: Ọláìyá lọ sí ilé ìwé alákọ̀ọ́bọẹ̀rẹ̀ St.Judes ní ìlú Abẹòkúta ní ìpínlẹ̀ Ògùn, tí ó sì tún tè síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ní ilé ìwé girama (Premier) ní Abẹ́òkúta.
Lẹ́yìn tí ó parí èyí ni ó lọ kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìbára ẹni sọọ̀rọ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ gbogbo - nìṣe tí Moshood Abíọ́lá Òjéèrè ìpínlẹ̀ Ògùn .
s-60
wiki0060
Lẹ́yìn tí ó parí èyí ni ó lọ kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìbára ẹni sọọ̀rọ̀ ní ilé ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe tí Moshood Abíọ́lá Òjéèrè ìpínlẹ̀ Ògùn.
Iṣẹ́ rè gẹ́gẹ́ bí òṣèré : Ọláìyá dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré Musibau Shodimú ní àsìkò ọdún 1970s tí ó wà ní Abẹ́òkúta nígbà náà .
s-61
wiki0061
Iṣẹ́ rè gẹ́gẹ́ bí òṣèré: Ọláìyá dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré Musibau Shodimú ní àsìkò ọdún 1970s tí ó wà ní Abẹ́òkúta nígbà náà.
Ojúewé yìí ní ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ kan Wikipedia nínú .
s-62
wiki0062
Ojúewé yìí ní ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ kan Wikipedia nínú.
Ó jẹ́ èso ìfohùnṣọ̀kan , bẹ́ ẹ̀ sì ni ó jẹ́ gbígbàgbọ́ pé gbogbo àwọn oníṣe gbọ́dọ̀ tẹ̀lé wọn gbámúgbámú .
s-63
wiki0063
Ó jẹ́ èso ìfohùnṣọ̀kan, bẹ́ ẹ̀ sì ni ó jẹ́ gbígbàgbọ́ pé gbogbo àwọn oníṣe gbọ́dọ̀ tẹ̀lé wọn gbámúgbámú.
Ẹ le ṣàtúnṣe àkóónú ojúewé náà sùgbọ́n ẹ jọ̀wọ́ ọ mọ́ ṣe ìyípadà ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ kankan láì kọ́kọ́ filọ àwọn oníṣe yìókù .
s-64
wiki0064
Ẹ le ṣàtúnṣe àkóónú ojúewé náà sùgbọ́n ẹ jọ̀wọ́ ọ mọ́ ṣe ìyípadà ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ kankan láì kọ́kọ́ filọ àwọn oníṣe yìókù.
Ojú ewé yìí ní kúkurú : Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà Wikipédíà jẹ́ Ojú ewé tó tọ́ka sí ìlànà tí a gbọ́dọ̀ tẹ̀lé ní àwùjọ Wikipédíà .
s-65
wiki0065
Ojú ewé yìí ní kúkurú: Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà Wikipédíà jẹ́ Ojú ewé tó tọ́ka sí ìlànà tí a gbọ́dọ̀ tẹ̀lé ní àwùjọ Wikipédíà.
Ìmúlò yìí ṣe àpèjúwe bí a ṣe lè máa mú ìdàgbàsókè bá àwọn Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà Wikipédíà .
s-66
wiki0066
Ìmúlò yìí ṣe àpèjúwe bí a ṣe lè máa mú ìdàgbàsókè bá àwọn Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà Wikipédíà.
Àwùjọ Wikipédíà ṣe Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà yìí lati ṣe àpèjúwe ọ̀nàn tó dára jùlọ lati ṣàgbékalẹ́ ọ̀rọ̀ , yanjú ìjà àti lati mú ìtẹ̀síwájú bá ìlépa wa fún ṣiṣẹda ìmọ ọfẹ .
s-67
wiki0067
Àwùjọ Wikipédíà ṣe Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà yìí lati ṣe àpèjúwe ọ̀nàn tó dára jùlọ lati ṣàgbékalẹ́ ọ̀rọ̀, yanjú ìjà àti lati mú ìtẹ̀síwájú bá ìlépa wa fún ṣiṣẹda ìmọ ọfẹ.
Kò pọn dandan lati ka Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà ojú ewé yìí lati bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ṣíṣàtúnkọ .
s-68
wiki0068
Kò pọn dandan lati ka Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà ojú ewé yìí lati bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ṣíṣàtúnkọ.
Orígun máàrún Wikipédíà ṣe àlàyé ránpẹ́ nípa ìlànà Wikipédíà .
s-69
wiki0069
Orígun máàrún Wikipédíà ṣe àlàyé ránpẹ́ nípa ìlànà Wikipédíà.
Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ wípé Wikipédíà Kò ní gba lílé ati sáré òfin , àwọn ojú ewé Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà ti ṣàgbékalẹ́ bí ohun gbogbo ṣe gbọ́dọ̀ máa lọ .
s-70
wiki0070
Bí ó ti lẹ̀ jẹ́ wípé Wikipédíà Kò ní gba lílé ati sáré òfin, àwọn ojú ewé Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà ti ṣàgbékalẹ́ bí ohun gbogbo ṣe gbọ́dọ̀ máa lọ.
Ìmúlò ṣe àlàyé àwọn ìlànà tí alàtúnkọ gbọ́dọ̀ tẹ̀lé ní àwùjọ Wikipédíà .
s-71
wiki0071
Ìmúlò ṣe àlàyé àwọn ìlànà tí alàtúnkọ gbọ́dọ̀ tẹ̀lé ní àwùjọ Wikipédíà.
Bakan náà ni ìtọ́nisọ́nà ṣe àlàyé ọ̀nàn tí a yàn lááyò lati tẹ̀lé ìlànà yìí .
s-72
wiki0072
Bakan náà ni ìtọ́nisọ́nà ṣe àlàyé ọ̀nàn tí a yàn lááyò lati tẹ̀lé ìlànà yìí.
A gbọ́dọ̀ máa lo ìtọ́nisọ́nà pẹ̀lú láákáyè .
s-73
wiki0073
A gbọ́dọ̀ máa lo ìtọ́nisọ́nà pẹ̀lú láákáyè.
Àjọ kòsí fún èrè Wikimedia Foundation ni ó n se alàkóso Wikipédíà pẹ̀lú àwọn òfin kan ( wo ibí fún àkójọ Ìmúlò ) .
s-74
wiki0074
Àjọ kòsí fún èrè Wikimedia Foundation ni ó n se alàkóso Wikipédíà pẹ̀lú àwọn òfin kan (wo ibí fún àkójọ Ìmúlò).
Tún wo Ipa Jimmy Wales ṣùgbọn , Wikipédíà ṣàkóso ara ẹ̀ nipase oníwé àwùjọ .
s-75
wiki0075
Tún wo Ipa Jimmy Wales ṣùgbọn, Wikipédíà ṣàkóso ara ẹ̀ nipase oníwé àwùjọ.
Ìmúlò jẹ́ ohun tí gbogbo alàtúnkọ gbà .
s-76
wiki0076
Ìmúlò jẹ́ ohun tí gbogbo alàtúnkọ gbà.
Osì tún se àpèjúwe ìlànà tí a gbọ́dọ̀ tẹ̀lé ní àwùjọ .
s-77
wiki0077
Osì tún se àpèjúwe ìlànà tí a gbọ́dọ̀ tẹ̀lé ní àwùjọ.
Gbogbo ojú ewé ìmúlò wà ní Wikipédíà :
s-78
wiki0078
Gbogbo ojú ewé ìmúlò wà ní Wikipédíà:
Gbogbo ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà àti .
s-79
wiki0079
Gbogbo ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà àti.
Fún kúkurú ojúlówó àwọn ìmúlò , wo Wikipédíà :
s-80
wiki0080
Fún kúkurú ojúlówó àwọn ìmúlò, wo Wikipédíà:
Wikipedia Yorùbá únlo àwọn ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ tó wà fún Wikipedia èdè Gẹ̀ẹ́sì .
s-82
wiki0082
Wikipedia Yorùbá únlo àwọn ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ tó wà fún Wikipedia èdè Gẹ̀ẹ́sì.
Tí ẹ bá fẹ́ ẹ lè lọ sí ojúewé ọ̀rọ̀ rẹ̀ láti fọ̀rọ̀wérọ̀ nípa wọn tàbí dámọ̀ràn ìpínu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ míràn .
s-83
wiki0083
Tí ẹ bá fẹ́ ẹ lè lọ sí ojúewé ọ̀rọ̀ rẹ̀ láti fọ̀rọ̀wérọ̀ nípa wọn tàbí dámọ̀ràn ìpínu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ míràn.
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́ .
s-84
wiki0084
Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tí tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́.
Ojúewé yìí lọ́wọ́lọ́wọ́ jẹ́ dídá àbò bò díẹ̀ nítoríẹ̀ àwọn oníṣe aforúkọsílẹ̀ tí wọ́n ti fẹsẹ̀múlẹ̀ nìkan ni wọ́n le ṣàtúnṣe rẹ̀ .
s-85
wiki0085
Ojúewé yìí lọ́wọ́lọ́wọ́ jẹ́ dídá àbò bò díẹ̀ nítoríẹ̀ àwọn oníṣe aforúkọsílẹ̀ tí wọ́n ti fẹsẹ̀múlẹ̀ nìkan ni wọ́n le ṣàtúnṣe rẹ̀.
Kílódé tí ojúewé ṣe ní àbò ?
s-86
wiki0086
Kílódé tí ojúewé ṣe ní àbò?
Bó tilẹ jẹ́ pé ọ̀pọ̀ àwọn àyọkà ni wọ́n le jẹ́ títúnṣe látọwọ́ olúkúlùkù , àbò díẹ̀ pọndandan ní gbà míi láti dínà ìbàjẹ́ sí àwọn ojúewé tó gbajúmọ̀ .
s-87
wiki0087
Bó tilẹ jẹ́ pé ọ̀pọ̀ àwọn àyọkà ni wọ́n le jẹ́ títúnṣe látọwọ́ olúkúlùkù, àbò díẹ̀ pọndandan ní gbà míi láti dínà ìbàjẹ́ sí àwọn ojúewé tó gbajúmọ̀.
Ìdí fún àbò wà nínú àkọọ́lẹ̀ àbo .
s-88
wiki0088
Ìdí fún àbò wà nínú àkọọ́lẹ̀ àbo.
Tí kò bá sí àkọsílẹ̀ abáramu nínú àkọọ́lẹ̀ àbò , ojúewé náà le ti jẹ́ yíyí nípò dà lẹ́yìn ìṣe àbò si .
s-89
wiki0089
Tí kò bá sí àkọsílẹ̀ abáramu nínú àkọọ́lẹ̀ àbò, ojúewé náà le ti jẹ́ yíyí nípò dà lẹ́yìn ìṣe àbò si.
Kíni mo le ṣe ?
s-90
wiki0090
Kíni mo le ṣe?
Tí ẹ bá ní àkópamọ́ oníṣe ẹ kọ́kọ́ wọlẹ́ .
s-91
wiki0091
Tí ẹ bá ní àkópamọ́ oníṣe ẹ kọ́kọ́ wọlẹ́.
Tí ẹ kò bá ní àkópamọ́ , ẹ le dá ìkan ; lẹ́yìn ọjọ́ 4 àti àtúnṣe 10 , ẹ ó le ṣàtúnṣe àwọn ojúewé àbò díẹ̀ .
s-92
wiki0092
Tí ẹ kò bá ní àkópamọ́, ẹ le dá ìkan; lẹ́yìn ọjọ́ 4 àti àtúnṣe 10, ẹ ó le ṣàtúnṣe àwọn ojúewé àbò díẹ̀.
Ẹ sọ̀rọ̀ nípa ojúewé yìí pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn .
s-93
wiki0093
Ẹ sọ̀rọ̀ nípa ojúewé yìí pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn.
Ẹ tọrọ ìjáwọ́ àbò ojúewé náà .
s-94
wiki0094
Ẹ tọrọ ìjáwọ́ àbò ojúewé náà.
Ẹ ka bí ẹ ṣele bẹ̀rẹ̀ síní ṣàtúnṣe Wikipedia .
s-95
wiki0095
Ẹ ka bí ẹ ṣele bẹ̀rẹ̀ síní ṣàtúnṣe Wikipedia.
Tí ẹ bá ṣàkíyèsí àsìṣe tàbí ẹ ní àbá fún àtúnṣe , ẹ le tọrọ àtúnṣe , nípa títẹ klik sí àjápọ̀ ìsàlẹ̀ , kí ẹ sì tẹ̀lẹ́ àwọn ìlànà ibẹ̀ .
s-96
wiki0096
Tí ẹ bá ṣàkíyèsí àsìṣe tàbí ẹ ní àbá fún àtúnṣe, ẹ le tọrọ àtúnṣe, nípa títẹ klik sí àjápọ̀ ìsàlẹ̀, kí ẹ sì tẹ̀lẹ́ àwọn ìlànà ibẹ̀.
Alámùójútó kan yíò ṣe àtúnṣe náà fun yín .
s-97
wiki0097
Alámùójútó kan yíò ṣe àtúnṣe náà fun yín.
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kọ́kọ́ wọ ojúewé ìfọ̀rọ̀wérọ̀ àyọkà náà , bóyá ọ̀rọ̀ ùnlọ nípa rẹ̀ .
s-98
wiki0098
Ẹ jọ̀wọ́ ẹ kọ́kọ́ wọ ojúewé ìfọ̀rọ̀wérọ̀ àyọkà náà, bóyá ọ̀rọ̀ ùnlọ nípa rẹ̀.
Àdírẹ́ẹ̀sì e - mail yín kò ṣe dandan , ṣùgbọ́n yíò jẹ́ lílò fún ìtúntò ọ̀rọ̀ìpamọ́ , tí ẹ bá gbàgbé ọ̀rọ̀ìpamọ́ yín .
s-99
wiki0099
Àdírẹ́ẹ̀sì e-mail yín kò ṣe dandan, ṣùgbọ́n yíò jẹ́ lílò fún ìtúntò ọ̀rọ̀ìpamọ́, tí ẹ bá gbàgbé ọ̀rọ̀ìpamọ́ yín.
Ẹ tún le yàn láti jẹ́ kí àwọn míràn ó bá a yín pàdé pẹ̀lú e - mail láti inú àjápọ̀ lórí ojúewé oníṣe tàbí ọ̀rọ̀ yín .
s-100
wiki0100
Ẹ tún le yàn láti jẹ́ kí àwọn míràn ó bá a yín pàdé pẹ̀lú e-mail láti inú àjápọ̀ lórí ojúewé oníṣe tàbí ọ̀rọ̀ yín.
Edit as list • Text view • Dependency trees