Sentence view
Universal Dependencies - Yoruba - YTB
Language | Yoruba |
---|
Project | YTB |
---|
Corpus Part | test |
---|
Annotation | Olúòkun, Adédayọ̀; Zeman, Daniel; Williams, Seyi; Ishola, Ọlájídé |
---|
showing 101 - 200 of 118 • previous
Àdírẹ́ẹ̀sì e-mail yín kò ní hàn síta nígbà tí àwọn oníṣe míràn bá a yín pàdé.
s-101
wiki0101
Àdírẹ́ẹ̀sì e-mail yín kò ní hàn síta nígbà tí àwọn oníṣe míràn bá a yín pàdé.
Kò sì áwọ́n iyipada ni akókò yì ti o ba àwon ìlànà yí mu.
s-102
wiki0102
Kò sì áwọ́n iyipada ni akókò yì ti o ba àwon ìlànà yí mu.
Lọ́wọ́lọ́wọ́ kò sí ìkọ̀ nínú ojúewé yìí.
s-103
wiki0103
Lọ́wọ́lọ́wọ́ kò sí ìkọ̀ nínú ojúewé yìí.
Ẹ le wá àkọlé ojúewé yìí nínú àwọn ojúewé mìíràn, tàbí wá àwọn àkọọ́lẹ̀ tó bámu, sùgbọ́n ẹ kò ní àṣẹ láti ṣ'ẹ̀dá ojúewé yìí.
s-104
wiki0104
Ẹ le wá àkọlé ojúewé yìí nínú àwọn ojúewé mìíràn, tàbí wá àwọn àkọọ́lẹ̀ tó bámu, sùgbọ́n ẹ kò ní àṣẹ láti ṣ'ẹ̀dá ojúewé yìí.
Robert Lavinsky, PhD, ti ṣọrẹ ibùdó dátà gbogbo àwọ àwòrán rẹ̀ ní mindat.org (ó tó bíi 29,000) àti gbogbo àwọn àwòrán láti ibi ojúewé ìtakùn rẹ̀ irocks.com fún Wikimedia Commons.
s-105
wiki0105

Bákanáà ó tún ti ṣe ìfilọ̀ iye àwórán bíi 20,000 láti inú ìkápamọ́ rẹ̀ fún lílò bóbá ṣe yẹ.
s-106
wiki0106
Bákanáà ó tún ti ṣe ìfilọ̀ iye àwórán bíi 20,000 láti inú ìkápamọ́ rẹ̀ fún lílò bóbá ṣe yẹ.
À únfẹ́ ìrànlọ́wọ́ láti ṣe ìyípadà ìjúwe gbogbo àwọn àwòrán náà, ṣíṣèyẹ̀wò wọn ní irocks.com bóyá àwòrán kan kò sí, àti láti rù wọ́n sókè sí Commons.
s-107
wiki0107

Ẹ le kà nípa bí ẹ ṣe le ràn wá lọ́wọ́ níbí.
s-108
wiki0108
Ẹ le kà nípa bí ẹ ṣe le ràn wá lọ́wọ́ níbí.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.
s-109
wiki0109
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí.
Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́.
s-110
wiki0110
Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́.
Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.
s-111
wiki0111
Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ.
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́.
s-112
wiki0112
Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́.
Ẹ wo Àwọn Ọ̀rọ̀ Àdéhùn Ìlò fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.
s-113
wiki0113
Ẹ wo Àwọn Ọ̀rọ̀ Àdéhùn Ìlò fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.
Ní ayé àtijọ́ àwọn onímọ́ ìṣirò mọ nọ́mbà tóṣòro gẹ́gẹ́ bíi nọ́mbà tí kòsí.
s-114
wiki0114
Ní ayé àtijọ́ àwọn onímọ́ ìṣirò mọ nọ́mbà tóṣòro gẹ́gẹ́ bíi nọ́mbà tí kòsí.
A lè sọ pé àwón nọ́mbà gidi je nọ́mbà tósòro pelu apá tíkòsi´ tó jé òdo; eyun pé nọ́mbà gidi a jẹ́ bakanna mọ́ nọ́mbà tósòro a+0i.
s-115
wiki0115

Fún àpẹrẹ, 3 + 2i jé nọ́mbà tósòro, pẹ̀lú apá gidi to jẹ 3 ati apá tíkòsi´ to jẹ 2.
s-116
wiki0116
Fún àpẹrẹ, 3 + 2i jé nọ́mbà tósòro, pẹ̀lú apá gidi to jẹ 3 ati apá tíkòsi´ to jẹ 2.
Àwon nọ́mbà tósòro se ròpọ̀, yọkúrò, sọdipúpọ̀ tàbi sèpínpiń gẹ́gẹ́ bi a ti n se fun àwon nọ́mbà gidi, be ni wón sì ní ìdámọ̀ tó lẹ́wà mìíràn.
s-117
wiki0117

Fún àpẹrẹ, nọ́mbà gidi nìkan kò ní ojúùtú fún ìdọ́gba aljebra alápọ̀ọ́nlépúpọ̀ (polynomial) pẹ̀lú nọ́mbà àfise gidi (coefficient), sùgbọ̀n àwọn nọ́mbà tósòro ní.
s-118
wiki0118

Edit as list • Text view • Dependency trees