yo-ytb-test-MARK_5

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest
AnnotationOlúòkun, Adédayọ̀; Zeman, Daniel; Williams, Seyi; Ishola, Ọlájídé

Javascript seems to be turned off, or there was a communication error. Turn on Javascript for more display options.

index sentence 1 - 6 > sentence 7 - 17

Wọn lọ si apákejì adágún ẹba ilẹ̀ àwọn ará Gádárà. Jésù ti ń ti inú ọkọ̀ ojú omi jáde. Ọkùnrin kan ó ẹ̀mí àìmọ́ jáde ti ibojì pàdé rẹ̀. Ọkùnrin yìí ń gbé nínú ìbojì, ẹni ó é mọ́, kódà ẹ̀wọ̀n le é. Nítorí nígbà púpọ̀ ni wọn ti ń fi ṣẹ́kẹ́sẹkẹ̀ é lọ́wọ́ àti ẹṣẹ̀, ó ń a dànù kúrò ni ẹṣẹ rẹ. ẹnìkan ó agbára láti káwọ́ rẹ̀. Tọ̀sán-tòru láàrin àwọn ibojì àti àwọn òkè ni ó máa ń kígbe rara ó ń fi òkúta ya ara rẹ̀. Nígbà ó Jésù látòkèrè, ó sáré lọ láti pàdé rẹ̀. Ó wólẹ̀ níwájú rẹ̀.

Download XMLDownload textSentence viewDependency trees