Dependency Tree
Universal Dependencies - Yoruba - YTB
Language | Yoruba |
---|
Project | YTB |
---|
Corpus Part | test |
---|
Annotation | Olúòkun, Adédayọ̀; Zeman, Daniel; Williams, Seyi; Ishola, Ọlájídé |
---|
Select a sentence
s-1
| Olúwa àyà mí kò gbéga bẹ́ẹ̀ ní ojú mi kò gbé sókè: bẹ́ẹ̀ ni èmi kò fi ọwọ́ mi lé ọ̀ràn ńlá, tàbí lé ohun tí ó ga jù mí lọ |
s-2
| Nítòótọ́ èmi mú ọkàn mi sinmi, mo sì mú-un dákẹ́jẹ́ẹ́, bí ọmọ tí a fi ọwọ ìyá Rẹ̀ gbà ní ẹnu ọmú: ọkàn mí rí gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí a já ní ẹnu ọmú. |
s-3
| Ísírẹ́lì, ìwọ ní ìrètí ní ti Olúwa láti ìsinsinyí lọ àti láéláé. |
Text view
•
Download CoNNL-U