Dependency Tree

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest
AnnotationOlúòkun, Adédayọ̀; Zeman, Daniel; Williams, Seyi; Ishola, Ọlájídé

Select a sentence

Showing 101 - 200 of 118 • previous

s-101 Àdírẹ́ẹ̀sì e-mail yín hàn síta nígbà àwọn oníṣe míràn a yín pàdé.
s-102 áwọ́n iyipada ni akókò ti o ba àwon ìlànà mu.
s-103 Lọ́wọ́lọ́wọ́ ìkọ̀ nínú ojúewé yìí.
s-104 le àkọlé ojúewé yìí nínú àwọn ojúewé mìíràn, tàbí àwọn àkọọ́lẹ̀ bámu, sùgbọ́n àṣẹ láti ṣ'ẹ̀dá ojúewé yìí.
s-105 Robert Lavinsky, PhD, ti ṣọrẹ ibùdó dátà gbogbo àwọ àwòrán rẹ̀ mindat.org (ó bíi 29,000) àti gbogbo àwọn àwòrán láti ibi ojúewé ìtakùn rẹ̀ irocks.com fún Wikimedia Commons.
s-106 Bákanáà ó tún ti ṣe ìfilọ̀ iye àwórán bíi 20,000 láti inú ìkápamọ́ rẹ̀ fún lílò bóbá ṣe yẹ.
s-107 À únfẹ́ ìrànlọ́wọ́ láti ṣe ìyípadà ìjúwe gbogbo àwọn àwòrán náà, ṣíṣèyẹ̀wò wọn irocks.com bóyá àwòrán kan , àti láti wọ́n sókè Commons.
s-108 le nípa ṣe le ràn lọ́wọ́ níbí.
s-109 Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe .
s-110 le fẹ̀ báyìí lọ tàbí ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà yíò mu kúnrẹ́rẹ́.
s-111 ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ báyìí lọ.
s-112 Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́.
s-113 wo Àwọn Ọ̀rọ̀ Àdéhùn Ìlò fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́.
s-114 ayé àtijọ́ àwọn onímọ́ ìṣirò mọ nọ́mbà tóṣòro gẹ́gẹ́ bíi nọ́mbà kòsí.
s-115 A sọ àwón nọ́mbà gidi je nọ́mbà tósòro pelu apá tíkòsi´ òdo; eyun nọ́mbà gidi a jẹ́ bakanna mọ́ nọ́mbà tósòro a+0i.
s-116 Fún àpẹrẹ, 3 + 2i nọ́mbà tósòro, pẹ̀lú apá gidi to jẹ 3 ati apá tíkòsi´ to jẹ 2.
s-117 Àwon nọ́mbà tósòro se ròpọ̀, yọkúrò, sọdipúpọ̀ tàbi sèpínpiń gẹ́gẹ́ bi a ti n se fun àwon nọ́mbà gidi, be ni wón ìdámọ̀ lẹ́wà mìíràn.
s-118 Fún àpẹrẹ, nọ́mbà gidi nìkan ojúùtú fún ìdọ́gba aljebra alápọ̀ọ́nlépúpọ̀ (polynomial) pẹ̀lú nọ́mbà àfise gidi (coefficient), sùgbọ̀n àwọn nọ́mbà tósòro .

Text viewDownload CoNNL-U