Dependency Tree
Universal Dependencies - Yoruba - YTB
Language | Yoruba |
---|
Project | YTB |
---|
Corpus Part | test |
---|
Annotation | Olúòkun, Adédayọ̀; Zeman, Daniel; Williams, Seyi; Ishola, Ọlájídé |
---|
Select a sentence
s-1
| Kíyèsí, ó ti dára ó sì ti dùn tó fún àwọn ará láti máa jùmọ̀ gbé ní ìrẹ́pọ̀. |
s-2
| Ó dàbí òróró ìkúnra iyebíye ní orí, tí ó ṣàn dé irungbọ̀n, àní irungbọ̀n Árónì: tí ó sì ṣàn sí etí aṣọ sórí Rẹ̀; |
s-3
| Bí irì Hémónì tí o ṣàn sórí òke Síónì: nítorí níbẹ̀ ní Olúwa gbé pàṣẹ ìbùkún, àni ìyè láéláé. |
Text view
•
Download CoNNL-U