Sentence view

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest
AnnotationOlúòkun, Adédayọ̀; Zeman, Daniel; Williams, Seyi; Ishola, Ọlájídé

Text: -


[1] tree
Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo fún yín, Ẹni gba ẹnu ọ̀nà wọ inú agbo àgùntàn, ṣùgbọ́n ó gba ibòmíràn gun òkè, Òun náà ni olè àti ọlọ́sà.
s-1
JOHN_10.1
“Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo wí fún yín, Ẹni tí kò bá gba ẹnu ọ̀nà wọ inú agbo àgùntàn, ṣùgbọ́n tí ó bá gba ibòmíràn gun òkè, Òun náà ni olè àti ọlọ́sà.
Verily, verily, I say unto you, He that entereth not by the door into the sheepfold, but climbeth up some other way, the same is a thief and a robber.
[2] tree
Ṣùgbọ́n ẹni ó ti ẹnu-ọ̀nà wọlé, Òun ni olùṣọ́ àwọn àgùntàn.
s-2
JOHN_10.2
Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ti ẹnu-ọ̀nà wọlé, Òun ni olùṣọ́ àwọn àgùntàn.
But he that entereth in by the door is the shepherd of the sheep.
[3] tree
Òun ni osọ́nà yóò ṣí ìlẹ̀kùn fún; àwọn àgùntàn gbọ́ ohùn rẹ̀: ó pe àwọn àgùntàn tirẹ̀ lórúkọ , ó se amọ̀nà wọn jáde.
s-3
JOHN_10.3
Òun ni osọ́nà yóò ṣí ìlẹ̀kùn fún; àwọn àgùntàn gbọ́ ohùn rẹ̀: ó sì pe àwọn àgùntàn tirẹ̀ lórúkọ, ó sì se amọ̀nà wọn jáde.
To him the porter openeth; and the sheep hear his voice: and he calleth his own sheep by name, and leadeth them out.
[4] tree
Nígbà ó ti àwọn àgùntàn tirẹ̀ jáde, yóò ṣíwájú wọn, àwọn àgùntàn yóò máa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn: nítorí wọ́n mọ ohùn rẹ̀.
s-4
JOHN_10.4
Nígbà tí ó bá sì ti mú àwọn àgùntàn tirẹ̀ jáde, yóò ṣíwájú wọn, àwọn àgùntàn yóò sì máa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn: nítorí tí wọ́n mọ ohùn rẹ̀.
And when he putteth forth his own sheep, he goeth before them, and the sheep follow him: for they know his voice.
[5] tree
Wọn jẹ́ tọ àlejò lẹ́yìn, ṣùgbọ́n wọn a kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀: nítorí wọn mọ ohùn àlejò.
s-5
JOHN_10.5
Wọn kò jẹ́ tọ àlejò lẹ́yìn, ṣùgbọ́n wọn a sá kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀: nítorí tí wọn kò mọ ohùn àlejò.”
And a stranger will they not follow, but will flee from him: for they know not the voice of strangers.
[6] tree
Òwe yìí ni Jésù pa fún wọn: ṣùgbọ́n òye ohun nǹkan wọ̀nyí jẹ́ ó ń sọ fún wọn wọn.
s-6
JOHN_10.6
Òwe yìí ni Jésù pa fún wọn: ṣùgbọ́n òye ohun tí nǹkan wọ̀nyí jẹ́ tí ó ń sọ fún wọn kò yé wọn.
This parable spake Jesus unto them: but they understood not what things they were which he spake unto them.
[7] tree
Nítorí náà Jésù tún fún wọn , Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo fún yín, Èmi ni ìlẹ̀kùn àwọn àgùntàn.
s-7
JOHN_10.7
Nítorí náà Jésù tún wí fún wọn pé, “Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo wí fún yín, Èmi ni ìlẹ̀kùn àwọn àgùntàn.
Then said Jesus unto them again, Verily, verily, I say unto you, I am the door of the sheep.
[8] tree
Olè àti ọlọ́sà ni gbogbo àwọn ó ti ṣáájú mi: ṣùgbọ́n àwọn àgùntàn gbọ́ ti wọn.
s-8
JOHN_10.8
Olè àti ọlọ́sà ni gbogbo àwọn tí ó ti wà ṣáájú mi: ṣùgbọ́n àwọn àgùntàn kò gbọ́ ti wọn.
All that ever came before me are thieves and robbers: but the sheep did not hear them.
[9] tree
Èmi ni ìlẹ̀kùn: ẹnìkan ọ̀dọ̀ mi wọlé, Òun ni a ó gbà , yóò wọlé, yóò jáde, yóò koríko.
s-9
JOHN_10.9
Èmi ni ìlẹ̀kùn: bí ẹnìkan bá bá ọ̀dọ̀ mi wọlé, Òun ni a ó gbà là, yóò wọlé, yóò sì jáde, yóò sì rí koríko.
I am the door: by me if any man enter in, he shall be saved, and shall go in and out, and find pasture.
[10] tree
Olè kìí ṣe láti jalè, láti pa, àti láti parun: èmi wọn ìyè, àní wọn i lọ́pọ̀lọpọ̀.
s-10
JOHN_10.10
Olè kìí wá bí kò ṣe láti jalè, láti pa, àti láti parun: èmi wá kí wọn lè ní ìyè, àní kí wọn lè ní i lọ́pọ̀lọpọ̀.
The thief cometh not, but for to steal, and to kill, and to destroy: I am come that they might have life, and that they might have it more abundantly.
[11] tree
Èmi ni olùṣọ́ àgùntàn rere: olùṣọ́-àgùntàn rere fi ọkàn rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn àgùntàn.
s-11
JOHN_10.11
“Èmi ni olùṣọ́ àgùntàn rere: olùṣọ́-àgùntàn rere fi ọkàn rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn àgùntàn.
I am the good shepherd: the good shepherd giveth his life for the sheep.
[12] tree
Ṣùgbọ́n alágbàṣe, kìí ṣe olùṣọ́ àgùntàn, ẹni àwọn àgùntàn kìí ṣe tirẹ̀, ó ìkokò ń bọ̀, ó fi àgùntàn sílẹ̀, ó fọ́n wọn kiri.
s-12
JOHN_10.12
Ṣùgbọ́n alágbàṣe, tí kìí ṣe olùṣọ́ àgùntàn, ẹni tí àwọn àgùntàn kìí ṣe tirẹ̀, ó rí ìkokò ń bọ̀, ó sì fi àgùntàn sílẹ̀, ó sì fọ́n wọn ká kiri.
But he that is an hireling, and not the shepherd, whose own the sheep are not, seeth the wolf coming, and leaveth the sheep, and fleeth: and the wolf catcheth them, and scattereth the sheep.
[13] tree
Òun lọ nítorí ó jẹ́ alágbàṣe, náání àwọn àgùntàn.
s-13
JOHN_10.13
Òun sá lọ nítorí tí ó jẹ́ alágbàṣe, kò sì náání àwọn àgùntàn.
The hireling fleeth, because he is an hireling, and careth not for the sheep.
[14] tree
Èmi àwọn àgùntàn mìíràn, kìí ṣe agbo yìí: àwọn ni èmi yóò pẹ̀lú, wọn ó gbọ́ ohùn mi; wọn ó jẹ́ agbo kan, olùsọ́-àgùntàn kan.
s-14
JOHN_10.16
Èmi sì ní àwọn àgùntàn mìíràn, tí kìí ṣe agbo yìí: àwọn ni èmi yóò mú wá pẹ̀lú, wọn ó sì gbọ́ ohùn mi; wọn ó sì jẹ́ agbo kan, olùsọ́-àgùntàn kan.
And other sheep I have, which are not of this fold: them also I must bring, and they shall hear my voice; and there shall be one fold, and one shepherd.
[15] tree
Nítorí náà ni Baba mi ṣe fẹ́ràn mi, nítorí mo fi ẹ̀mí mi lélẹ̀, èmi tún gbà á.
s-15
JOHN_10.17
Nítorí náà ni Baba mi ṣe fẹ́ràn mi, nítorí tí mo fi ẹ̀mí mi lélẹ̀, kí èmi lè tún gbà á.
Therefore doth my Father love me, because I lay down my life, that I might take it again.
[16] tree
Ẹnìkan gbà á lọ́wọ́ mi, ṣùgbọ́n mo fi í lélẹ̀, mo lágbára láti tún gbà á. Àṣẹ yìí ni mo ti gbà láti ọ̀dọ̀ Baba mi.
s-16
JOHN_10.18
Ẹnìkan kò gbà á lọ́wọ́ mi, ṣùgbọ́n mo fi í lélẹ̀, mo sì lágbára láti tún gbà á. Àṣẹ yìí ni mo ti gbà wá láti ọ̀dọ̀ Baba mi.”
No man taketh it from me, but I lay it down of myself. I have power to lay it down, and I have power to take it again. This commandment have I received of my Father.
[17] tree
Nítorí náà ìyapa tún láàrin àwọn Júù nítorí ọ̀rọ̀ wọ̀nyí.
s-17
JOHN_10.19
Nítorí náà ìyapa tún wà láàrin àwọn Júù nítorí ọ̀rọ̀ wọ̀nyí.
There was a division therefore again among the Jews for these sayings.
[18] tree
Ọ̀pọ̀ nínú wọn , Ó ẹ̀mí èṣù, orí rẹ̀ dàrú; èéṣe ẹ̀yin fi ń gbọ́rọ̀ rẹ̀?
s-18
JOHN_10.20
Ọ̀pọ̀ nínú wọn sì wí pé, “Ó ní ẹ̀mí èṣù, orí rẹ̀ sì dàrú; èéṣe tí ẹ̀yin fi ń gbọ́rọ̀ rẹ̀?”
And many of them said, He hath a devil, and is mad; why hear ye him?
[19] tree
Àwọn mìíràn , Ìwọ̀nyí kìí ṣe ọ̀rọ̀ ẹni ó ẹ̀mí èṣù. Ẹ̀mi èṣù la ojú àwọn afọ́jú ?
s-19
JOHN_10.21
Àwọn mìíràn wí pé, “Ìwọ̀nyí kìí ṣe ọ̀rọ̀ ẹni tí ó ní ẹ̀mí èṣù. Ẹ̀mi èṣù lè la ojú àwọn afọ́jú bí?”
Others said, These are not the words of him that hath a devil. Can a devil open the eyes of the blind?
[20] tree
Ó jẹ́ àjọ̀dún ìyàsímímọ́ Jérúsálẹ́mù, ìgbà òtútù ni.
s-20
JOHN_10.22
Ó sì jẹ́ àjọ̀dún ìyàsímímọ́ ní Jérúsálẹ́mù, ìgbà òtútù ni.
And it was at Jerusalem the feast of the dedication, and it was winter.
[21] tree
Jésù ń rìn tẹ́mpílì, ìloro Sólómónì,
s-21
JOHN_10.23
Jésù sì ń rìn ní tẹ́mpílì, ní ìloro Sólómónì,
And Jesus walked in the temple in Solomon's porch.
[22] tree
Nítorí náà àwọn Júù dúró i , wọ́n fún un , Ìwọ ó ti wa ṣe iyèméjì pẹ́ ? ìwọ ni Kírísítì náà, fún wa gbangba.
s-22
JOHN_10.24
Nítorí náà àwọn Júù wá dúró yí i ká, wọ́n sì wí fún un pé, “Ìwọ ó ti mú wa ṣe iyèméjì pẹ́ tó? Bí ìwọ bá ni Kírísítì náà, wí fún wa gbangba.”
Then came the Jews round about him, and said unto him, How long dost thou make us to doubt? If thou be the Christ, tell us plainly.
[23] tree
Jésù wọn lóhùn , Èmi ti fún yín, ẹ̀yin gbàgbọ́; iṣẹ́ èmi ń ṣe lórúkọ Baba mi, àwọn ni ó ń jẹ́rìí mi.
s-23
JOHN_10.25
Jésù dá wọn lóhùn pé, “Èmi ti wí fún yín, ẹ̀yin kò sì gbàgbọ́; iṣẹ́ tí èmi ń ṣe lórúkọ Baba mi, àwọn ni ó ń jẹ́rìí mi.
Jesus answered them, I told you, and ye believed not: the works that I do in my Father's name, they bear witness of me.
[24] tree
Ṣùgbọ́n ẹ̀yin gbàgbọ́, nítorí ẹ̀yin nínú àwọn àgùntàn mi, gẹ́gẹ́ mo fún yín.
s-24
JOHN_10.26
Ṣùgbọ́n ẹ̀yin kò gbàgbọ́, nítorí ẹ̀yin kò sí nínú àwọn àgùntàn mi, gẹ́gẹ́ bí mo tí wí fún yín.
But ye believe not, because ye are not of my sheep, as I said unto you.
[25] tree
Baba mi, ẹni ó fi wọ́n fún mi pọ̀ ju gbogbo wọn lọ; ẹni ó wọn gbà kúrò lọ́wọ́ Baba mi.
s-25
JOHN_10.29
Baba mi, ẹni tí ó fi wọ́n fún mi pọ̀ ju gbogbo wọn lọ; kò sì sí ẹni tí ó lè já wọn gbà kúrò lọ́wọ́ Baba mi.
My Father, which gave them me, is greater than all; and no man is able to pluck them out of my Father's hand.
[26] tree
Ọ̀kan ni èmi àti Baba mi.
s-26
JOHN_10.30
Ọ̀kan ni èmi àti Baba mi.”
I and my Father are one.
[27] tree
Àwọn Júù tún he òkúta, láti sọ ú.
s-27
JOHN_10.31
Àwọn Júù sì tún he òkúta, láti sọ lù ú.
Then the Jews took up stones again to stone him.
[28] tree
Jésù wọn lóhùn , Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ rere ni mo fi hàn yín láti ọ̀dọ̀ Baba mi ; nítorí èwo nínú iṣẹ́ wọ̀nyí ni ẹ̀yin ṣe sọ òkúta?
s-28
JOHN_10.32
Jésù dá wọn lóhùn pé, “Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ rere ni mo fi hàn yín láti ọ̀dọ̀ Baba mi wá; nítorí èwo nínú iṣẹ́ wọ̀nyí ni ẹ̀yin ṣe sọ mí ní òkúta?”
Jesus answered them, Many good works have I shewed you from my Father; for which of those works do ye stone me?
[29] tree
Àwọn Júù a lóhùn , Àwa sọ ọ́ lókúta nítorí iṣẹ́ rere, ṣùgbọ́n nítorí ọ̀rọ̀-ọ̀dì: àti nítorí ìwọ í ṣe ènìyàn ń fi ara rẹ pe Ọlọ́run.
s-29
JOHN_10.33
Àwọn Júù sì dá a lóhùn pé, “Àwa kò sọ ọ́ lókúta nítorí iṣẹ́ rere, ṣùgbọ́n nítorí ọ̀rọ̀-ọ̀dì: àti nítorí ìwọ tí í ṣe ènìyàn ń fi ara rẹ pe Ọlọ́run.”
The Jews answered him, saying, For a good work we stone thee not; but for blasphemy; and because that thou, being a man, makest thyself God.
[30] tree
Jésù wọn lóhùn , A ha ti kọ ọ́ nínú òfin yín , Mo ti , Ọlọ́run ni ẹ̀yin jẹ́?
s-30
JOHN_10.34
Jésù dá wọn lóhùn pé, “A kò ha ti kọ ọ́ nínú òfin yín pé, ‘Mo ti wí pé, Ọlọ́run ni ẹ̀yin jẹ́’?
Jesus answered them, Is it not written in your law, I said, Ye are gods?
[31] tree
èmi ṣe iṣẹ́ Baba mi, ṣe gbà gbọ́.
s-31
JOHN_10.37
Bí èmi kò bá ṣe iṣẹ́ Baba mi, ẹ má ṣe gbà mí gbọ́.
If I do not the works of my Father, believe me not.
[32] tree
Ṣùgbọ́n èmi ṣe wọ́n, ẹ̀yin tilẹ̀ gbà gbọ́, gbà iṣẹ́ náà gbọ́: ẹ̀yin baà mọ̀, ó yín , Baba nínú mi, èmi nínú rẹ̀.
s-32
JOHN_10.38
Ṣùgbọ́n bí èmi bá ṣe wọ́n, bí ẹ̀yin kò tilẹ̀ gbà mí gbọ́, ẹ gbà iṣẹ́ náà gbọ́: kí ẹ̀yin baà lè mọ̀, kí ó sì lè yé yín pé, Baba wà nínú mi, èmi sì wà nínú rẹ̀.”
But if I do, though ye believe not me, believe the works: that ye may know, and believe, that the Father is in me, and I in him.
[33] tree
Wọ́n tún ń ọ̀nà láti un: ó bọ́ lọ́wọ́ wọn.
s-33
JOHN_10.39
Wọ́n sì tún ń wá ọ̀nà láti mú un: ó sì bọ́ lọ́wọ́ wọn.
Therefore they sought again to take him: but he escaped out of their hand,
[34] tree
Àwọn ènìyàn púpọ̀ sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n , Jòhánù ṣe iṣẹ́ àmì kan: Ṣùgbọ́n òtítọ́ ni ohun gbogbo Jòhánù sọ nípa ti ọkùnrin yìí.
s-34
JOHN_10.41
Àwọn ènìyàn púpọ̀ sì wá sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n sì wí pé, “Jòhánù kò ṣe iṣẹ́ àmì kan: Ṣùgbọ́n òtítọ́ ni ohun gbogbo tí Jòhánù sọ nípa ti ọkùnrin yìí.”
And many resorted unto him, and said, John did no miracle: but all things that John spake of this man were true.
[35] tree
Àwọn ènìyàn púpọ̀ níbẹ̀ gbàágbọ́ .
s-35
JOHN_10.42
Àwọn ènìyàn púpọ̀ níbẹ̀ sì gbàágbọ́.
And many believed on him there.

Edit as listText viewDependency trees