yo-ytb-test-PS_133

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest

Javascript seems to be turned off, or there was a communication error. Turn on Javascript for more display options.

Kíyèsí, ó ti dára ó ti dùn fún àwọn ará láti máa jùmọ̀ gbé ìrẹ́pọ̀. Ó dàbí òróró ìkúnra iyebíye orí, ó ṣàn irungbọ̀n, àní irungbọ̀n Árónì: ó ṣàn etí aṣọ sórí Rẹ̀; irì Hémónì o ṣàn sórí òke Síónì: nítorí níbẹ̀ Olúwa gbé pàṣẹ ìbùkún, àni ìyè láéláé.

Download XMLDownload textSentence viewDependency trees