yo-ytb-test-MATT_5

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest

Javascript seems to be turned off, or there was a communication error. Turn on Javascript for more display options.

index sentence 1 - 6 > sentence 7 - 17

Nígbà ó ọ̀pọ̀ ènìyàn, ó gun orí òkè lọ ó jókòó. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ si tọ̀ ọ́ . Ó bẹ̀rẹ̀ kọ́ wọn : Alábùkún-fún ni àwọn òtòsì ẹ̀mí, nítorí tiwọn ni ìjọba ọ̀run. Alábùkún-fún ni àwọn ń ṣọ̀fọ̀, nítorí a ó wọ́n nínú. Alábùkún-fún ni àwọn ọlọ́kàn tútù, nítorí wọn yóò jogún ayé. Alábùkún fún ni àwọn ebi ń pa òùngbẹ ń gbẹ́ nítorí òdodo, nítorí wọn yóò .

Download XMLDownload textSentence viewDependency trees