yo-ytb-test-JOHN_10

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest

Javascript seems to be turned off, or there was a communication error. Turn on Javascript for more display options.

index sentence 1 - 6 > sentence 7 - 17

Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo fún yín, Ẹni gba ẹnu ọ̀nà wọ inú agbo àgùntàn, ṣùgbọ́n ó gba ibòmíràn gun òkè, Òun náà ni olè àti ọlọ́sà. Ṣùgbọ́n ẹni ó ti ẹnu-ọ̀nà wọlé, Òun ni olùṣọ́ àwọn àgùntàn. Òun ni osọ́nà yóò ṣí ìlẹ̀kùn fún; àwọn àgùntàn gbọ́ ohùn rẹ̀: ó pe àwọn àgùntàn tirẹ̀ lórúkọ , ó se amọ̀nà wọn jáde. Nígbà ó ti àwọn àgùntàn tirẹ̀ jáde, yóò ṣíwájú wọn, àwọn àgùntàn yóò máa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn: nítorí wọ́n mọ ohùn rẹ̀. Wọn jẹ́ tọ àlejò lẹ́yìn, ṣùgbọ́n wọn a kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀: nítorí wọn mọ ohùn àlejò. Òwe yìí ni Jésù pa fún wọn: ṣùgbọ́n òye ohun nǹkan wọ̀nyí jẹ́ ó ń sọ fún wọn wọn.

Download XMLDownload textSentence viewDependency trees