Dependency Tree

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest

Select a sentence

s-1 Kíyèsí, ó ti dára ó ti dùn fún àwọn ará láti máa jùmọ̀ gbé ìrẹ́pọ̀.
s-2 Ó dàbí òróró ìkúnra iyebíye orí, ó ṣàn irungbọ̀n, àní irungbọ̀n Árónì: ó ṣàn etí aṣọ sórí Rẹ̀;
s-3 irì Hémónì o ṣàn sórí òke Síónì: nítorí níbẹ̀ Olúwa gbé pàṣẹ ìbùkún, àni ìyè láéláé.

Text viewDownload CoNNL-U