Dependency Tree

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest

Select a sentence

s-1 Nígbà ó ọ̀pọ̀ ènìyàn, ó gun orí òkè lọ ó jókòó. Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ si tọ̀ ọ́ .
s-2 Ó bẹ̀rẹ̀ kọ́ wọn :
s-3 Alábùkún-fún ni àwọn òtòsì ẹ̀mí, nítorí tiwọn ni ìjọba ọ̀run.
s-4 Alábùkún-fún ni àwọn ń ṣọ̀fọ̀, nítorí a ó wọ́n nínú.
s-5 Alábùkún-fún ni àwọn ọlọ́kàn tútù, nítorí wọn yóò jogún ayé.
s-6 Alábùkún fún ni àwọn ebi ń pa òùngbẹ ń gbẹ́ nítorí òdodo, nítorí wọn yóò .
s-7 Alábùkún-fún ni àwọn aláàánú, nítorí wọn yóò àánú gbà.
s-8 Alábùkún-fún ni àwọn ọlọ́kàn mímọ́, nítorí wọn yóò Ọlọ́run.
s-9 Alábùkún-fún ni àwọn tonílàjà, nítorí ọmọ Ọlọ́run ni a ó máa wọ́n.
s-10 Alábùkún-fún ni àwọn ẹni a ṣe inúnibíni , nítorí wọ́n jẹ́ olódodo nítorí tiwọn ìjọba ọ̀run.
s-11 Alábùkún-fún ni ẹ̀yin nígbà àwọn ènìyàn fi àbùkù kàn yín wọn ṣe inúnibíni yín, ti wọn fi ètè èké sọ̀rọ̀ búburú gbogbo yín nítorí mi.
s-12 yọ̀, ẹ̀yin fún ayọ, nítorí ńlá ni èrè yín ọ̀run, nítorí bẹ́ẹ̀ ni wọ́n ṣe ṣe inúnibíni àwọn wòlíì ń bẹ ṣáájú yín.
s-13 Ẹ̀yin ni iyọ̀ ayé. Ṣùgbọ́n iyọ̀ di òbu ni a ó fi un dùn? tún wúlò fún ohunkóhun mọ́, ṣe a á , ó di ohun ènìyàn ń fi ẹsẹ̀ tẹ̀ mọ́lẹ̀ .
s-14 Ẹyin ni ìmọ́lẹ̀ ayé. Ìlú a tẹ̀dó sórí òkè fara sin.
s-15 Bẹ́ẹ̀ ni a í tan fìtílà tán, a gbé e abẹ́ òṣùnwọ̀n; ṣe orí ọ̀pá fìtílà, a tan ìmọ́lẹ̀ fún gbogbo ẹni ń bẹ nínú ilé.
s-16 Bákan náà, jẹ́ ìmọ́lẹ̀ yín ó mọ́lẹ níwájú ènìyàn, wọ́n máa iṣẹ́ rere yín, wọn máa yin baba yín ń bẹ ọ̀run lógo .
s-17 se , èmí láti pa òfin àwọn wòlíì run, èmi láti pa wọn rẹ́, ṣe láti wọn ṣẹ.
s-18 Lóòótọ́ ni mo fún un yín, títí ọ̀run òun ayé yóò fi kọjá, àmì kínkínní a fi gègé ṣe kan yóò parẹ́ kúrò nínú gbogbo òfin nínú ìwé ofin títí gbogbo rẹ̀ yóò fi ìmúṣẹ.
s-19 Ẹnikẹ́ni ti ó òfin ó tilẹ̀ kéré lọ, ó kọ́ ẹlòmíràn láti ṣe bẹ́ẹ̀, òun ni yóò kéré lọ ìjọba ọ̀run, ṣùgbọ́n ẹni ó ń sewọn , ó ń kọ́ wọn, ni yóò jẹ́ ẹni ńlá ìjọba ọ̀run.
s-20 Nítorì náà ni mọ ti fún yín àfi òdodo yín ju ti àwọn Farisí àti ti àwọn olùkọ́ òfin lọ, dájúdájú ẹ̀yin yóò le wọ ìjọba ọ̀run.
s-21 Ẹ̀yin ti gbọ́ a ti fún àwọn ará ìgbàanì , Ìwọ gbọdọ̀ pànìyàn , ẹnikẹni ó pànìyàn yóò nínú ewu ìdájọ́.
s-22 Ṣùgbọ́n èmi fún un yín , ẹnikẹ́ni ó bínú arákùnrin rẹ̀ yóò nínú ewu ìdájọ́. Ẹnikẹ́ni ti ó ba fun arakùnrin rẹ̀ , Ráákà yóò fara hàn níwájú Sahẹ́ńdìrì; ṣùgbọ́n ẹni ó Ìwọ wèrè! yóò nínú ewu iná ọ̀run àpáàdì.
s-23 Nítorí náà, nígbà ìwọ ń ẹ̀bùn rẹ ṣíwájú pẹpẹ, ìwọ rántí níbẹ̀ arákùnrin rẹ̀ ni ohùn kan nínú .
s-24 Fi ẹ̀bùn rẹ sílẹ̀ níwájú pẹpẹ. Ìwọ kọ́kọ́ lọ ṣe ìlàjà láàrin ìwọ àti arákùnrin rẹ̀ na. Lẹ́yìn náà, ó fi ẹ̀bùn rẹ sílẹ̀ .
s-25 ọ̀tá rẹ làjà kánkán, ẹni ó ń gbé lọ sílé ẹjọ́. Ṣe é nígbà ti ó ọ̀nà pẹ̀lú rẹ, bẹ́ẹ̀ kọ́ yóò ọ́ onídajọ lọ́wọ́ , onídájọ́ yóò àwọn ẹ̀sọ́ lọ́wọ́ , wọ́n a sọ ọ́ sínú túbú.
s-26 Lóòótọ ni mo fún , ìwọ yóò jáde kúrò níbẹ̀ títítí ìwọ yóò fi san ẹyọ owó kan ó .
s-27 Ẹ̀yin ti gbọ́ òfin ti , Ìwọ gbọdọ̀ ṣe panṣágà.
s-28 Ṣùgbọ́n mo fún yín , ẹnikẹ́ni ó wo obìrinrin kan ìwòkuwò, ti a ṣe panṣágà ọkàn rẹ̀.
s-29 ojú rẹ ọ̀tún dẹ́sẹ̀, yọ ọ́ jáde, ó sọ ọ́ . Ó sàn ẹ̀ya ara rẹ kan ṣègbé, ju a gbé gbogbo ara rẹ sínú iná ọ̀run àpáàdì.
s-30 ọwọ́ rẹ ọ̀tún dẹ́ṣẹ̀ e kúrò, ó sọ ọ́ . Ó sàn ẹ̀ya ara rẹ kan ṣègbé ju gbogbo ara rẹ lọ sínú iná ọ̀run àpáàdì.
s-31 A ti pẹ̀lú , Ẹnikẹ́ni ó kọ aya rẹ̀ sílẹ̀ gbọdọ̀ fún un ìwé-ẹ̀rí ìkọ̀sílẹ̀.
s-32 Ṣùgbọ́n mo fún yín , ẹnikẹ́ni ó kọ aya rẹ̀, àfi nítorí àgbèrè, un se àgbèrè, ẹnikẹ́ni ó fẹ́ obìnrin a kọ̀ sílẹ̀ ìyàwó ṣe àgbèrè.
s-33 Ẹ̀yin ti gbọ́ a ti fún àwọn ará ìgbàani ; Ìwọ gbọdọ̀ búrá èké ṣe ìwọ ó ìbúra rẹ̀ Olúwa ṣẹ.
s-34 Ṣùgbọ́n èmi fún yín, ṣe búra rárá,: ìbáà ṣe ìfi-ọ̀run-búra, nítorí ìtẹ́ Ọlọ́run ni.
s-35 Tàbí ìfi-ayé-búra, nítorí àpótí ìtìsẹ̀ Ọlọ́run ni; tàbí Jerúsálémù, nítorí olórí ìlú Ọba Ńlá ni.
s-36 ṣe fi orí rẹ búra, nítorí ìwọ sọ irun ẹyọ kan di funfun tàbí di dúdú.
s-37 jẹ́ bẹ́ẹ̀ ni yín jẹ́ bẹ́ẹ̀ ni àti bẹ́ẹ̀ kọ́ yín jẹ́ bẹ́ẹ̀ kọ́, ohunkóhun ó ba ju ìwọ̀nyí lọ, láti ọ̀dọ̀ ẹni ibi.
s-38 Ẹ̀yin gbọ́ òfin , Ojú fún ojú àti eyín fún eyín.
s-39 Ṣùgbọ́n èmi fún yín , ṣe tako ẹni ibi. ẹnì kan gbá lẹ́rẹ̀kẹ́ ọ̀tún, ẹ̀rẹ̀kẹ́ òsì olúwa rẹ̀ pẹ̀lú.
s-40 ẹnì kan fẹ́ gbé lọ sílé ẹjọ́, ó fẹ́ gba ẹ̀wù àwọ̀tẹ́lẹ̀, jọ̀wọ́ agbádá rẹ fún un pẹ̀lú.
s-41 ẹni kan fẹ́ fi agbára rìn ibùsọ̀ kan, a lọ ibùsọ̀ méjì.
s-42 Fi fún àwọn ó béèrè lọ́wọ́ rẹ, ṣe kọ̀ fún ẹni ó fẹ́ ya láti lọ́wọ́ rẹ.
s-43 Ẹ̀yin ti gbọ́ òfin ti , Fẹ́ràn aládúgbo rẹ, ìwọ kórírà ọ̀ta rẹ̀.
s-44 Ṣùgbọ́n èmi fún yín , fẹ́ràn àwọn ọ̀ta yín gbàdúrà fún àwọn ń ṣe inúnibíni yín,
s-45 ẹ̀yin jẹ́ ọmọ Baba yín bi ń bẹ ọ̀run. Ó oòrùn rẹ̀ ràn sára ènìyàn búburú àti ènìyàn rere, ó rọ̀jò fún àwọn olódodo àti fún àwọn aláìṣòdodo.
s-46 ẹ̀yin fẹ́ràn àwọn ó fẹ́ràn yín nìkan, èrè ni ẹ̀yin ? Àwọn agbowó-òde ha ń ṣe bẹ́ẹ̀ gẹ́gẹ́?
s-47 Àti ó jẹ́ kìkì àwọn arákùnrin yín nìkan ni ẹ̀yin ń , kín ni ẹ̀yin ń ṣe ju àwọn mìíràn? Àwọn abọ̀rìṣà ha ń ṣe bẹ́ẹ̀ ?
s-48 Nítorí náà, jẹ́ pípé, gẹ́gẹ́ Baba yín ń bẹ ọ̀run ṣe jẹ́ pípé.

Text viewDownload CoNNL-U