Dependency Tree

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest

Select a sentence

s-1 Wọn lọ si apákejì adágún ẹba ilẹ̀ àwọn ará Gádárà.
s-2 Jésù ti ń ti inú ọkọ̀ ojú omi jáde. Ọkùnrin kan ó ẹ̀mí àìmọ́ jáde ti ibojì pàdé rẹ̀.
s-3 Ọkùnrin yìí ń gbé nínú ìbojì, ẹni ó é mọ́, kódà ẹ̀wọ̀n le é.
s-4 Nítorí nígbà púpọ̀ ni wọn ti ń fi ṣẹ́kẹ́sẹkẹ̀ é lọ́wọ́ àti ẹṣẹ̀, ó ń a dànù kúrò ni ẹṣẹ rẹ. ẹnìkan ó agbára láti káwọ́ rẹ̀.
s-5 Tọ̀sán-tòru láàrin àwọn ibojì àti àwọn òkè ni ó máa ń kígbe rara ó ń fi òkúta ya ara rẹ̀.
s-6 Nígbà ó Jésù látòkèrè, ó sáré lọ láti pàdé rẹ̀. Ó wólẹ̀ níwájú rẹ̀.
s-7 Ó kígbe ohùn rara , ni ṣe tèmi tìrẹ, Jésù Ọmọ Ọlọ́run Ọ̀ga Ògo? Mo fi Ọlọ́run bẹ̀ ọ́ ṣe mi lóró .
s-8 Nítorí Ó fún un , Jáde kúrò lára ọkùnrin náà, ìwọ ẹ̀mí àìmọ́!
s-9 Jésù bi í léèrè , ni orúkọ rẹ? Ẹ̀mí àìmọ́ náà dáhùn , Líjíọ́nì, nítorí àwa pọ̀.
s-10 Nígbà náà ni ẹ̀mí àìmọ́ náà bẹ̀rẹ̀ í bẹ Jésù gidigidi, ó ṣe rán àwọn jáde kúrò agbègbè náà.
s-11 Agbo ẹlẹ́dẹ̀ ńlá kan ń jẹ lẹ́bàá òké.
s-12 Àwọn ẹ̀mí àìmọ́ náà bẹ Jésù , Rán wa lọ sínú àwọn ẹlẹ́dẹ̀ wọnni awa le è wọ inú wọn lọ.
s-13 Jésù fún wọn láàyè, àwọn ẹ̀mí àìmọ́ náà jáde kúrò lára ọkùnrin náà, wọ́n wọ inú àwọn ẹlẹ́dẹ̀ náà lọ. Agbo ẹlẹ́dẹ̀ náà ó ìwọ̀n ẹgbàá túká lọ́gán, wọ́n sáré lọ gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́ òkè rọ́ sínú òkun, wọ́n ṣègbé.
s-14 Àwọn olùtọ́jú ẹran wọ̀nyí lọ àwọn ìlú ńlá àti ìlú kéékèèkéé, wọ́n ń tan ìròyìn náà wọ́n ti ń sáré. Àwọn ènìyàn jáde láti fojú gán-án-ní ohun náà ó sẹlẹ̀.
s-15 Nígbà wọ́n péjọ sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n ọkùnrin náà, ẹni ó ẹ̀mí-èṣù, ó jokòó níbẹ̀, ó wọ aṣọ iye rẹ bọ̀ sípọ, ẹ̀rù wọ́n.
s-16 Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ṣojú wọn ń ròyìn rẹ̀ fún àwọn ènìyàn ohun ó sẹlẹ̀ ọkùnrin ẹlẹ́mí àìmọ́, wọn si sọ nípa agbo ẹlẹ́dẹ̀ náà pẹ̀lú.
s-17 Nígbà náà, àwọn èrò bẹ̀rẹ̀ bẹ Jésù ó fi agbégbé àwọn sílẹ̀.
s-18 Jésù ti ń wọ inú ọkọ̀ ojú-omi lọ, ọkùnrin náà ó ti ẹ̀mí àìmọ́ tẹ̀lẹ̀ bẹ̀ Ẹ́ òun a lọ.
s-19 Jésù gbà fún un, ṣùgbọ́n ó fún un , Lọ ilé ọ̀dọ̀ àwọn ẹbí rẹ, o sọ fún wọn Ọlọ́run ti ṣe ohun ńlá fún , àti ó ti ṣàánú fún .
s-20 Nítorí naà, ọkùnrin yìí padà lọ, ó bẹ̀rẹ̀ ròyìn Dekapolisi nípa ohun ńlá Jésù ṣe fún un. Ẹnu ya gbogbo ènìyàn.
s-21 Nígbà Jésù ti inú ọkọ̀ rékọjá apá kejì òkun, ọ̀pọ̀ ìjọ ènìyàn péjọ i etí òkun.
s-22 Ọ̀kan nínú àwọn olórí sínágọ́gù à ń ni Jáírù sọ́dọ̀ Jésù, nígbà ó i, ó wólẹ̀ níwájú rẹ̀.
s-23 Ó bẹ̀ ẹ́ gidigidi , Ọmọbìnrin mi lójú ikú, mo bẹ̀ ọ́, fi ọwọ́ rẹ e, ara rẹ̀ , ó .
s-24 Jésù ń a lọ. Ọ̀pọ̀ ìjọ ènìyàn ń tọ̀ Ọ́ lẹ́yìn.
s-25 Obìnrin kan láàrin ọ̀pọ̀ ènìyàn náà, ó ti ìsun ẹ̀jẹ̀ fún odidi ọdún méjìlá.
s-26 Ẹni ojú rẹ̀ ti ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpọ́njú lọ́dọ̀ ọ̀pọ̀ àwọn oníṣègùn, ó ti gbogbo ohun ó , síbẹ̀ kàkà ó san, ó ń burú i.
s-27 Nígbà ó gburo iṣẹ́ ìyanu Jésù ṣe, ìdí nìyìí ó fi sẹ́yìn rẹ̀, láàrin ọ̀pọ̀ ènìyàn, ó fọwọ́ kan aṣọ rẹ̀.
s-28 Nítorí ti ó ọkàn rẹ̀ , mo ṣá à fi ọwọ́ kan aṣọ rẹ̀, ara mi yóò .
s-29 Ìsun ẹ̀jẹ̀ rẹ gbẹ lẹṣẹkẹṣẹ, òun mọ̀ lára rẹ̀ , a òun láradá kúrò nínú àrùn náà.
s-30 Lọ́gán, Jésù mọ̀ nínú ara rẹ̀ agbára jáde lára òun. Ó yípadà láàrin ọ̀pọ̀ ènìyàn, ó béèrè, Ta ni ó fi ọwọ́ kan aṣọ mi?
s-31 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ fún un , Ìwọ ọ̀pọ̀ ènìyàn ó rọ̀gbà , ìwọ́ tún ń bèèrè ẹni ó fi ọwọ́ kàn ọ́?
s-32 Ṣíbẹ̀, Jésù bẹ̀rẹ̀ yíká láti ẹni náà, ó fi ọwọ́ kan òun.
s-33 Nígbà náà, obìnrin náà kún fún ìbẹ̀rù àti ìwárìrì nítorí ó ti mọ ohun ó ṣẹlẹ̀ lára òun. Ó kúnlẹ̀ níwájú rẹ̀, ó sọ ohun òun ti ṣe.
s-34 Jésù fún un , Ọmọbìnrin, ìgbàgbọ́ rẹ lára : a lọ àlàáfíà, ìwọ ti sàn nínú àrùn rẹ.
s-35 Jésù ti ń ba obìnrin náà sọ̀rọ̀, àwọn ìránṣẹ́ láti ilé Jáírù olorí sínágọ́gù , wọ́n fún un , ọmọbìnrin rẹ ti , àti wọn ṣe yọ Jésù lẹ́nu láti , nítorí ó ti pẹ́ .
s-36 Ṣùgbọ́n bi Jésù ti gbọ́ ọ̀rọ̀ náà, ó fún Jáírù , bẹ̀rù, à gbà gbọ́ nìkan.
s-37 Nígbà náà, Jésù ọ̀pọ̀ ènìyàn náà dúró. jẹ́ ẹnikẹ́ni tẹ̀lé òun lẹ́yìn lọ ilé Jáírù, ṣe Pétérù, Jákọ́bù àti Jòhánù.
s-38 Nígbà wọ́n ibẹ̀, Jésù i gbogbo nǹkan ti dàrú. Ilé kún fún àwọn ń sọkún, àti àwọn ń pohùnréré ẹkún.
s-39 Ó wọ inú ilé lọ, Ó àwọn ènìyàn sọ̀rọ̀, ó béèrè , Èéṣe ẹ̀yin fi ń sọkún ń pohunréré ẹkún? Ọmọbìnrin náà , ó sùn lásán ni.
s-40 Wọ́n fi í rẹ́rín. Ṣùgbọ́n ó sọ fún gbogbo wọn láti bọ́ síta , ó baba àti ìyá ọmọ náà, àti àwọn ọmọ ẹ̀yin rẹ̀ mẹ́ta. Ó wọ inú yàrá ọmọbìnrin náà gbé dùbúlẹ̀ .
s-41 Ó gba a ọwọ́ , ó , Tàlítà kúùmì ( ó túmọ̀ , ọmọdébìnrin, díde dúró).
s-42 Lẹ́sẹ̀kan-náà, ọmọbìnrin náà dìde. Ó ń rìn, ẹ̀rù ba wọn, ẹnú ya àwọn òbí rẹ̀ gidigidi.
s-43 Jésù kìlọ̀ fún wọn gidigidi wọn ṣe sọ ohun ó ti ṣẹlẹ̀. Ó fún wọn wọn fún ọmọbìnrin náà oúnjẹ.

Text viewDownload CoNNL-U