Dependency Tree

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest

Select a sentence

s-1 Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo fún yín, Ẹni gba ẹnu ọ̀nà wọ inú agbo àgùntàn, ṣùgbọ́n ó gba ibòmíràn gun òkè, Òun náà ni olè àti ọlọ́sà.
s-2 Ṣùgbọ́n ẹni ó ti ẹnu-ọ̀nà wọlé, Òun ni olùṣọ́ àwọn àgùntàn.
s-3 Òun ni osọ́nà yóò ṣí ìlẹ̀kùn fún; àwọn àgùntàn gbọ́ ohùn rẹ̀: ó pe àwọn àgùntàn tirẹ̀ lórúkọ , ó se amọ̀nà wọn jáde.
s-4 Nígbà ó ti àwọn àgùntàn tirẹ̀ jáde, yóò ṣíwájú wọn, àwọn àgùntàn yóò máa tọ̀ ọ́ lẹ́yìn: nítorí wọ́n mọ ohùn rẹ̀.
s-5 Wọn jẹ́ tọ àlejò lẹ́yìn, ṣùgbọ́n wọn a kúrò lọ́dọ̀ rẹ̀: nítorí wọn mọ ohùn àlejò.
s-6 Òwe yìí ni Jésù pa fún wọn: ṣùgbọ́n òye ohun nǹkan wọ̀nyí jẹ́ ó ń sọ fún wọn wọn.
s-7 Nítorí náà Jésù tún fún wọn , Lóòótọ́, lóòótọ́ ni mo fún yín, Èmi ni ìlẹ̀kùn àwọn àgùntàn.
s-8 Olè àti ọlọ́sà ni gbogbo àwọn ó ti ṣáájú mi: ṣùgbọ́n àwọn àgùntàn gbọ́ ti wọn.
s-9 Èmi ni ìlẹ̀kùn: ẹnìkan ọ̀dọ̀ mi wọlé, Òun ni a ó gbà , yóò wọlé, yóò jáde, yóò koríko.
s-10 Olè kìí ṣe láti jalè, láti pa, àti láti parun: èmi wọn ìyè, àní wọn i lọ́pọ̀lọpọ̀.
s-11 Èmi ni olùṣọ́ àgùntàn rere: olùṣọ́-àgùntàn rere fi ọkàn rẹ̀ lélẹ̀ nítorí àwọn àgùntàn.
s-12 Ṣùgbọ́n alágbàṣe, kìí ṣe olùṣọ́ àgùntàn, ẹni àwọn àgùntàn kìí ṣe tirẹ̀, ó ìkokò ń bọ̀, ó fi àgùntàn sílẹ̀, ó fọ́n wọn kiri.
s-13 Òun lọ nítorí ó jẹ́ alágbàṣe, náání àwọn àgùntàn.
s-14 Èmi àwọn àgùntàn mìíràn, kìí ṣe agbo yìí: àwọn ni èmi yóò pẹ̀lú, wọn ó gbọ́ ohùn mi; wọn ó jẹ́ agbo kan, olùsọ́-àgùntàn kan.
s-15 Nítorí náà ni Baba mi ṣe fẹ́ràn mi, nítorí mo fi ẹ̀mí mi lélẹ̀, èmi tún gbà á.
s-16 Ẹnìkan gbà á lọ́wọ́ mi, ṣùgbọ́n mo fi í lélẹ̀, mo lágbára láti tún gbà á. Àṣẹ yìí ni mo ti gbà láti ọ̀dọ̀ Baba mi.
s-17 Nítorí náà ìyapa tún láàrin àwọn Júù nítorí ọ̀rọ̀ wọ̀nyí.
s-18 Ọ̀pọ̀ nínú wọn , Ó ẹ̀mí èṣù, orí rẹ̀ dàrú; èéṣe ẹ̀yin fi ń gbọ́rọ̀ rẹ̀?
s-19 Àwọn mìíràn , Ìwọ̀nyí kìí ṣe ọ̀rọ̀ ẹni ó ẹ̀mí èṣù. Ẹ̀mi èṣù la ojú àwọn afọ́jú ?
s-20 Ó jẹ́ àjọ̀dún ìyàsímímọ́ Jérúsálẹ́mù, ìgbà òtútù ni.
s-21 Jésù ń rìn tẹ́mpílì, ìloro Sólómónì,
s-22 Nítorí náà àwọn Júù dúró i , wọ́n fún un , Ìwọ ó ti wa ṣe iyèméjì pẹ́ ? ìwọ ni Kírísítì náà, fún wa gbangba.
s-23 Jésù wọn lóhùn , Èmi ti fún yín, ẹ̀yin gbàgbọ́; iṣẹ́ èmi ń ṣe lórúkọ Baba mi, àwọn ni ó ń jẹ́rìí mi.
s-24 Ṣùgbọ́n ẹ̀yin gbàgbọ́, nítorí ẹ̀yin nínú àwọn àgùntàn mi, gẹ́gẹ́ mo fún yín.
s-25 Baba mi, ẹni ó fi wọ́n fún mi pọ̀ ju gbogbo wọn lọ; ẹni ó wọn gbà kúrò lọ́wọ́ Baba mi.
s-26 Ọ̀kan ni èmi àti Baba mi.
s-27 Àwọn Júù tún he òkúta, láti sọ ú.
s-28 Jésù wọn lóhùn , Ọ̀pọ̀lọpọ̀ iṣẹ́ rere ni mo fi hàn yín láti ọ̀dọ̀ Baba mi ; nítorí èwo nínú iṣẹ́ wọ̀nyí ni ẹ̀yin ṣe sọ òkúta?
s-29 Àwọn Júù a lóhùn , Àwa sọ ọ́ lókúta nítorí iṣẹ́ rere, ṣùgbọ́n nítorí ọ̀rọ̀-ọ̀dì: àti nítorí ìwọ í ṣe ènìyàn ń fi ara rẹ pe Ọlọ́run.
s-30 Jésù wọn lóhùn , A ha ti kọ ọ́ nínú òfin yín , Mo ti , Ọlọ́run ni ẹ̀yin jẹ́?
s-31 èmi ṣe iṣẹ́ Baba mi, ṣe gbà gbọ́.
s-32 Ṣùgbọ́n èmi ṣe wọ́n, ẹ̀yin tilẹ̀ gbà gbọ́, gbà iṣẹ́ náà gbọ́: ẹ̀yin baà mọ̀, ó yín , Baba nínú mi, èmi nínú rẹ̀.
s-33 Wọ́n tún ń ọ̀nà láti un: ó bọ́ lọ́wọ́ wọn.
s-34 Àwọn ènìyàn púpọ̀ sọ́dọ̀ rẹ̀, wọ́n , Jòhánù ṣe iṣẹ́ àmì kan: Ṣùgbọ́n òtítọ́ ni ohun gbogbo Jòhánù sọ nípa ti ọkùnrin yìí.
s-35 Àwọn ènìyàn púpọ̀ níbẹ̀ gbàágbọ́ .

Text viewDownload CoNNL-U