Sentence view

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest


[1] tree
Kíyèsí, ó ti dára ó ti dùn fún àwọn ará láti máa jùmọ̀ gbé ìrẹ́pọ̀.
s-1
PS_133.1
Kíyèsí, ó ti dára ó sì ti dùn tó fún àwọn ará láti máa jùmọ̀ gbé ní ìrẹ́pọ̀.
Behold, how good and how pleasant it is for brethren to dwell together in unity!
[2] tree
Ó dàbí òróró ìkúnra iyebíye orí, ó ṣàn irungbọ̀n, àní irungbọ̀n Árónì: ó ṣàn etí aṣọ sórí Rẹ̀;
s-2
PS_133.2
Ó dàbí òróró ìkúnra iyebíye ní orí, tí ó ṣàn dé irungbọ̀n, àní irungbọ̀n Árónì: tí ó sì ṣàn sí etí aṣọ sórí Rẹ̀;
It is like the precious ointment upon the head, that ran down upon the beard, even Aaron's beard: that went down to the skirts of his garments;
[3] tree
irì Hémónì o ṣàn sórí òke Síónì: nítorí níbẹ̀ Olúwa gbé pàṣẹ ìbùkún, àni ìyè láéláé.
s-3
PS_133.3
Bí irì Hémónì tí o ṣàn sórí òke Síónì: nítorí níbẹ̀ ní Olúwa gbé pàṣẹ ìbùkún, àni ìyè láéláé.
As the dew of Hermon, and as the dew that descended upon the mountains of Zion: for there the LORD commanded the blessing, even life for evermore.

Edit as listText viewDependency trees