Sentence view
Universal Dependencies - Yoruba - YTB
Language | Yoruba |
---|
Project | YTB |
---|
Corpus Part | test |
---|
Olúwa àyà mí kò gbéga bẹ́ẹ̀ ní ojú mi kò gbé sókè: bẹ́ẹ̀ ni èmi kò fi ọwọ́ mi lé ọ̀ràn ńlá, tàbí lé ohun tí ó ga jù mí lọ
s-1
PS_131.1
Olúwa àyà mí kò gbéga bẹ́ẹ̀ ní ojú mi kò gbé sókè: bẹ́ẹ̀ ni èmi kò fi ọwọ́ mi lé ọ̀ràn ńlá, tàbí lé ohun tí ó ga jù mí lọ
LORD, my heart is not haughty, nor mine eyes lofty: neither do I exercise myself in great matters, or in things too high for me.
Nítòótọ́ èmi mú ọkàn mi sinmi, mo sì mú-un dákẹ́jẹ́ẹ́, bí ọmọ tí a fi ọwọ ìyá Rẹ̀ gbà ní ẹnu ọmú: ọkàn mí rí gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí a já ní ẹnu ọmú.
s-2
PS_131.2
Nítòótọ́ èmi mú ọkàn mi sinmi, mo sì mú-un dákẹ́jẹ́ẹ́, bí ọmọ tí a fi ọwọ ìyá Rẹ̀ gbà ní ẹnu ọmú: ọkàn mí rí gẹ́gẹ́ bí ọmọ tí a já ní ẹnu ọmú.
Surely I have behaved and quieted myself, as a child that is weaned of his mother: my soul is even as a weaned child.
Ísírẹ́lì, ìwọ ní ìrètí ní ti Olúwa láti ìsinsinyí lọ àti láéláé.
s-3
PS_131.3
Ísírẹ́lì, ìwọ ní ìrètí ní ti Olúwa láti ìsinsinyí lọ àti láéláé.
Let Israel hope in the LORD from henceforth and for ever.
Edit as list • Text view • Dependency trees