# newdoc id = yo-ytb-test-JOHN_11 # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-1 # text = Ara ọkùnrin kan sì ṣe aláìdá, Lásárù, ará Bẹ́tẹ́nì, tí í ṣe ìlú Màríà àti Mátà arábìnrin rẹ̀. 1 Ara ara PRON _ PronType=Emp 2 nmod _ _ 2 ọkùnrin ọkùnrin NOUN _ _ 5 nsubj _ _ 3 kan kan NUM _ NumType=Card 2 nummod _ _ 4 sì sì CCONJ _ _ 5 cc _ _ 5 ṣe ṣe VERB _ _ 0 root _ _ 6 aláìdá aláìdá NOUN _ _ 5 xcomp _ _ 7 , , PUNCT _ _ 8 punct _ _ 8 Lásárù Lásárù PROPN _ _ 2 appos _ _ 9 , , PUNCT _ _ 10 punct _ _ 10 ará ará NOUN _ _ 8 nmod _ _ 11 Bẹ́tẹ́nì Bẹ́tẹ́nì PROPN _ _ 10 nmod _ _ 12 , , PUNCT _ _ 15 punct _ _ 13 tí tí PRON _ PronType=Rel 15 nsubj _ _ 14 í í PART _ _ 15 expl _ _ 15 ṣe ṣe VERB _ _ 11 acl _ _ 16 ìlú ìlú NOUN _ _ 15 obj _ _ 17 Màríà Màríà PROPN _ _ 16 nmod _ _ 18 àti àti CCONJ _ _ 19 cc _ _ 19 Mátà Mátà PROPN _ _ 17 conj _ _ 20 arábìnrin arábìnrin NOUN _ _ 19 appos _ _ 21 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 20 nmod _ _ 22 . . PUNCT _ _ 5 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-2 # text = (Màríà náà ni ẹni tí ó fi òróró ìkunra kun Olúwa, tí ó sì fi irun orí rẹ̀ nù ún, arákùnrin rẹ̀ ni Lásárù í ṣe, ara ẹni tí kò dá.) 1 ( ( PUNCT _ _ 2 punct _ _ 2 Màríà Màríà PROPN _ _ 0 root _ _ 3 náà náà DET _ _ 2 det _ _ 4 ni ni PART _ _ 2 case _ _ 5 ẹni ẹni PRON _ PronType=Ind 2 appos _ _ 6 tí tí PRON _ PronType=Rel 5 fixed _ _ 7 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 8 expl _ _ 8 fi fi VERB _ _ 5 acl _ _ 9 òróró òróró NOUN _ _ 8 obj _ _ 10 ìkunra ìkunra NOUN _ _ 9 nmod _ _ 11 kun kun VERB _ _ 8 compound:svc _ _ 12 Olúwa Olúwa PROPN _ _ 11 obj _ _ 13 , , PUNCT _ _ 17 punct _ _ 14 tí tí PRON _ PronType=Rel 17 nsubj _ _ 15 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 17 expl _ _ 16 sì sì CCONJ _ _ 17 cc _ _ 17 fi fi VERB _ _ 8 conj _ _ 18 irun irun NOUN _ _ 17 obj _ _ 19 orí orí NOUN _ _ 18 nmod _ _ 20 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 19 nmod _ _ 21 nù nù VERB _ _ 17 compound:svc _ _ 22 ún ún PRON _ _ 21 obj _ _ 23 , , PUNCT _ _ 24 punct _ _ 24 arákùnrin arákùnrin NOUN _ _ 29 nsubj _ _ 25 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 24 nmod _ _ 26 ni ni PART _ _ 24 case _ _ 27 Lásárù Lásárù PROPN _ _ 24 flat _ _ 28 í í PRON _ _ 29 expl _ _ 29 ṣe ṣe VERB _ _ 17 xcomp _ _ 30 , , PUNCT _ _ 31 punct _ _ 31 ara ara PRON _ PronType=Emp 27 appos _ _ 32 ẹni ẹni PRON _ PronType=Ind 31 nmod _ _ 33 tí tí PRON _ PronType=Rel 32 fixed _ _ 34 kò kò PART _ _ 35 advmod _ _ 35 dá dá ADJ _ _ 32 acl _ _ 36 . . PUNCT _ _ 2 punct _ _ 37 ) ) PUNCT _ _ 2 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-3 # text = Nítorí náà, àwọn arákùnrin rẹ̀ ránsẹ́ sí i, wí pé, “Olúwa, wò ó, ara ẹni tí ìwọ fẹ́ràn kò dá.” 1 Nítorí Nítorí SCONJ _ _ 7 mark _ _ 2 náà náà PRON _ _ 1 fixed _ _ 3 , , PUNCT _ _ 7 punct _ _ 4 àwọn àwọn DET _ Number=Plur|PronType=Dem 5 det _ _ 5 arákùnrin arákùnrin NOUN _ _ 7 nsubj _ _ 6 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 5 nmod _ _ 7 ránsẹ́ ránsẹ́ NOUN _ _ 0 root _ _ 8 sí sí ADP _ _ 9 case _ _ 9 i i PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 7 obl _ _ 10 , , PUNCT _ _ 11 punct _ _ 11 wí wí VERB _ _ 7 conj _ _ 12 pé pé SCONJ _ _ 11 compound _ _ 13 , , PUNCT _ _ 17 punct _ _ 14 “ “ PUNCT _ _ 17 punct _ _ 15 Olúwa Olúwa PROPN _ _ 17 vocative _ _ 16 , , PUNCT _ _ 15 punct _ _ 17 wò wò VERB _ _ 11 ccomp _ _ 18 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 17 obj _ _ 19 , , PUNCT _ _ 26 punct _ _ 20 ara ara PRON _ PronType=Emp 26 nsubj _ _ 21 ẹni ẹni PRON _ PronType=Ind 20 nmod _ _ 22 tí tí PRON _ PronType=Rel 21 fixed _ _ 23 ìwọ ìwọ PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 24 nsubj _ _ 24 fẹ́ràn fẹ́ràn VERB _ _ 21 acl _ _ 25 kò kò PART _ _ 26 advmod _ _ 26 dá dá ADJ _ _ 17 conj _ _ 27 . . PUNCT _ _ 7 punct _ _ 28 ” ” PUNCT _ _ 7 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-4 # text = Nígbà tí Jésù sì gbọ́, ó wí pé, “Àìsàn yìí kìí ṣe sí ikú, ṣùgbọ́n fún Ògo Ọlọ́run, kí a lè yin Ọmọ Ọlọ́run lógo nípasẹ̀ rẹ̀.” 1 Nígbà nígbà ADV _ _ 5 advmod _ _ 2 tí tí PRON _ PronType=Rel 1 fixed _ _ 3 Jésù Jésù PROPN _ _ 5 nsubj _ _ 4 sì sì CCONJ _ _ 5 cc _ _ 5 gbọ́ gbọ́ VERB _ _ 8 advcl _ _ 6 , , PUNCT _ _ 5 punct _ _ 7 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 8 nsubj _ _ 8 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 9 pé pé SCONJ _ _ 8 compound _ _ 10 , , PUNCT _ _ 15 punct _ _ 11 “ “ PUNCT _ _ 15 punct _ _ 12 Àìsàn Àìsàn NOUN _ _ 15 nsubj _ _ 13 yìí yìí DET _ _ 12 det _ _ 14 kìí kìí PART _ _ 15 mark _ _ 15 ṣe ṣe VERB _ _ 8 ccomp _ _ 16 sí ti ADP _ Typo=Yes 17 case _ _ 17 ikú ikú NOUN _ _ 15 xcomp _ _ 18 , , PUNCT _ _ 21 punct _ _ 19 ṣùgbọ́n ṣùgbọ́n CCONJ _ _ 21 cc _ _ 20 fún fún ADP _ _ 21 case _ _ 21 Ògo Ògo NOUN _ _ 17 conj _ _ 22 Ọlọ́run Ọlọ́run NOUN _ _ 21 nmod _ _ 23 , , PUNCT _ _ 27 punct _ _ 24 kí kí SCONJ _ _ 27 mark _ _ 25 a a PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=1|PronType=Prs 27 nsubj _ _ 26 lè lè AUX _ _ 27 aux _ _ 27 yin yin VERB _ _ 15 advcl _ _ 28 Ọmọ Ọmọ NOUN _ _ 27 obj _ _ 29 Ọlọ́run Ọlọ́run NOUN _ _ 28 nmod _ _ 30 lógo lógo VERB _ _ 27 compound:svc _ _ 31 nípasẹ̀ nípasẹ̀ ADP _ _ 32 case _ _ 32 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 27 obl _ _ 33 . . PUNCT _ _ 15 punct _ _ 34 ” ” PUNCT _ _ 15 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-5 # text = Ṣùgbọ́n bí ẹnìkan bá rìn ní òru, yóò kọsẹ̀, nítorí tí kò sí ìmọ́lẹ̀ nínú rẹ̀.” 1 Ṣùgbọ́n Ṣùgbọ́n CCONJ _ _ 10 cc _ _ 2 bí bí SCONJ _ _ 5 mark _ _ 3 ẹnìkan ẹnìkan NOUN _ _ 5 nsubj _ _ 4 bá bá SCONJ _ _ 5 mark _ _ 5 rìn rìn VERB _ _ 10 advcl _ _ 6 ní ní ADP _ _ 7 case _ _ 7 òru òru NOUN _ _ 5 obl _ _ 8 , , PUNCT _ _ 5 punct _ _ 9 yóò yóò AUX _ _ 10 aux _ _ 10 kọsẹ̀ kọsẹ̀ VERB _ _ 0 root _ _ 11 , , PUNCT _ _ 15 punct _ _ 12 nítorí nítorí SCONJ _ _ 15 mark _ _ 13 tí tí PRON _ PronType=Rel 12 fixed _ _ 14 kò kò PART _ _ 15 advmod _ _ 15 sí sí VERB _ _ 10 advcl _ _ 16 ìmọ́lẹ̀ ìmọ́lẹ̀ NOUN _ _ 15 obj _ _ 17 nínú nínú ADP _ _ 18 case _ _ 18 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 15 obl _ _ 19 . . PUNCT _ _ 10 punct _ _ 20 ” ” PUNCT _ _ 10 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-6 # text = Nǹkan wọ̀nyí ni ó sọ: lẹ́yìn èyí nì ó sì wí fún wọn pé, “Lásárù ọ̀rẹ́ wa sùn; ṣùgbọ́n èmi ń lọ kí èmi kí ó lè jí i dìde nínú orun rẹ̀.” 1 Nǹkan Nǹkan NOUN _ _ 5 obj _ _ 2 wọ̀nyí wọ̀nyí DET _ _ 1 det _ _ 3 ni ni PART _ _ 1 case _ _ 4 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 5 nsubj _ _ 5 sọ sọ VERB _ _ 0 root _ _ 6 : : PUNCT _ _ 12 punct _ _ 7 lẹ́yìn lẹ́yìn ADP _ _ 8 case _ _ 8 èyí èyí PRON _ PronType=Dem 12 obl _ _ 9 nì ni PART _ _ 8 case _ _ 10 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 12 nsubj _ _ 11 sì sì CCONJ _ _ 12 cc _ _ 12 wí wí VERB _ _ 5 parataxis _ _ 13 fún fún ADP _ _ 14 case _ _ 14 wọn wọn PRON _ Case=Acc|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 12 obl _ _ 15 pé pé SCONJ _ _ 21 mark _ _ 16 , , PUNCT _ _ 21 punct _ _ 17 “ “ PUNCT _ _ 21 punct _ _ 18 Lásárù Lásárù PROPN _ _ 21 nsubj _ _ 19 ọ̀rẹ́ ọ̀rẹ́ NOUN _ _ 18 appos _ _ 20 wa wa PRON _ Case=Acc|Number=Plur|Person=1|PronType=Prs 19 nmod _ _ 21 sùn sùn VERB _ _ 12 ccomp _ _ 22 ; ; PUNCT _ _ 26 punct _ _ 23 ṣùgbọ́n ṣùgbọ́n CCONJ _ _ 26 cc _ _ 24 èmi èmi PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 26 nsubj _ _ 25 ń ń AUX _ _ 26 aux _ _ 26 lọ lọ VERB _ _ 21 conj _ _ 27 kí kí SCONJ _ _ 32 mark _ _ 28 èmi èmi PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 32 nsubj _ _ 29 kí kí SCONJ _ _ 32 mark _ _ 30 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 32 expl _ _ 31 lè lè AUX _ _ 32 aux _ _ 32 jí jí VERB _ _ 26 xcomp _ _ 33 i i PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 32 obj _ _ 34 dìde dìde VERB _ _ 32 compound:svc _ _ 35 nínú nínú ADP _ _ 36 case _ _ 36 orun orun NOUN _ _ 32 obl _ _ 37 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 36 nmod _ _ 38 . . PUNCT _ _ 21 punct _ _ 39 ” ” PUNCT _ _ 21 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-7 # text = Nítorí náà àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ wí fún un pé, “Olúwa, bí ó bá se pé ó sùn, yóò sàn.” 1 Nítorí Nítorí SCONJ _ _ 8 mark _ _ 2 náà náà PRON _ _ 1 fixed _ _ 3 àwọn àwọn DET _ Number=Plur|PronType=Dem 4 det _ _ 4 ọmọ ọmọ NOUN _ _ 8 nsubj _ _ 5 - - PUNCT _ _ 6 punct _ _ 6 ẹ̀yìn ẹ̀yìn NOUN _ _ 4 compound _ _ 7 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 4 nmod _ _ 8 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 9 fún fún ADP _ _ 10 case _ _ 10 un un PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 8 obl _ _ 11 pé pé SCONJ _ _ 25 mark _ _ 12 , , PUNCT _ _ 25 punct _ _ 13 “ “ PUNCT _ _ 25 punct _ _ 14 Olúwa Olúwa PROPN _ _ 25 vocative _ _ 15 , , PUNCT _ _ 14 punct _ _ 16 bí bí SCONJ _ _ 19 mark _ _ 17 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 19 nsubj _ _ 18 bá bá SCONJ _ _ 19 mark _ _ 19 se ṣe VERB _ _ 25 advcl _ _ 20 pé pé SCONJ _ _ 22 mark _ _ 21 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 22 expl _ _ 22 sùn sùn VERB _ _ 19 ccomp _ _ 23 , , PUNCT _ _ 19 punct _ _ 24 yóò yóò AUX _ _ 25 aux _ _ 25 sàn sàn ADJ _ _ 8 ccomp _ _ 26 . . PUNCT _ _ 25 punct _ _ 27 ” ” PUNCT _ _ 25 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-8 # text = Ṣùgbọ́n Jésù ń sọ ti ikú rẹ̀: ṣùgbọ́n wọ́n rò pé, ó ń sọ ti orun sísùn. 1 Ṣùgbọ́n Ṣùgbọ́n CCONJ _ _ 4 cc _ _ 2 Jésù Jésù PROPN _ _ 4 nsubj _ _ 3 ń ń AUX _ _ 4 aux _ _ 4 sọ sọ VERB _ _ 0 root _ _ 5 ti ti ADP _ _ 6 case _ _ 6 ikú ikú NOUN _ _ 4 obl _ _ 7 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 6 nmod _ _ 8 : : PUNCT _ _ 11 punct _ _ 9 ṣùgbọ́n ṣùgbọ́n CCONJ _ _ 11 cc _ _ 10 wọ́n wọ́n PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 11 nsubj _ _ 11 rò rò VERB _ _ 4 conj _ _ 12 pé pé SCONJ _ _ 16 mark _ _ 13 , , PUNCT _ _ 16 punct _ _ 14 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 16 nsubj _ _ 15 ń ń AUX _ _ 16 aux _ _ 16 sọ sọ VERB _ _ 11 ccomp _ _ 17 ti ti ADP _ _ 18 case _ _ 18 orun orun NOUN _ _ 16 obl _ _ 19 sísùn sísùn NOUN _ _ 18 nmod _ _ 20 . . PUNCT _ _ 4 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-9 # text = Nígbà náà ni Jésù wí fún wọn gbangba pé, Lásárù kú, 1 Nígbà Nígbà ADV _ _ 5 advmod _ _ 2 náà náà ADV _ _ 1 fixed _ _ 3 ni ni PART _ _ 4 case _ _ 4 Jésù Jésù PROPN _ _ 5 nsubj _ _ 5 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 6 fún fún ADP _ _ 7 case _ _ 7 wọn wọn PRON _ Case=Acc|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 5 obl _ _ 8 gbangba gbangba ADV _ _ 5 advmod _ _ 9 pé pé SCONJ _ _ 12 mark _ _ 10 , , PUNCT _ _ 12 punct _ _ 11 Lásárù Lásárù PROPN _ _ 12 nsubj _ _ 12 kú kú VERB _ _ 5 ccomp _ _ 13 , , PUNCT _ _ 5 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-10 # text = Èmi sì yọ̀ nítorí yín, tí èmi kò sí níbẹ̀, Kí ẹ le gbàgbọ́; ṣùgbọ́n ẹ jẹ́ kí a lọ sọ́dọ̀ rẹ̀. 1 Èmi Èmi PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 3 nsubj _ _ 2 sì sì CCONJ _ _ 3 cc _ _ 3 yọ̀ yọ̀ VERB _ _ 0 root _ _ 4 nítorí nítorí SCONJ _ _ 5 case _ _ 5 yín yín PRON _ Case=Gen|Number=Plur|Person=2|PronType=Prs 3 obl _ _ 6 , , PUNCT _ _ 10 punct _ _ 7 tí tí PRON _ PronType=Rel 10 obl _ _ 8 èmi èmi PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 10 nsubj _ _ 9 kò kò PART _ _ 10 advmod _ _ 10 sí sí VERB _ _ 3 advcl _ _ 11 níbẹ̀ níbẹ̀ ADV _ _ 10 advmod _ _ 12 , , PUNCT _ _ 16 punct _ _ 13 Kí Kí SCONJ _ _ 16 mark _ _ 14 ẹ ẹ PRON _ Case=Acc|Number=Plur|Person=2|PronType=Prs 16 nsubj _ _ 15 le lè AUX _ _ 16 aux _ _ 16 gbàgbọ́ gbàgbọ́ VERB _ _ 3 advcl _ _ 17 ; ; PUNCT _ _ 23 punct _ _ 18 ṣùgbọ́n ṣùgbọ́n CCONJ _ _ 23 cc _ _ 19 ẹ ẹ PRON _ Case=Acc|Number=Plur|Person=2|PronType=Prs 23 discourse _ _ 20 jẹ́ jẹ́ VERB _ _ 23 ccomp _ _ 21 kí kí AUX _ _ 20 aux _ _ 22 a a PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=1|PronType=Prs 23 nsubj _ _ 23 lọ lọ VERB _ _ 3 parataxis _ _ 24 sọ́dọ̀ sọ́dọ̀ ADP _ _ 25 case _ _ 25 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 23 obl _ _ 26 . . PUNCT _ _ 3 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-11 # text = “Nítorí náà Tómásì, ẹni tí à ń pè ní Dídímù, wí fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn ẹgbẹ́ rẹ̀ pé, Ẹ jẹ́ kí àwa náà lọ, kí a lè bá a kú pẹ̀lú.” 1 “ “ PUNCT _ _ 14 punct _ _ 2 Nítorí nítorí SCONJ _ _ 14 mark _ _ 3 náà náà PRON _ _ 2 fixed _ _ 4 Tómásì tómásì PROPN _ _ 14 nsubj _ _ 5 , , PUNCT _ _ 6 punct _ _ 6 ẹni ẹni PRON _ PronType=Ind 4 appos _ _ 7 tí tí PRON _ PronType=Rel 6 fixed _ _ 8 à à PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=1|PronType=Prs 10 nsubj _ _ 9 ń ń AUX _ _ 10 aux _ _ 10 pè pè VERB _ _ 6 acl _ _ 11 ní ní AUX _ _ 12 cop _ _ 12 Dídímù dídímù PROPN _ _ 10 xcomp _ _ 13 , , PUNCT _ _ 6 punct _ _ 14 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 15 fún fún ADP _ _ 17 case _ _ 16 àwọn àwọn DET _ Number=Plur|PronType=Dem 17 det _ _ 17 ọmọ ọmọ NOUN _ _ 14 obl _ _ 18 - - PUNCT _ _ 19 punct _ _ 19 ẹ̀yìn ẹ̀yìn NOUN _ _ 17 compound _ _ 20 ẹgbẹ́ ẹgbẹ́ NOUN _ _ 17 nmod _ _ 21 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 20 nmod _ _ 22 pé pé SCONJ _ _ 29 mark _ _ 23 , , PUNCT _ _ 29 punct _ _ 24 Ẹ ẹ PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=2|PronType=Prs 29 discourse _ _ 25 jẹ́ jẹ́ VERB _ _ 29 ccomp _ _ 26 kí kí AUX _ _ 25 aux _ _ 27 àwa àwa PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=1|PronType=Prs 29 nsubj _ _ 28 náà náà ADV _ _ 29 advmod _ _ 29 lọ lọ VERB _ _ 14 ccomp _ _ 30 , , PUNCT _ _ 36 punct _ _ 31 kí kí SCONJ _ _ 36 mark _ _ 32 a a PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=1|PronType=Prs 36 nsubj _ _ 33 lè lè AUX _ _ 36 aux _ _ 34 bá bá ADP _ _ 36 case _ _ 35 a a PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 36 expl _ _ 36 kú kú VERB _ _ 29 advcl _ _ 37 pẹ̀lú pẹ̀lú ADV _ _ 36 advmod _ _ 38 . . PUNCT _ _ 14 punct _ _ 39 ” ” PUNCT _ _ 14 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-12 # text = Nítorí náà nígbà tí Jésù dé, ó rí i pé a ti tẹ́ ẹ sínú ibojì ní ijọ́ mẹ́rin ná, 1 Nítorí nítorí SCONJ _ _ 6 mark _ _ 2 náà náà PRON _ _ 1 fixed _ _ 3 nígbà nígbà ADV _ _ 6 advmod _ _ 4 tí tí PRON _ PronType=Rel 3 fixed _ _ 5 Jésù jésù PROPN _ _ 6 nsubj _ _ 6 dé dé VERB _ _ 9 advcl _ _ 7 , , PUNCT _ _ 6 punct _ _ 8 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 9 nsubj _ _ 9 rí rí VERB _ _ 0 root _ _ 10 i i PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 9 obj _ _ 11 pé pé SCONJ _ _ 14 mark _ _ 12 a a PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=1|PronType=Prs 14 nsubj _ _ 13 ti ti AUX _ _ 14 aux _ _ 14 tẹ́ tẹ́ VERB _ _ 10 acl _ _ 15 ẹ ẹ PRON _ Case=Acc|Number=Plur|Person=2|PronType=Prs 14 obj _ _ 16 sínú sínú ADP _ _ 17 case _ _ 17 ibojì ibojì NOUN _ _ 14 obl _ _ 18 ní ní ADP _ _ 19 case _ _ 19 ijọ́ ijọ́ NOUN _ _ 14 obl _ _ 20 mẹ́rin mẹ́rin NUM _ NumType=Card 19 nummod _ _ 21 ná ná ADV _ _ 14 advmod _ _ 22 , , PUNCT _ _ 9 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-13 # text = Ǹjẹ́ Bétanì súnmọ́ Jérúsálẹ́mù tó ibùsọ Mẹ́ẹ̀dógún: 1 Ǹjẹ́ Ǹjẹ́ PART _ _ 3 mark _ _ 2 Bétanì bẹ́tẹ́nì PROPN _ Typo=Yes 3 nsubj _ _ 3 súnmọ́ súnmọ́ ADV _ _ 0 root _ _ 4 Jérúsálẹ́mù jérúsálẹ́mù PROPN _ _ 3 obj _ _ 5 tó tó SCONJ _ _ 6 case _ _ 6 ibùsọ ibùsọ NOUN _ _ 3 obl _ _ 7 Mẹ́ẹ̀dógún Mẹ́ẹ̀dógún NUM _ NumType=Card 6 nummod _ _ 8 : : PUNCT _ _ 3 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-14 # text = Ọ̀pọ̀ nínú àwọn Júù sì wá sọ́dọ̀ Mátà àti Màríà láti tù wọ́n nínú nítorí ti arákùnrin wọn. 1 Ọ̀pọ̀ Ọ̀pọ̀ ADJ _ _ 6 nsubj _ _ 2 nínú nínú ADP _ _ 4 case _ _ 3 àwọn àwọn DET _ Number=Plur|PronType=Dem 4 det _ _ 4 Júù júù PROPN _ _ 1 nmod _ _ 5 sì sì CCONJ _ _ 6 cc _ _ 6 wá wá VERB _ _ 0 root _ _ 7 sọ́dọ̀ sọ́dọ̀ ADP _ _ 8 case _ _ 8 Mátà mátà PROPN _ _ 6 obl _ _ 9 àti àti CCONJ _ _ 10 cc _ _ 10 Màríà màríà PROPN _ _ 8 conj _ _ 11 láti láti ADP _ _ 12 mark _ _ 12 tù tù VERB _ _ 6 advcl _ _ 13 wọ́n wọ́n PRON _ Case=Acc|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 12 obj _ _ 14 nínú nínú ADP _ _ 17 case _ _ 15 nítorí nítorí SCONJ _ _ 17 case _ _ 16 ti ti ADP _ _ 17 case _ _ 17 arákùnrin arákùnrin NOUN _ _ 12 obl _ _ 18 wọn wọn PRON _ Case=Acc|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 17 nmod _ _ 19 . . PUNCT _ _ 6 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-15 # text = Nítorí náà, nígbà tí Mátà gbọ́ pé Jésù ń bọ̀ wá, ó jáde lọ pàdé rẹ̀: ṣùgbọ́n Màríà jòkó nínú ilé. 1 Nítorí nítorí SCONJ _ _ 15 mark _ _ 2 náà náà PRON _ _ 1 fixed _ _ 3 , , PUNCT _ _ 7 punct _ _ 4 nígbà nígbà ADV _ _ 7 advmod _ _ 5 tí tí PRON _ PronType=Rel 4 fixed _ _ 6 Mátà mátà PROPN _ _ 7 nsubj _ _ 7 gbọ́ gbọ́ VERB _ _ 15 advcl _ _ 8 pé pé SCONJ _ _ 11 mark _ _ 9 Jésù jésù PROPN _ _ 11 nsubj _ _ 10 ń ń AUX _ _ 11 aux _ _ 11 bọ̀ bọ̀ VERB _ _ 7 xcomp _ _ 12 wá wá VERB _ _ 11 compound:svc _ _ 13 , , PUNCT _ _ 7 punct _ _ 14 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 15 nsubj _ _ 15 jáde jáde VERB _ _ 0 root _ _ 16 lọ lọ VERB _ _ 15 compound:svc _ _ 17 pàdé pàdé VERB _ _ 16 compound:svc _ _ 18 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 17 obj _ _ 19 : : PUNCT _ _ 22 punct _ _ 20 ṣùgbọ́n ṣùgbọ́n CCONJ _ _ 22 cc _ _ 21 Màríà màríà PROPN _ _ 22 nsubj _ _ 22 jòkó jòkó VERB _ _ 15 conj _ _ 23 nínú nínú ADP _ _ 24 case _ _ 24 ilé ilé NOUN _ _ 22 obl _ _ 25 . . PUNCT _ _ 15 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-16 # text = Nígbà náà, ni Mátà wí fún Jésù pé, “Olúwa, ì bá ṣe pé ìwọ ti wà níhìn-ín, arákùnrin mi kì bá kú. 1 Nígbà nígbà ADV _ _ 6 advmod _ _ 2 náà náà ADV _ _ 1 fixed _ _ 3 , , PUNCT _ _ 2 punct _ _ 4 ni ni PART _ _ 5 case _ _ 5 Mátà Mátà PROPN _ _ 6 nsubj _ _ 6 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 7 fún fún ADP _ _ 8 case _ _ 8 Jésù Jésù PROPN _ _ 6 obl _ _ 9 pé pé SCONJ _ _ 27 mark _ _ 10 , , PUNCT _ _ 27 punct _ _ 11 “ “ PUNCT _ _ 27 punct _ _ 12 Olúwa Olúwa PROPN _ _ 27 vocative _ _ 13 , , PUNCT _ _ 12 punct _ _ 14 ì ì AUX _ _ 16 aux _ _ 15 bá bá AUX _ _ 14 fixed _ _ 16 ṣe ṣe VERB _ _ 27 advcl _ _ 17 pé pé SCONJ _ _ 16 mark _ _ 18 ìwọ ìwọ PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 20 nsubj _ _ 19 ti ti AUX _ _ 20 aux _ _ 20 wà wà VERB _ _ 16 ccomp _ _ 21 níhìn-ín níhìn-ín ADV _ _ 20 advmod _ _ 22 , , PUNCT _ _ 16 punct _ _ 23 arákùnrin arákùnrin NOUN _ _ 27 nsubj _ _ 24 mi mi PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 23 nmod _ _ 25 kì kì PART _ _ 27 advmod _ _ 26 bá bá SCONJ _ _ 27 mark _ _ 27 kú kú VERB _ _ 6 ccomp _ _ 28 . . PUNCT _ _ 6 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-17 # text = Jésù wí fún un pé, “Arákùnrin rẹ yóò jíǹde.” 1 Jésù jésù PROPN _ _ 2 nsubj _ _ 2 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 3 fún fún ADP _ _ 4 case _ _ 4 un un PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 2 obl _ _ 5 pé pé SCONJ _ _ 11 mark _ _ 6 , , PUNCT _ _ 11 punct _ _ 7 “ “ PUNCT _ _ 11 punct _ _ 8 Arákùnrin Arákùnrin NOUN _ _ 11 nsubj _ _ 9 rẹ rẹ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 8 nmod _ _ 10 yóò yóò AUX _ _ 11 aux _ _ 11 jíǹde jíǹde VERB _ _ 2 ccomp _ _ 12 . . PUNCT _ _ 11 punct _ _ 13 ” ” PUNCT _ _ 11 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-18 # text = Mátà wí fún un pé, “Mo mọ̀ pé yóò jíǹde ní àjíǹde ìkẹyìn.” 1 Mátà mátà PROPN _ _ 2 nsubj _ _ 2 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 3 fún fún ADP _ _ 4 case _ _ 4 un un PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 2 obl _ _ 5 pé pé SCONJ _ _ 9 mark _ _ 6 , , PUNCT _ _ 9 punct _ _ 7 “ “ PUNCT _ _ 9 punct _ _ 8 Mo Mo PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 9 nsubj _ _ 9 mọ̀ mọ̀ VERB _ _ 2 ccomp _ _ 10 pé pé SCONJ _ _ 12 mark _ _ 11 yóò yóò AUX _ _ 12 aux _ _ 12 jíǹde jíǹde VERB _ _ 9 ccomp _ _ 13 ní ní ADP _ _ 14 case _ _ 14 àjíǹde àjíǹde NOUN _ _ 12 obl _ _ 15 ìkẹyìn ìkẹyìn ADJ _ _ 14 amod _ _ 16 . . PUNCT _ _ 9 punct _ _ 17 ” ” PUNCT _ _ 9 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-19 # text = Jésù wí fún un pé, “Èmi ni àjíǹde àti ìyè: ẹni tí ó bá gbà mí gbọ́, bí ó tilẹ̀ kú, yóò yè: 1 Jésù jésù PROPN _ _ 2 nsubj _ _ 2 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 3 fún fún ADP _ _ 4 case _ _ 4 un un PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 2 obl _ _ 5 pé pé SCONJ _ _ 10 mark _ _ 6 , , PUNCT _ _ 10 punct _ _ 7 “ “ PUNCT _ _ 10 punct _ _ 8 Èmi Èmi PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 10 nsubj _ _ 9 ni ni PART _ _ 8 case _ _ 10 àjíǹde àjíǹde NOUN _ _ 2 ccomp _ _ 11 àti àti CCONJ _ _ 12 cc _ _ 12 ìyè ìyè NOUN _ _ 10 conj _ _ 13 : : PUNCT _ _ 28 punct _ _ 14 ẹni ẹni PRON _ PronType=Ind 28 nsubj _ _ 15 tí tí PRON _ PronType=Rel 14 fixed _ _ 16 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 18 expl _ _ 17 bá bá SCONJ _ _ 18 mark _ _ 18 gbà gbà VERB _ _ 14 acl _ _ 19 mí mí PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 18 obj _ _ 20 gbọ́ gbọ́ VERB _ _ 18 compound:svc _ _ 21 , , PUNCT _ _ 25 punct _ _ 22 bí bí SCONJ _ _ 25 mark _ _ 23 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 25 nsubj _ _ 24 tilẹ̀ tilẹ̀ SCONJ _ _ 25 mark _ _ 25 kú kú VERB _ _ 28 advcl _ _ 26 , , PUNCT _ _ 25 punct _ _ 27 yóò yóò AUX _ _ 28 aux _ _ 28 yè yè VERB _ _ 10 parataxis _ _ 29 : : PUNCT _ _ 2 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-20 # text = Ẹnikẹ́ni tí ó ń bẹ láàyè, tí ó sì gbà mí gbọ́, kì yóò kú láéláé ìwọ gbà èyí gbọ́?” 1 Ẹnikẹ́ni ẹnikẹ́ni PRON _ PronType=Ind 17 nsubj _ _ 2 tí tí PRON _ PronType=Rel 5 nsubj _ _ 3 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 5 expl _ _ 4 ń ń AUX _ _ 5 aux _ _ 5 bẹ bẹ VERB _ _ 1 acl _ _ 6 láàyè láàyè VERB _ _ 5 compound:svc _ _ 7 , , PUNCT _ _ 11 punct _ _ 8 tí tí PRON _ PronType=Rel 11 nsubj _ _ 9 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 11 expl _ _ 10 sì sì CCONJ _ _ 11 cc _ _ 11 gbà gbà VERB _ _ 5 conj _ _ 12 mí mí PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 11 obj _ _ 13 gbọ́ gbọ́ VERB _ _ 11 compound:svc _ _ 14 , , PUNCT _ _ 5 punct _ _ 15 kì kì PART _ _ 17 advmod _ _ 16 yóò yóò AUX _ _ 17 aux _ _ 17 kú kú VERB _ _ 0 root _ _ 18 láéláé láéláé ADV _ _ 17 advmod _ _ 19 ìwọ ìwọ PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 20 nsubj _ _ 20 gbà gbà VERB _ _ 17 parataxis _ _ 21 èyí èyí PRON _ PronType=Dem 20 obj _ _ 22 gbọ́ gbọ́ VERB _ _ 20 compound:svc _ _ 23 ? ? PUNCT _ _ 20 punct _ _ 24 ” ” PUNCT _ _ 17 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-21 # text = Ó wí fún un pé, “Bẹ́ẹ̀ ni, Olúwa: èmi gbàgbọ́ pé, ìwọ ni Kírísítì náà Ọmọ Ọlọ́run, ẹni tí ń bọ̀ wá sí ayé.” 1 Ó Ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 2 nsubj _ _ 2 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 3 fún fún ADP _ _ 4 case _ _ 4 un un PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 2 obl _ _ 5 pé pé SCONJ _ _ 14 mark _ _ 6 , , PUNCT _ _ 14 punct _ _ 7 “ “ PUNCT _ _ 14 punct _ _ 8 Bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ ADV _ _ 14 discourse _ _ 9 ni ni PART _ _ 8 compound:prt _ _ 10 , , PUNCT _ _ 14 punct _ _ 11 Olúwa Olúwa PROPN _ _ 14 vocative _ _ 12 : : PUNCT _ _ 14 punct _ _ 13 èmi èmi PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 14 nsubj _ _ 14 gbàgbọ́ gbàgbọ́ VERB _ _ 2 ccomp _ _ 15 pé pé SCONJ _ _ 19 mark _ _ 16 , , PUNCT _ _ 19 punct _ _ 17 ìwọ ìwọ PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 19 nsubj _ _ 18 ni ni PART _ _ 17 case _ _ 19 Kírísítì kírísítì PROPN _ _ 14 ccomp _ _ 20 náà náà DET _ _ 21 det _ _ 21 Ọmọ Ọmọ NOUN _ _ 19 appos _ _ 22 Ọlọ́run Ọlọ́run NOUN _ _ 21 nmod _ _ 23 , , PUNCT _ _ 24 punct _ _ 24 ẹni ẹni PRON _ PronType=Ind 19 appos _ _ 25 tí tí PRON _ PronType=Rel 24 fixed _ _ 26 ń ń AUX _ _ 27 aux _ _ 27 bọ̀ bọ̀ VERB _ _ 24 acl _ _ 28 wá wá VERB _ _ 27 compound:svc _ _ 29 sí sí ADP _ _ 30 case _ _ 30 ayé ayé NOUN _ _ 27 obl _ _ 31 . . PUNCT _ _ 14 punct _ _ 32 ” ” PUNCT _ _ 14 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-22 # text = Nígbà tí ó sì ti wí èyí tán, ó lọ, ó sì pe Màríà arábìnrin rẹ̀ sẹ́yìn wí pé, “Olùkọ́ dé, ó sì ń pè ọ́.” 1 Nígbà nígbà ADV _ _ 6 advmod _ _ 2 tí tí PRON _ PronType=Rel 1 fixed _ _ 3 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 6 nsubj _ _ 4 sì sì CCONJ _ _ 6 cc _ _ 5 ti ti AUX _ _ 6 aux _ _ 6 wí wí VERB _ _ 11 advcl _ _ 7 èyí èyí PRON _ PronType=Dem 6 obj _ _ 8 tán tán VERB _ _ 6 compound:svc _ _ 9 , , PUNCT _ _ 6 punct _ _ 10 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 11 nsubj _ _ 11 lọ lọ VERB _ _ 0 root _ _ 12 , , PUNCT _ _ 15 punct _ _ 13 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 15 nsubj _ _ 14 sì sì CCONJ _ _ 15 cc _ _ 15 pe pe VERB _ _ 11 conj _ _ 16 Màríà màríà PROPN _ _ 15 obj _ _ 17 arábìnrin arábìnrin NOUN _ _ 16 appos _ _ 18 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 17 nmod _ _ 19 sẹ́yìn sẹ́yìn ADV _ _ 15 advmod _ _ 20 wí wí VERB _ _ 15 xcomp _ _ 21 pé pé SCONJ _ _ 20 compound _ _ 22 , , PUNCT _ _ 25 punct _ _ 23 “ “ PUNCT _ _ 25 punct _ _ 24 Olùkọ́ olùkọ́ NOUN _ _ 25 nsubj _ _ 25 dé dé VERB _ _ 20 ccomp _ _ 26 , , PUNCT _ _ 30 punct _ _ 27 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 30 nsubj _ _ 28 sì sì CCONJ _ _ 30 cc _ _ 29 ń ń AUX _ _ 30 aux _ _ 30 pè pè VERB _ _ 25 conj _ _ 31 ọ́ ọ́ PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 30 obj _ _ 32 . . PUNCT _ _ 25 punct _ _ 33 ” ” PUNCT _ _ 25 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-23 # text = Nígbà tí ó gbọ́, ó dìde lọ́gán, ó sì wá sọ́dọ̀ rẹ̀. 1 Nígbà nígbà ADV _ _ 4 advmod _ _ 2 tí tí PRON _ PronType=Rel 1 fixed _ _ 3 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 4 nsubj _ _ 4 gbọ́ gbọ́ VERB _ _ 7 advcl _ _ 5 , , PUNCT _ _ 4 punct _ _ 6 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 7 nsubj _ _ 7 dìde dìde VERB _ _ 0 root _ _ 8 lọ́gán lọ́gán ADV _ _ 7 advmod _ _ 9 , , PUNCT _ _ 12 punct _ _ 10 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 12 nsubj _ _ 11 sì sì CCONJ _ _ 12 cc _ _ 12 wá wá VERB _ _ 7 conj _ _ 13 sọ́dọ̀ sọ́dọ̀ ADP _ _ 14 case _ _ 14 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 12 obl _ _ 15 . . PUNCT _ _ 7 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-24 # text = Jésù kò tíì wọ ìlú, ṣùgbọ́n ó wà ní ibi kan náà tí Mátà ti pàdé rẹ̀. 1 Jésù jésù PROPN _ _ 4 nsubj _ _ 2 kò kò PART _ _ 4 advmod _ _ 3 tíì tíì ADV _ _ 4 advmod _ _ 4 wọ wọ VERB _ _ 0 root _ _ 5 ìlú ìlú NOUN _ _ 4 obj _ _ 6 , , PUNCT _ _ 9 punct _ _ 7 ṣùgbọ́n ṣùgbọ́n CCONJ _ _ 9 cc _ _ 8 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 9 nsubj _ _ 9 wà wà VERB _ _ 4 conj _ _ 10 ní ní ADP _ _ 11 case _ _ 11 ibi ibi NOUN _ _ 9 obl _ _ 12 kan kan NUM _ NumType=Card 11 nummod _ _ 13 náà náà DET _ _ 11 det _ _ 14 tí tí PRON _ PronType=Rel 17 obl _ _ 15 Mátà mátà PROPN _ _ 17 nsubj _ _ 16 ti ti AUX _ _ 17 aux _ _ 17 pàdé pàdé VERB _ _ 11 acl _ _ 18 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 17 obj _ _ 19 . . PUNCT _ _ 4 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-25 # text = Nígbà tí àwọn Júù tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ̀ nínú ilé, tí wọ́n ń tù ú nínú rí Màríà tí ó dìde kánkán, tí ó sì jáde, wọ́n tẹ̀lé, wọ́n ṣebí ó ń lọ sí ibojì láti sọkún níbẹ̀. 1 Nígbà nígbà ADV _ _ 19 advmod _ _ 2 tí tí PRON _ PronType=Rel 1 fixed _ _ 3 àwọn àwọn DET _ Number=Plur|PronType=Dem 4 det _ _ 4 Júù júù PROPN _ _ 19 nsubj _ _ 5 tí tí PRON _ PronType=Rel 7 nsubj _ _ 6 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 7 expl _ _ 7 wà wà VERB _ _ 4 advcl _ _ 8 lọ́dọ̀ lọ́dọ̀ ADP _ _ 9 case _ _ 9 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 7 obl _ _ 10 nínú nínú ADP _ _ 11 case _ _ 11 ilé ilé NOUN _ _ 7 obl _ _ 12 , , PUNCT _ _ 16 punct _ _ 13 tí tí PRON _ PronType=Rel 16 nsubj _ _ 14 wọ́n wọ́n PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 16 expl _ _ 15 ń ń AUX _ _ 16 aux _ _ 16 tù tù VERB _ _ 7 conj _ _ 17 ú ú PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 16 obj _ _ 18 nínú nínú ADP _ _ 16 compound:prt _ _ 19 rí rí VERB _ _ 32 advcl _ _ 20 Màríà màríà PROPN _ _ 19 obj _ _ 21 tí tí PRON _ PronType=Rel 23 nsubj _ _ 22 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 23 expl _ _ 23 dìde dìde VERB _ _ 20 acl _ _ 24 kánkán kánkán ADV _ _ 23 advmod _ _ 25 , , PUNCT _ _ 29 punct _ _ 26 tí tí PRON _ PronType=Rel 29 nsubj _ _ 27 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 29 expl _ _ 28 sì sì CCONJ _ _ 29 cc _ _ 29 jáde jáde VERB _ _ 23 conj _ _ 30 , , PUNCT _ _ 19 punct _ _ 31 wọ́n wọ́n PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 32 nsubj _ _ 32 tẹ̀lé tẹ̀lé VERB _ _ 0 root _ _ 33 , , PUNCT _ _ 35 punct _ _ 34 wọ́n wọ́n PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 35 nsubj _ _ 35 ṣebí ṣebí VERB _ _ 32 conj _ _ 36 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 38 nsubj _ _ 37 ń ń AUX _ _ 38 aux _ _ 38 lọ lọ VERB _ _ 35 ccomp _ _ 39 sí sí ADP _ _ 40 case _ _ 40 ibojì ibojì NOUN _ _ 38 obl _ _ 41 láti láti ADP _ _ 42 mark _ _ 42 sọkún sọkún VERB _ _ 40 xcomp _ _ 43 níbẹ̀ níbẹ̀ ADV _ _ 42 advmod _ _ 44 . . PUNCT _ _ 32 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-26 # text = Nígbà tí Màríà sì dé ibi tí Jésù wà, tí ó sì rí i, ó wólẹ̀ lẹ́bàá ẹsẹ̀ rẹ̀, ó wí fún un pé, “Olúwa, ìbáṣe pé ìwọ ti wà níhín-ín, arákùnrin mi kì bá kú.” 1 Nígbà nígbà ADV _ _ 5 advmod _ _ 2 tí tí PRON _ PronType=Rel 1 fixed _ _ 3 Màríà màríà PROPN _ _ 5 nsubj _ _ 4 sì sì CCONJ _ _ 5 cc _ _ 5 dé dé VERB _ _ 18 advcl _ _ 6 ibi ibi NOUN _ _ 5 obj _ _ 7 tí tí ADV _ _ 6 fixed _ _ 8 Jésù jésù PROPN _ _ 9 nsubj _ _ 9 wà wà VERB _ _ 6 acl _ _ 10 , , PUNCT _ _ 14 punct _ _ 11 tí tí PRON _ PronType=Rel 14 obl _ _ 12 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 14 nsubj _ _ 13 sì sì CCONJ _ _ 14 cc _ _ 14 rí rí VERB _ _ 9 conj _ _ 15 i i PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 14 obj _ _ 16 , , PUNCT _ _ 5 punct _ _ 17 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 18 nsubj _ _ 18 wólẹ̀ wólẹ̀ VERB _ _ 0 root _ _ 19 lẹ́bàá lẹ́bàá ADP _ _ 20 case _ _ 20 ẹsẹ̀ ẹsẹ̀ NOUN _ _ 18 obl _ _ 21 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 20 nmod _ _ 22 , , PUNCT _ _ 24 punct _ _ 23 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 24 nsubj _ _ 24 wí wí VERB _ _ 18 conj _ _ 25 fún fún ADP _ _ 26 case _ _ 26 un un PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 24 obl _ _ 27 pé pé SCONJ _ _ 43 mark _ _ 28 , , PUNCT _ _ 43 punct _ _ 29 “ “ PUNCT _ _ 43 punct _ _ 30 Olúwa Olúwa PROPN _ _ 43 vocative _ _ 31 , , PUNCT _ _ 30 punct _ _ 32 ìbáṣe ìbáṣe SCONJ _ _ 36 mark _ _ 33 pé pé SCONJ _ _ 36 mark _ _ 34 ìwọ ìwọ PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 36 nsubj _ _ 35 ti ti AUX _ _ 36 aux _ _ 36 wà wà VERB _ _ 43 advcl _ _ 37 níhín-ín níhín-ín ADV _ _ 36 advmod _ _ 38 , , PUNCT _ _ 36 punct _ _ 39 arákùnrin arákùnrin NOUN _ _ 43 nsubj _ _ 40 mi mi PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 39 nmod _ _ 41 kì kì PART _ _ 43 advmod _ _ 42 bá bá SCONJ _ _ 43 mark _ _ 43 kú kú VERB _ _ 24 ccomp _ _ 44 . . PUNCT _ _ 43 punct _ _ 45 ” ” PUNCT _ _ 43 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-27 # text = Ó sì wí pé, “Níbo ni ẹ̀yin gbé tẹ́ ẹ sí?” Wọ́n sì wí fún un pé, “Olúwa, wá wò ó.” 1 Ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 3 nsubj _ _ 2 sì sì CCONJ _ _ 3 cc _ _ 3 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 4 pé pé SCONJ _ _ 3 compound _ _ 5 , , PUNCT _ _ 10 punct _ _ 6 “ “ PUNCT _ _ 10 punct _ _ 7 Níbo níbo ADV _ _ 10 advmod _ _ 8 ni ni PART _ _ 7 case _ _ 9 ẹ̀yin ẹ̀yin PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=2|PronType=Prs 10 nsubj _ _ 10 gbé gbé VERB _ _ 3 xcomp _ _ 11 tẹ́ tẹ́ VERB _ _ 10 compound:svc _ _ 12 ẹ ẹ PRON _ Case=Acc|Number=Plur|Person=2|PronType=Prs 10 obj _ _ 13 sí sí ADP _ _ 7 case _ _ 14 ? ? PUNCT _ _ 10 punct _ _ 15 ” ” PUNCT _ _ 10 punct _ _ 16 Wọ́n Wọ́n PRON _ _ 18 nsubj _ _ 17 sì sì CCONJ _ _ 18 cc _ _ 18 wí wí VERB _ _ 3 parataxis _ _ 19 fún fún ADP _ _ 20 case _ _ 20 un un PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 18 obl _ _ 21 pé pé SCONJ _ _ 26 mark _ _ 22 , , PUNCT _ _ 26 punct _ _ 23 “ “ PUNCT _ _ 26 punct _ _ 24 Olúwa Olúwa PROPN _ _ 26 vocative _ _ 25 , , PUNCT _ _ 24 punct _ _ 26 wá wá VERB _ _ 18 ccomp _ _ 27 wò wò VERB _ _ 26 compound:svc _ _ 28 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 27 obj _ _ 29 . . PUNCT _ _ 26 punct _ _ 30 ” ” PUNCT _ _ 26 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-28 # text = Jésù sọkún. 1 Jésù jésù PROPN _ _ 2 nsubj _ _ 2 sọkún sọkún VERB _ _ 0 root _ _ 3 . . PUNCT _ _ 2 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-29 # text = Nítorí náà àwọn Júù wí pé, “Sá wò ó bí ó ti fẹ́ràn rẹ̀ tó!” 1 Nítorí nítorí SCONJ _ _ 5 mark _ _ 2 náà náà PRON _ _ 1 fixed _ _ 3 àwọn àwọn DET _ Number=Plur|PronType=Dem 4 det _ _ 4 Júù júù PROPN _ _ 5 nsubj _ _ 5 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 6 pé pé SCONJ _ _ 5 compound _ _ 7 , , PUNCT _ _ 10 punct _ _ 8 “ “ PUNCT _ _ 10 punct _ _ 9 Sá sá ADV _ _ 10 advmod _ _ 10 wò wò VERB _ _ 5 ccomp _ _ 11 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 10 obj _ _ 12 bí bí SCONJ _ _ 15 mark _ _ 13 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 15 nsubj _ _ 14 ti ti AUX _ _ 15 aux _ _ 15 fẹ́ràn fẹ́ràn VERB _ _ 11 acl _ _ 16 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 15 obj _ _ 17 tó tó ADV _ _ 15 advmod _ _ 18 ! ! PUNCT _ _ 10 punct _ _ 19 ” ” PUNCT _ _ 10 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-30 # text = Àwọn kan nínú wọn sì wí pé, “Ọkùnrin yìí, ẹni tí ó la ojú afọ́jú, kò lè ṣeé kí ọkùnrin yìí má kú bí?” 1 Àwọn àwọn PRON _ PronType=Ind 6 nsubj _ _ 2 kan kan NUM _ NumType=Card 1 nummod _ _ 3 nínú nínú ADP _ _ 4 case _ _ 4 wọn wọn PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 1 nmod _ _ 5 sì sì CCONJ _ _ 6 cc _ _ 6 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 7 pé pé SCONJ _ _ 6 compound _ _ 8 , , PUNCT _ _ 22 punct _ _ 9 “ “ PUNCT _ _ 22 punct _ _ 10 Ọkùnrin Ọkùnrin NOUN _ _ 22 nsubj _ _ 11 yìí yìí DET _ _ 10 det _ _ 12 , , PUNCT _ _ 13 punct _ _ 13 ẹni ẹni PRON _ PronType=Ind 10 appos _ _ 14 tí tí PRON _ PronType=Rel 13 fixed _ _ 15 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 16 expl _ _ 16 la la VERB _ _ 13 acl _ _ 17 ojú ojú NOUN _ _ 16 obj _ _ 18 afọ́jú afọ́jú ADJ _ _ 17 amod _ _ 19 , , PUNCT _ _ 13 punct _ _ 20 kò kò PART _ _ 22 advmod _ _ 21 lè lè AUX _ _ 22 aux _ _ 22 ṣeé ṣeé VERB _ _ 6 ccomp _ _ 23 kí kí SCONJ _ _ 27 mark _ _ 24 ọkùnrin ọkùnrin NOUN _ _ 27 nsubj _ _ 25 yìí yìí DET _ _ 24 det _ _ 26 má má AUX _ _ 27 aux _ _ 27 kú kú VERB _ _ 22 ccomp _ _ 28 bí bí SCONJ _ _ 27 mark _ _ 29 ? ? PUNCT _ _ 22 punct _ _ 30 ” ” PUNCT _ _ 22 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-31 # text = Nígbà náà ni Jésù tún kérora nínú ara rẹ̀, ó wá sí ibojì, ó sì jẹ́ ihò, a sì gbé òkúta lé ẹnu rẹ̀. 1 Nígbà nígbà ADV _ _ 6 advmod _ _ 2 náà náà ADV _ _ 1 fixed _ _ 3 ni ni PART _ _ 4 case _ _ 4 Jésù jésù PROPN _ _ 6 nsubj _ _ 5 tún tún ADV _ _ 6 advmod _ _ 6 kérora kérora VERB _ _ 12 advcl _ _ 7 nínú nínú ADP _ _ 8 case _ _ 8 ara ara PRON _ PronType=Emp 6 obl _ _ 9 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 8 nmod _ _ 10 , , PUNCT _ _ 6 punct _ _ 11 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 12 nsubj _ _ 12 wá wá VERB _ _ 0 root _ _ 13 sí sí ADP _ _ 14 case _ _ 14 ibojì ibojì NOUN _ _ 12 obl _ _ 15 , , PUNCT _ _ 19 punct _ _ 16 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 19 nsubj _ _ 17 sì sì CCONJ _ _ 19 cc _ _ 18 jẹ́ jẹ́ AUX _ _ 19 cop _ _ 19 ihò ihò NOUN _ _ 12 conj _ _ 20 , , PUNCT _ _ 23 punct _ _ 21 a a PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 23 nsubj _ _ 22 sì sì CCONJ _ _ 23 cc _ _ 23 gbé gbé VERB _ _ 19 conj _ _ 24 òkúta òkúta NOUN _ _ 23 obj _ _ 25 lé lé ADP _ _ 23 case _ _ 26 ẹnu ẹnu NOUN _ _ 27 obj _ _ 27 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 23 nmod _ _ 28 . . PUNCT _ _ 12 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-32 # text = Jésù wí pé, “Ẹ gbé òkúta náà kúrò!” Màtá, arábìnrin ẹni tí ó kú náà wí fún un pé, “Olúwa, ó ti ń rùn nísinsin yìí: nítorí pé ó di ijọ́ kẹrin tí ó tí kú.” 1 Jésù jésù PROPN _ _ 2 nsubj _ _ 2 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 3 pé pé SCONJ _ _ 2 compound _ _ 4 , , PUNCT _ _ 7 punct _ _ 5 “ “ PUNCT _ _ 7 punct _ _ 6 Ẹ ẹ PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=2|PronType=Prs 7 nsubj _ _ 7 gbé gbé VERB _ _ 2 xcomp _ _ 8 òkúta òkúta NOUN _ _ 7 obj _ _ 9 náà náà DET _ _ 8 det _ _ 10 kúrò kúrò ADP _ _ 7 compound:prt _ _ 11 ! ! PUNCT _ _ 7 punct _ _ 12 ” ” PUNCT _ _ 7 punct _ _ 13 Màtá màtá PROPN _ _ 21 nsubj _ _ 14 , , PUNCT _ _ 15 punct _ _ 15 arábìnrin arábìnrin NOUN _ _ 13 appos _ _ 16 ẹni ẹni PRON _ PronType=Ind 15 nmod _ _ 17 tí tí PRON _ PronType=Rel 16 fixed _ _ 18 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 19 expl _ _ 19 kú kú VERB _ _ 16 acl _ _ 20 náà náà ADV _ _ 21 advmod _ _ 21 wí wí VERB _ _ 2 parataxis _ _ 22 fún fún ADP _ _ 23 case _ _ 23 un un PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 21 obl _ _ 24 pé pé SCONJ _ _ 32 mark _ _ 25 , , PUNCT _ _ 32 punct _ _ 26 “ “ PUNCT _ _ 32 punct _ _ 27 Olúwa Olúwa PROPN _ _ 32 vocative _ _ 28 , , PUNCT _ _ 27 punct _ _ 29 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 32 nsubj _ _ 30 ti ti AUX _ _ 32 aux _ _ 31 ń ń AUX _ _ 32 aux _ _ 32 rùn rùn VERB _ _ 21 ccomp _ _ 33 nísinsin nísinsin ADV _ _ 32 advmod _ _ 34 yìí yìí DET _ _ 33 det _ _ 35 : : PUNCT _ _ 39 punct _ _ 36 nítorí nítorí SCONJ _ _ 39 mark _ _ 37 pé pé SCONJ _ _ 36 fixed _ _ 38 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 39 nsubj _ _ 39 di di VERB _ _ 32 advcl _ _ 40 ijọ́ ijọ́ NOUN _ _ 39 obj _ _ 41 kẹrin kẹrin ADJ _ NumType=Ord 40 amod _ _ 42 tí tí PRON _ PronType=Rel 45 obl _ _ 43 ó ó AUX _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 45 nsubj _ _ 44 tí ti AUX _ Typo=Yes 45 aux _ _ 45 kú kú VERB _ _ 40 acl _ _ 46 . . PUNCT _ _ 32 punct _ _ 47 ” ” PUNCT _ _ 32 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-33 # text = Jésù wí fún un pé, “Èmi kò ti wí fún ọ pé, bí ìwọ bá gbàgbọ́, ìwọ ó rí ògo Ọlọ́run?” 1 Jésù jésù PROPN _ _ 2 nsubj _ _ 2 wí wí VERB _ _ 0 root _ _ 3 fún fún ADP _ _ 4 case _ _ 4 un un PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 2 obl _ _ 5 pé pé SCONJ _ _ 11 mark _ _ 6 , , PUNCT _ _ 11 punct _ _ 7 “ “ PUNCT _ _ 11 punct _ _ 8 Èmi Èmi PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 11 nsubj _ _ 9 kò kò PART _ _ 11 advmod _ _ 10 ti ti AUX _ _ 11 aux _ _ 11 wí wí VERB _ _ 2 ccomp _ _ 12 fún fún ADP _ _ 13 case _ _ 13 ọ ọ PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 11 obl _ _ 14 pé pé SCONJ _ _ 23 mark _ _ 15 , , PUNCT _ _ 23 punct _ _ 16 bí bí SCONJ _ _ 19 mark _ _ 17 ìwọ ìwọ PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 19 nsubj _ _ 18 bá bá SCONJ _ _ 19 mark _ _ 19 gbàgbọ́ gbàgbọ́ VERB _ _ 23 advcl _ _ 20 , , PUNCT _ _ 19 punct _ _ 21 ìwọ ìwọ PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 23 nsubj _ _ 22 ó ó AUX _ _ 23 aux _ _ 23 rí rí VERB _ _ 11 ccomp _ _ 24 ògo ògo NOUN _ _ 23 obj _ _ 25 Ọlọ́run Ọlọ́run NOUN _ _ 24 nmod _ _ 26 ? ? PUNCT _ _ 11 punct _ _ 27 ” ” PUNCT _ _ 11 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-34 # text = Nígbà náà ni wọ́n gbé òkúta náà kúrò (níbi tí a tẹ́ ẹ sí). Jésù sì gbé ojú rẹ̀ sókè, ó sì wí pé, “Baba, mo dúpẹ́ lọ́wọ́ rẹ nítorí tí ìwọ gbọ́ tèmi. 1 Nígbà nígbà ADV _ _ 5 advmod _ _ 2 náà náà ADV _ _ 1 fixed _ _ 3 ni ni PART _ _ 4 case _ _ 4 wọ́n wọ́n PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 5 nsubj _ _ 5 gbé gbé VERB _ _ 0 root _ _ 6 òkúta òkúta NOUN _ _ 5 obj _ _ 7 náà náà DET _ _ 6 det _ _ 8 kúrò kúrò ADP _ _ 5 compound:prt _ _ 9 ( ( PUNCT _ _ 13 punct _ _ 10 níbi níbi ADV _ _ 13 advmod _ _ 11 tí tí PRON _ PronType=Rel 10 fixed _ _ 12 a a PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=1|PronType=Prs 13 nsubj _ _ 13 tẹ́ tẹ́ VERB _ _ 5 advcl _ _ 14 ẹ ẹ PRON _ _ 13 obj _ _ 15 sí sí ADP _ _ 10 case _ _ 16 ) ) PUNCT _ _ 13 punct _ _ 17 . . PUNCT _ _ 5 punct _ _ 18 Jésù jésù PROPN _ _ 20 nsubj _ _ 19 sì sì CCONJ _ _ 20 cc _ _ 20 gbé gbé VERB _ _ 5 parataxis _ _ 21 ojú ojú NOUN _ _ 20 obj _ _ 22 rẹ̀ rẹ̀ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 21 nmod _ _ 23 sókè sókè ADP _ _ 20 compound:prt _ _ 24 , , PUNCT _ _ 27 punct _ _ 25 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 27 nsubj _ _ 26 sì sì CCONJ _ _ 27 cc _ _ 27 wí wí VERB _ _ 20 conj _ _ 28 pé pé SCONJ _ _ 27 compound _ _ 29 , , PUNCT _ _ 34 punct _ _ 30 “ “ PUNCT _ _ 34 punct _ _ 31 Baba Baba NOUN _ _ 34 vocative _ _ 32 , , PUNCT _ _ 31 punct _ _ 33 mo mo PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 34 nsubj _ _ 34 dúpẹ́ dúpẹ́ VERB _ _ 27 ccomp _ _ 35 lọ́wọ́ lọ́wọ́ ADP _ _ 36 case _ _ 36 rẹ rẹ PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 34 obl _ _ 37 nítorí nítorí SCONJ _ _ 40 mark _ _ 38 tí tí PRON _ PronType=Rel 37 fixed _ _ 39 ìwọ ìwọ PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 40 nsubj _ _ 40 gbọ́ gbọ́ VERB _ _ 34 advcl _ _ 41 tèmi tèmi PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 40 obj _ _ 42 . . PUNCT _ _ 20 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-35 # text = Èmi sì ti mọ̀ pé, ìwọ a máa gbọ́ ti èmi nígbà gbogbo: ṣùgbọ́n nítorí ìjọ ènìyàn tí ó dúró yìí ni mo ṣe wí i, kí wọn baà lè gbàgbọ́ pé ìwọ ni ó rán mi.” 1 Èmi èmi PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 4 nsubj _ _ 2 sì sì CCONJ _ _ 4 cc _ _ 3 ti ti AUX _ _ 4 aux _ _ 4 mọ̀ mọ̀ VERB _ _ 0 root _ _ 5 pé pé SCONJ _ _ 10 mark _ _ 6 , , PUNCT _ _ 10 punct _ _ 7 ìwọ ìwọ PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 10 nsubj _ _ 8 a a ADV _ _ 10 advmod _ _ 9 máa máa AUX _ _ 10 aux _ _ 10 gbọ́ gbọ́ VERB _ _ 4 ccomp _ _ 11 ti ti PRON _ _ 12 nmod _ _ 12 èmi èmi PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 10 obl _ _ 13 nígbà nígbà ADV _ _ 10 advmod _ _ 14 gbogbo gbogbo DET _ _ 13 fixed _ _ 15 : : PUNCT _ _ 26 punct _ _ 16 ṣùgbọ́n ṣùgbọ́n CCONJ _ _ 26 cc _ _ 17 nítorí nítorí SCONJ _ _ 18 case _ _ 18 ìjọ ìjọ NOUN _ _ 26 obl _ _ 19 ènìyàn ènìyàn NOUN _ _ 18 nmod _ _ 20 tí tí PRON _ PronType=Rel 22 nsubj _ _ 21 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 22 expl _ _ 22 dúró dúró VERB _ _ 19 acl _ _ 23 yìí yìí DET _ _ 22 obl _ _ 24 ni ni PART _ _ 18 case _ _ 25 mo mo PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 26 nsubj _ _ 26 ṣe ṣe VERB _ _ 4 conj _ _ 27 wí wí VERB _ _ 26 compound:svc _ _ 28 i i PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 27 obj _ _ 29 , , PUNCT _ _ 34 punct _ _ 30 kí kí SCONJ _ _ 34 mark _ _ 31 wọn wọn PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 34 nsubj _ _ 32 baà baà SCONJ _ _ 34 mark _ _ 33 lè lè AUX _ _ 34 aux _ _ 34 gbàgbọ́ gbàgbọ́ VERB _ _ 27 advcl _ _ 35 pé pé SCONJ _ _ 39 mark _ _ 36 ìwọ ìwọ PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=2|PronType=Prs 39 nsubj _ _ 37 ni ni PART _ _ 36 case _ _ 38 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 39 expl _ _ 39 rán rán VERB _ _ 34 xcomp _ _ 40 mi mi PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=1|PronType=Prs 39 obj _ _ 41 . . PUNCT _ _ 4 punct _ _ 42 ” ” PUNCT _ _ 4 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-36 # text = Nígbà tí ó sì wí bẹ́ẹ̀ tan, ó kígbe lóhùn rara pé, “Lásárù, jáde wá.” 1 Nígbà nígbà ADV _ _ 5 advmod _ _ 2 tí tí PRON _ PronType=Rel 1 fixed _ _ 3 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 5 nsubj _ _ 4 sì sì CCONJ _ _ 5 cc _ _ 5 wí wí VERB _ _ 10 advcl _ _ 6 bẹ́ẹ̀ bẹ́ẹ̀ ADV _ _ 5 advmod _ _ 7 tan tan VERB _ _ 5 compound:svc _ _ 8 , , PUNCT _ _ 5 punct _ _ 9 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 10 nsubj _ _ 10 kígbe kígbe VERB _ _ 0 root _ _ 11 lóhùn lóhùn VERB _ _ 10 compound:svc _ _ 12 rara rara ADV _ _ 10 advmod _ _ 13 pé pé SCONJ _ _ 18 mark _ _ 14 , , PUNCT _ _ 18 punct _ _ 15 “ “ PUNCT _ _ 18 punct _ _ 16 Lásárù lásárù PROPN _ _ 18 vocative _ _ 17 , , PUNCT _ _ 16 punct _ _ 18 jáde jáde VERB _ _ 10 ccomp _ _ 19 wá wá VERB _ _ 18 compound:svc _ _ 20 . . PUNCT _ _ 18 punct _ _ 21 ” ” PUNCT _ _ 18 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-37 # text = Ẹni tí ó kú náà sì jáde wá, tí a fi aṣọ òkú dì tọwọ́ tẹsẹ̀ a sì fi gèlè dì í lójú. Jésù wí fún wọn pé, “Ẹ tú u, ẹ sì jẹ́ kí ó má a lọ!” 1 Ẹni ẹni PRON _ PronType=Ind 7 nsubj _ _ 2 tí tí PRON _ PronType=Rel 1 fixed _ _ 3 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 4 expl _ _ 4 kú kú VERB _ _ 1 acl _ _ 5 náà náà ADV _ _ 4 advmod _ _ 6 sì sì CCONJ _ _ 7 cc _ _ 7 jáde jáde VERB _ _ 0 root _ _ 8 wá wá VERB _ _ 7 compound:svc _ _ 9 , , PUNCT _ _ 12 punct _ _ 10 tí tí PRON _ PronType=Rel 12 obl _ _ 11 a a PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=1|PronType=Prs 12 nsubj _ _ 12 fi fi VERB _ _ 4 conj _ _ 13 aṣọ aṣọ NOUN _ _ 12 obj _ _ 14 òkú òkú NOUN _ _ 13 nmod _ _ 15 dì dì VERB _ _ 12 compound:svc _ _ 16 tọwọ́ tọwọ́ NOUN _ _ 15 conj _ _ 17 tẹsẹ̀ tẹsẹ̀ NOUN _ _ 16 compound _ _ 18 a a PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=1|PronType=Prs 20 nsubj _ _ 19 sì sì CCONJ _ _ 20 cc _ _ 20 fi fi VERB _ _ 12 conj _ _ 21 gèlè gèlè NOUN _ _ 20 obj _ _ 22 dì dì VERB _ _ 20 compound:svc _ _ 23 í í PRON _ Case=Acc|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 22 obj _ _ 24 lójú lójú NOUN _ _ 22 obl _ _ 25 . . PUNCT _ _ 7 punct _ _ 26 Jésù jésù PROPN _ _ 27 nsubj _ _ 27 wí wí VERB _ _ 7 parataxis _ _ 28 fún fún ADP _ _ 29 case _ _ 29 wọn wọn PRON _ Case=Acc|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 27 obl _ _ 30 pé pé SCONJ _ _ 34 mark _ _ 31 , , PUNCT _ _ 34 punct _ _ 32 “ “ PUNCT _ _ 34 punct _ _ 33 Ẹ Ẹ PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=2|PronType=Prs 34 nsubj _ _ 34 tú tú VERB _ _ 27 ccomp _ _ 35 u u PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 34 obj _ _ 36 , , PUNCT _ _ 39 punct _ _ 37 ẹ ẹ PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=2|PronType=Prs 39 nsubj _ _ 38 sì sì CCONJ _ _ 39 cc _ _ 39 jẹ́ jẹ́ VERB _ _ 34 ccomp _ _ 40 kí kí AUX _ _ 39 aux _ _ 41 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 44 nsubj _ _ 42 má máa AUX _ Typo=Yes 44 aux _ _ 43 a _ X _ _ 42 goeswith _ _ 44 lọ lọ VERB _ _ 39 ccomp _ _ 45 ! ! PUNCT _ _ 34 punct _ _ 46 ” ” PUNCT _ _ 34 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-38 # text = Nítorí náà ni ọ̀pọ̀ àwọn Júù tí ó wá sọ́dọ̀ Màríà, tí wọ́n rí ohun tí Jésù ṣe, ṣe gbà á gbọ́. 1 Nítorí nítorí SCONJ _ _ 21 mark _ _ 2 náà náà PRON _ _ 1 fixed _ _ 3 ni ni PART _ _ 6 case _ _ 4 ọ̀pọ̀ ọ̀pọ̀ ADJ _ _ 6 amod _ _ 5 àwọn àwọn DET _ Number=Plur|PronType=Dem 6 det _ _ 6 Júù júù PROPN _ _ 21 nsubj _ _ 7 tí tí PRON _ PronType=Rel 9 nsubj _ _ 8 ó ó PRON _ Case=Nom|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 9 expl _ _ 9 wá wá VERB _ _ 6 acl _ _ 10 sọ́dọ̀ sọ́dọ̀ ADP _ _ 11 case _ _ 11 Màríà màríà PROPN _ _ 9 obl _ _ 12 , , PUNCT _ _ 15 punct _ _ 13 tí tí PRON _ PronType=Rel 15 nsubj _ _ 14 wọ́n wọ́n PRON _ _ 15 expl _ _ 15 rí rí VERB _ _ 9 conj _ _ 16 ohun ohun NOUN _ _ 15 obj _ _ 17 tí tí PRON _ PronType=Rel 19 obj _ _ 18 Jésù jésù PROPN _ _ 19 nsubj _ _ 19 ṣe ṣe VERB _ _ 16 acl _ _ 20 , , PUNCT _ _ 9 punct _ _ 21 ṣe ṣe VERB _ _ 0 root _ _ 22 gbà gbà VERB _ _ 21 compound:svc _ _ 23 á á PRON _ Case=Gen|Number=Sing|Person=3|PronType=Prs 21 obj _ _ 24 gbọ́ gbọ́ VERB _ _ 21 compound:svc _ _ 25 . . PUNCT _ _ 21 punct _ _ # sent_id = yo-ytb-test-JOHN_11:s-39 # text = Ṣùgbọ́n àwọn ẹlòmíràn nínú wọn tọ àwọn Farisí lọ, wọ́n sì sọ fún wọn ohun tí Jésù ṣe. 1 Ṣùgbọ́n Ṣùgbọ́n CCONJ _ _ 6 cc _ _ 2 àwọn àwọn DET _ Number=Plur|PronType=Dem 3 det _ _ 3 ẹlòmíràn ẹlòmíràn ADJ _ _ 6 nsubj _ _ 4 nínú nínú ADP _ _ 5 case _ _ 5 wọn wọn PRON _ Case=Nom|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 3 nmod _ _ 6 tọ tọ VERB _ _ 0 root _ _ 7 àwọn àwọn DET _ Number=Plur|PronType=Dem 8 det _ _ 8 Farisí farisí PROPN _ _ 6 obj _ _ 9 lọ lọ VERB _ _ 6 compound:svc _ _ 10 , , PUNCT _ _ 13 punct _ _ 11 wọ́n wọ́n PRON _ _ 13 nsubj _ _ 12 sì sì CCONJ _ _ 13 cc _ _ 13 sọ sọ VERB _ _ 6 conj _ _ 14 fún fún ADP _ _ 15 case _ _ 15 wọn wọn PRON _ Case=Acc|Number=Plur|Person=3|PronType=Prs 13 obl _ _ 16 ohun ohun NOUN _ _ 13 obj _ _ 17 tí tí PRON _ PronType=Rel 19 obj _ _ 18 Jésù jésù PROPN _ _ 19 nsubj _ _ 19 ṣe ṣe VERB _ _ 16 acl _ _ 20 . . PUNCT _ _ 6 punct _ _