Dependency Tree

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest

Select a sentence

s-1 ìbẹ̀rẹ̀ ohun gbogbo Ọlọ́run àwọn ọ̀run àti ayé.
s-2 Ayé rúdurùdu, ó ṣófo, òkùnkùn lójú ibú omi, Ẹ̀mí Ọlọ́run ń rábàbà lójú omi gbogbo.
s-3 Ọlọ́run , Jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ó , ìmọ́lẹ̀ .
s-4 Ọlọ́run i ìmọ́lẹ̀ náà dára, ó ya ìmọ́lẹ̀ náà sọ́tọ̀ kúrò lára òkùnkùn.
s-5 Ọlọ́run pe ìmọ́lẹ̀ náà Ọ̀sán àti òkùnkùn Òru. Àsálẹ́ àti òwúrọ̀ jẹ́ ọjọ́ kìn-ín-ní.
s-6 Ọlọ́run Jẹ́ òfurufú ó àárin àwọn omi láti pààlà àárin àwọn omi.
s-7 Ọlọ́run òfurufú láti ya omi ó òkè òfurufú kúrò lára omi ó orí ilẹ̀. Ó bẹ́ẹ̀.
s-8 Ọlọ́run pe òfúrufú Ọ̀run, àsálẹ́ àti òwúrọ̀ jẹ́ ọjọ́ kejì.
s-9 Ọlọ́run , Jẹ́ omi abẹ́ ọ̀run wọ́ papọ̀ ojúkan, ilẹ̀ gbígbẹ farahàn. Ó bẹ́ẹ̀.
s-10 Ọlọ́run pe ilẹ̀ gbígbẹ náà Ilẹ̀ àti àpapọ̀ omi Òkun: Ọlórun i ó dára.
s-11 Ọlọ́run , Jẹ́ ilẹ̀ ó hu ọ̀gbìn: ewéko yóò máa èṣo àti igi yóò máa so èṣo irú tirẹ̀, ó irúgbìn nínú. Ó bẹ́ẹ̀.
s-12 Ilẹ̀ ọ̀gbìn: ewéko ó ń so èṣo irú tirẹ̀, àti igi ń so èṣo, ó irúgbìn nínú irú tirẹ̀. Ọlọ́run ri ó dára.
s-13 Àsálẹ́ àti òwúrọ̀ jẹ́ ọjọ́ kẹta.
s-14 Ọlọ́run Jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ó ojú ọ̀run, làti pààlà àárin ọ̀sán àti òru, wọn ó máa fún àmì láti mọ àwọn àsìkò, àti àwọn ọjọ́ àti àwọn ọdún,
s-15 wọn ó jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ojú ọ̀run, láti tan ìmọ́lẹ̀ orí ilẹ̀. Ó bẹ́ẹ̀.
s-16 Ọlọ́run ìmọ́lẹ̀ ńlá-ńlá méjì, ìmọ́lẹ̀ ó tóbi láti ṣe àkóso ọ̀sán àti ìmọ́lẹ̀ ó kéré láti ṣe àkóso òru. Ó àwọn ìràwọ̀ pẹ̀lú.
s-17 Ọlọ́run ṣe wọ́n lọ́jọ̀ ojú ọ̀run láti máa tan ìmọ́lẹ̀ si orí ilẹ̀,
s-18 láti ṣàkóso ọ̀sán àti òru àti láti pààlà àárin ìmọ́lẹ̀ àti òkùnkùn: Ọlọ́run i ó dára.
s-19 Àsálẹ́ àti òwúrọ jẹ́ ọjọ́ kẹrin.
s-20 Ọlọ́run , Jẹ́ omi ó kún fún àwọn ohun alààyè, àwọn ẹyẹ ó máa òfurufú.
s-21 Nítorí náà Ọlọ́run àwọn ẹ̀dá alààyè ńlá-ńlá inú òkun, àwọn ohun ẹlẹ́mìí àti àwọn ohun ń rìn onírúurú tiwọn, àti àwọn ẹyẹ abìyẹ́ onírúurú tiwọn. Ọlọ́run i ó dára.
s-22 Ọlọ́run súre fún wọn, ó , máa i, máa pọ̀ i, kún inú omi òkun, àwọn ẹyẹ náà máa pọ̀ i orí ilẹ̀.
s-23 Àsálẹ́ àti òwúrọ̀ jẹ́ ọjọ́ kárùn-ún.
s-24 Ọlọ́run , ilẹ̀ ó ohun alààyè jáde onírúurú wọn: ẹran ọ̀sìn, àwọn ohun afàyàfà àti àwọn ẹran inú igbó, ọ̀kọ̀ọ̀kan irú tirẹ̀. Ó bẹ́ẹ̀.
s-25 Ọlọ́run ẹranko inú igbó àti ẹran ọ̀sìn gbogbo irú tirẹ̀ àti gbogbo ohun alààyè ń rìn ilẹ̀ irú tirẹ̀. Ọlọ́run i ó dára.
s-26 Lẹ́yìn náà ni Ọlọ́run , jẹ́ a ènìyàn àwòrán ara wa, gẹ́gẹ́ àwa ti , wọn ó jọba lórí ẹja òkun, ẹyẹ ojú ọ̀run, ohun ọ̀sìn, gbogbo ilẹ̀ àti lórí ohun gbogbo ń rìn lórí ilẹ̀.

Text viewDownload CoNNL-U