Dependency Tree
Universal Dependencies - Yoruba - YTB
Language | Yoruba |
---|
Project | YTB |
---|
Corpus Part | test |
---|
Select a sentence
Showing 101 - 200 of 118 • previous
s-101
| Àdírẹ́ẹ̀sì e-mail yín kò ní hàn síta nígbà tí àwọn oníṣe míràn bá a yín pàdé. |
s-102
| Kò sì áwọ́n iyipada ni akókò yì ti o ba àwon ìlànà yí mu. |
s-103
| Lọ́wọ́lọ́wọ́ kò sí ìkọ̀ nínú ojúewé yìí. |
s-104
| Ẹ le wá àkọlé ojúewé yìí nínú àwọn ojúewé mìíràn, tàbí wá àwọn àkọọ́lẹ̀ tó bámu, sùgbọ́n ẹ kò ní àṣẹ láti ṣ'ẹ̀dá ojúewé yìí. |
s-105
| Robert Lavinsky, PhD, ti ṣọrẹ ibùdó dátà gbogbo àwọ àwòrán rẹ̀ ní mindat.org (ó tó bíi 29,000) àti gbogbo àwọn àwòrán láti ibi ojúewé ìtakùn rẹ̀ irocks.com fún Wikimedia Commons. |
s-106
| Bákanáà ó tún ti ṣe ìfilọ̀ iye àwórán bíi 20,000 láti inú ìkápamọ́ rẹ̀ fún lílò bóbá ṣe yẹ. |
s-107
| À únfẹ́ ìrànlọ́wọ́ láti ṣe ìyípadà ìjúwe gbogbo àwọn àwòrán náà, ṣíṣèyẹ̀wò wọn ní irocks.com bóyá àwòrán kan kò sí, àti láti rù wọ́n sókè sí Commons. |
s-108
| Ẹ le kà nípa bí ẹ ṣe le ràn wá lọ́wọ́ níbí. |
s-109
| Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. |
s-110
| Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. |
s-111
| Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
s-112
| Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́. |
s-113
| Ẹ wo Àwọn Ọ̀rọ̀ Àdéhùn Ìlò fún ẹ̀kúnrẹ́rẹ́. |
s-114
| Ní ayé àtijọ́ àwọn onímọ́ ìṣirò mọ nọ́mbà tóṣòro gẹ́gẹ́ bíi nọ́mbà tí kòsí. |
s-115
| A lè sọ pé àwón nọ́mbà gidi je nọ́mbà tósòro pelu apá tíkòsi´ tó jé òdo; eyun pé nọ́mbà gidi a jẹ́ bakanna mọ́ nọ́mbà tósòro a+0i. |
s-116
| Fún àpẹrẹ, 3 + 2i jé nọ́mbà tósòro, pẹ̀lú apá gidi to jẹ 3 ati apá tíkòsi´ to jẹ 2. |
s-117
| Àwon nọ́mbà tósòro se ròpọ̀, yọkúrò, sọdipúpọ̀ tàbi sèpínpiń gẹ́gẹ́ bi a ti n se fun àwon nọ́mbà gidi, be ni wón sì ní ìdámọ̀ tó lẹ́wà mìíràn. |
s-118
| Fún àpẹrẹ, nọ́mbà gidi nìkan kò ní ojúùtú fún ìdọ́gba aljebra alápọ̀ọ́nlépúpọ̀ (polynomial) pẹ̀lú nọ́mbà àfise gidi (coefficient), sùgbọ̀n àwọn nọ́mbà tósòro ní. |
Text view
•
Download CoNNL-U