Dependency Tree

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest

Select a sentence

Showing 1 - 100 of 118 • previousnext

s-1 Ẹ̀gbà ọrùn ìbòju Benin jẹ́ ẹ̀gbà ọrùn wọ́n gbẹ́ lére ó jẹ́ àwòrán akọni obìrin a mọ̀ si ìyá wa Olorì Idia ti ọ̀rundún mẹ́rìndínlógún ṣẹ́yìn.
s-2 Ọmọ rẹ̀ Esigie ó jẹ́ ọba ti Benin maa ń wọ́ èyí ó jọọ́ fún àwọn ọmọ ogun ẹ̀yìn ìya olorì.
s-3 Ibojú yìí méjì ó jọ ara wọn: Ìkan Ilé ọnà ti a mọ̀ British Museum ìlú London ìkejì ilé ọnà a mọ̀ Metropolitan Museum of Art ìlú New York.
s-4 Àwọn àpẹẹrẹ rẹ̀ lórí àkọ́lé kan náà Seattle Art Museum àti Linden Museum, ìkan ilé ibi wọ́n gba òpò eniyan láyè láti wọ̀, gbogbo rẹ̀ wọ́n nígbà ìwádí lọ ìlú Benin ọdún 1897.
s-5 Ìbojú yìí ti di àmì ìdánimọ̀ lóde òní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà láti ìgbà ìpéjọ-pọ̀ kan a mọ̀ FESTAC 77 ó wáyé ọdún 1977.
s-6 Ìrísí àti Ìwúlò rẹ̀.
s-7 ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ó ìrísí èyí ó jọ Ìbojú Ìbílẹ̀ Aláwọ̀dúdú, ībòjú kékeré òhún gígùn rẹ̀ ju ìwòn 24cm lọ kìí ṣé fún wíwọ̀ sójú, Ọba wọ̀ọ́ sọ́rùn ( ó maa mu) tàbí bi 'ìlẹ̀kẹ̀ ìbàdí' (èyí ó maa ayẹyẹ ó fẹ́ sẹe mu).
s-8 Èyí ó ilé ọnà Met àti èyí ó ilé ọnà British fẹ́ jọ ara wọn, méjèèjì ni ó jẹ́ àwòràn Olorì Idia.
s-9 Wọn dárà ìlẹ̀kẹ̀ si lórí, lọ́rùn, ègbẹ́ níwájú orí àti gbígbẹ́ èyí ó fàyè ọ̀nà méjì wọ́n fi ẹ̀gbà kọ́.
s-10 Lóde òní àwọn ènìyàn máa ń gbé onírú irú àworan ó jọ́ọ níbi ayẹyẹ láti ẹbọra búrúkú, ṣùgbọ́n ọrundún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn, wọ́n maa lòó fún ayẹyẹ ìya ọba.
s-11 Ó dàbí wípé ìbẹ̀rẹ̀ ọrúndún mẹ́rìndínlógún sẹ́yìn ni wọ́n gbẹ́ àwọn Ìbòjú méjèèjì, bóya ọdún 1520, nígbà Olorì Idia, ìyá ọba Oba Esigie, jẹ́ aládájọ́ ilé ẹjọ́ ti Benin.
s-12 Akọni obìnrin.
s-13 Irú àwòrán yìí wọ́pọ̀ iṣẹ́ ọnà ilẹ̀ Benin, àti ipò Idia, iṣẹ̀ṣe àwọn Edo mọ̀ 'obìnrin kan ṣoṣo lọ sógun', ó da yàtọ̀, wọ́n oyèIyoba tàbí Ìyá Olori ̀́n sílẹ̀ fun Ìwérí rẹ̀ jẹ́ ara irú irun wọ́n ń ẹnu àparò, a dáadára àfihàn orí edẹ Olorì Idia.
s-14 Ìwérí rẹ̀ ó rẹwà àti ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn rẹ̀ ìlẹ̀kẹ̀ roboto ('ọlà'), wọ́n fún ìya wa olorì láàfàní láti máa wọ̀, léyí ó jẹ́ olóyè ni ówà fún.
s-15 Ìlẹ̀kẹ̀ pupa yìí àti aṣọ pupa, ti fìgbàkan fún àwọn olókìkí, wọ́n ti ri lóde òní gẹ́gẹ́ bi ara imùra ìbílẹ̀ Edo.
s-16 iwájú orí ìbòjú méjì yìí, ìlà mẹ́rin níbẹ̀, ó dúro ṣangílítí òkè ojú kànkan, irin méjì ṣe àpèjúwe ilà yìí.
s-17 Irin ni wọ́n fi ṣe ibi ojú rẹ̀.
s-18 Àmì fún okùn òwò.
s-19 Ibi funfun ìwò ẹ̀fọ̀ wọ́n fi ṣe ìwòjú yìí jẹ́ àpẹẹrẹ òòṣà Olokun.
s-20 ó ṣe yìí, wọ́n nìkan nítórí wọ́n lọ ìwo ẹfọ̀ ó wúlò ó ṣeétà lówó gọbọhi, ṣùgbọ́n àwọ̀ rẹ̀ tún jẹ́ àpẹ́ẹrẹ òòṣà ó pẹ̀lú olá Oba Benin.
s-21 Ihò ó ibi oun ẹ̀ṣọ́ rẹ̀ àti ibi ọrùn rẹ̀ jẹ́ àpẹẹrẹ ìlẹ̀kẹ̀ ọrùn àwọn ọkùnrin Àgùdà maa ń fi ṣẹ̀ṣọ́, ó jẹ́ wípé àwòrán mọ́kànlá bẹ́ẹ̀ ilé ọnà ìbòjú Bìrìtìkó àti mẹ́tàlá ilé ọnà Met ó ṣe àfihàn àwọn ọkùnrin Àgùdá wọ́n múra àwọn ènìyàn dúdú.
s-22 Orùn ìwòjú ó ilé ọnà Metropolitant (Met) jọ mọ́ èyí wọ́n fi àwọn ọkùnrin Àgùdà ṣẹ̀ṣọ́ rẹ̀ (ẹ̀gbẹ́ rẹ̀ ti bàjẹ́ díẹ̀), ó tilẹ̀ jẹ́ , ọrùn ìwòjú èyí ó ilé ọnà Bìrìtìkó jẹ́ èyí wọ́n fi igi tàbí irin gbẹ́.
s-23 Àwọn Àgùdà jẹ́ oníṣòwò pẹ̀lú àwọn Benin nígbàyẹn gẹ́gẹ́ wọ́n ti ṣàpèjúwe rẹ̀, ó jẹ́ àpẹrẹ́ àjọṣepọ̀ láàrin omi àti ilẹ̀.
s-24 ti tẹ̀lé ìjápọ̀ mọ́ ojúewé .
s-25 Láti ojúewé bẹ̀rẹ̀ síní tẹ́kọ inú àpótí ìsàlẹ̀ ( wo ojúewé ìrànlọ́wọ́ fun ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ ).
s-26 T'óbá sepé àsìse gbé yin bi, kọn bọ́tìnì ìpadàsẹ́yìn.
s-27 Orúkọ dàbí àmì ìdánimọ̀ a fi ń ẹnìkọ̀ọ̀kan mọ̀ orúkọ jẹ́ á Táyé mọ̀ yàtọ̀ Kẹ́hìndé, káàkiri àgbáyé a ń lo orúkọ , ọ̀pọ̀ ìgbà orúkọ máa ń fi ènìyàn ṣe jẹ́ láwùjọ hàn àti pe orúkọ ẹni le buyì fún ènìyàn láwùjọ.
s-28 Ìṣọmọlórúkọ láàárín àwọn Yorùbá dàbí ìgbà a ń ṣe ọdún torí tọmọ, taya, tẹbí, tará, tìyekan àti àwọn alábáse gbogbo yóò pésẹ̀ ibẹ̀.
s-29 Láyé àtijọ́ ọjọ́ keje wọ́n máa ń sọ ọmọ obìnrin lórúkọ nígbà tọmọ kùnrin jẹ́ ọjọ́ kẹsàn-án èyí ìbámu pẹ̀lú èrò àti ìgbàgbọ́ wọn eegun méje ni obìnrin nígbà tọkùnrin jẹ́ mẹ́sàn-án.
s-30 ṣùgbọ́n lóde-òní ohun gbogbo ti padà àti obìnrin àti ọkùnrin ni wọ́n ń sọ lórúkọ lọ́jẹ́ kẹjọ.
s-31 a ṣe ń ṣe ìṣọmọlórúkọ yàtọ̀ láti idílẹ́ ìdílé ṣùgbọ́n ọjọ́ ìṣọmọlórúkọ yìí àgbà ilé lóbìnrin yóò gbé ọmọ yìí lọ́wọ́ yóò ẹsẹ̀ rẹ̀ tẹ ilẹ̀.
s-32 Orísìírísìí nǹkan wọ́n ń níbi ìsọmọlórúkọ bíi Oyin, Epo, Iṣu, Ẹja,
s-33 Iyọ̀, Omi, abbl láti jẹ́ ọmọ yìí mọ ayé se wọn yóò gbogbo ohun a sókè yìí tọ́ ọmọ lẹ́nu , wọ́n máa ń wọ́n omi ọmọ yìí lára tàbí wọ́n da omi orí páànù wọn ó jẹ́ ó kán si ọmọ yìí lára.
s-34 Orúkọ dabí fèrèsé ó fi ÀṢÀ, Èsìn, Iṣé àti ìgbàgbọ́ àwọn Yorùbá hàn.
s-35 Oríṣìíríṣìí nǹkan la fi ń sọmọ lórúkọ bíi OYIN, EPO, IYỌ, ẸJA, OMI abbl.
s-36 Oríṣìíríṣìí nǹkan le yọrí orúkọ a sọ ọmọ.
s-37 Genevieve Nnaji ọjọ́ ìbí May 3, 1979 Mbaise, Ipinle Imo, jẹ́ òṣeré filmu ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà.
s-38 2005 ó gba Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà gẹ́gẹ́ bíi Òṣeré Obìnrin Dídárajùlọ.
s-39 Ìgbà èwe: Ìlú Èkó ni Genevieve Nnaji ti dàgbà.
s-40 Ìkẹrin nínú àwọn ọmọ méjọ, ọ̀mọ̀wé ni àwọn òbí rẹ̀.
s-41 Bàbá rẹ̀ siṣẹ́ gẹ́gẹ́ bíi onímọ̀ iṣẹ́-ẹ̀rọ (engineer) nígbàtí ìyá rẹ̀ jẹ́ olùkọ́.
s-42 Ò lọ ilé ẹ̀kọ́ Methodist Girls College Yaba, lẹ́yìn rẹ̀ ó tẹrísí Yunifásítì ìlú Èkó.
s-43 Níbẹ̀ lówà ti bẹ̀rẹ̀ ṣiṣẹ́ díèdíẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré ni Nollywood.
s-44 Nnaji bẹ̀rẹ̀ ìṣèré rẹ̀ láti ọmọdé ninu eré tẹlifísọ̀n Ripples nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 8.
s-45 Ó tún ṣe ìpolówó ọjà bíi méèló kan nínú èyí jẹ́ fún Pronto àti ọṣẹ ìfọsọ Omo.
s-46 2004 ó di aṣojú fún ọsẹ ìwẹ̀ Lux, ìbáṣe ìgbọ̀wọ́ tọ́ fa èrè ínlá fun.
s-47 Ni 1998 nígbà tójẹ́ ọmọ ọdún 19 wọn ṣe àmúhàn rẹ̀ àwọn olólùfẹ́ filmu ni Naijiria pẹ̀lú filmu ún jẹ́ Most Wanted.
s-48 Lẹ́yìn rẹ̀ ó tún ṣe àwọn filmu bíi Last Party, Mark of the Beast àti Ijele.
s-49 Ó ti kópa nínúu filmu 80 ni Nollywood.
s-50 Nnaji ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀bùn fún iṣẹ́ rẹ̀ ìkan nínú wọn jẹ́ gẹ́gẹ́ bíi òṣèré obìnrin dára jùlọ fún 2001 City People Awards, ó tún gba ẹ̀yẹ gẹ́gẹ́ bíi Òṣèré Obìnrin Tódárajùlọ 2005 nínú àwọn Ẹ̀bùn Akadẹ́mì Filmu ilẹ̀ Áfríkà.
s-51 2004, ó tọwọ́bọ̀wé pẹ̀lú ilé ìṣẹ́ àwo-orin ilẹ̀ Ghana, EKB Records láti gbé àwo-orin àkọ́kọ́ rẹ̀ jáde ún jẹ́ One Logologo Line, àdàlú orin R&B, Hip-Hop àti Urban.
s-52 2008 ni ó ṣí ilé ìránsọ rẹ̀ ún jẹ́ 'St.
s-53 Genevieve', èyí ún ṣọrẹ ìdámẹ́ẹ̀wá èrè rẹ̀.
s-54 Nollywood, Genevieve Nnaji jẹ́ ọ̀kan nínú àwọn owó iṣẹ́ wọn pọ̀jùlọ.
s-55 Ẹgbẹ́ Akọ́mọlédè àti àṣà Yorùbá jẹ́ àgbárí-jọ-pọ Àwọn olùkọ́ nílé ìwé alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀, girama àti ilé ẹ̀kọ́ fásitì ti ìjọba pẹ̀lú aládàáni jákè jádò ilẹ̀ Nàjíríà.
s-56 Ẹgbẹ́ yìí ń ṣojú Yorùbá níbi ìgbé lárugẹ èdè, àṣà àti ìdàgbà sókè ìṣèṣe Yorùbá.
s-57 Alhaji Lukman Ẹ̀bùn Olóyèdé Ọláìyá gbogbo ènìyàn mọ̀ Igwe jẹ́ ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti òṣèré sinimá àgbéléwò.
s-58 Wọ́n Ẹ̀bùn Olóyèdé ilú Kẹ́nta, Òkè-Èjìgbò Abẹ́òkúta.
s-59 Ètò ẹ̀kọ́ rẹ̀: Ọláìyá lọ ilé ìwé alákọ̀ọ́bọẹ̀rẹ̀ St.Judes ìlú Abẹòkúta ìpínlẹ̀ Ògùn, ó tún síwájú nínú ẹ̀kọ́ rẹ̀ ilé ìwé girama (Premier) Abẹ́òkúta.
s-60 Lẹ́yìn ó parí èyí ni ó lọ kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìbára ẹni sọọ̀rọ̀ ilé ẹ̀kọ́ gbogbo-nìṣe Moshood Abíọ́lá Òjéèrè ìpínlẹ̀ Ògùn.
s-61 Iṣẹ́ gẹ́gẹ́ òṣèré: Ọláìyá dara pọ̀ mọ́ ẹgbẹ́ òṣèré Musibau Shodimú àsìkò ọdún 1970s ó Abẹ́òkúta nígbà náà.
s-62 Ojúewé yìí ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ kan Wikipedia nínú.
s-63 Ó jẹ́ èso ìfohùnṣọ̀kan, bẹ́ ẹ̀ ni ó jẹ́ gbígbàgbọ́ gbogbo àwọn oníṣe gbọ́dọ̀ tẹ̀lé wọn gbámúgbámú.
s-64 le ṣàtúnṣe àkóónú ojúewé náà sùgbọ́n jọ̀wọ́ mọ́ ṣe ìyípadà ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ kankan láì kọ́kọ́ filọ àwọn oníṣe yìókù.
s-65 Ojú ewé yìí kúkurú: Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà Wikipédíà jẹ́ Ojú ewé tọ́ka ìlànà a gbọ́dọ̀ tẹ̀lé àwùjọ Wikipédíà.
s-66 Ìmúlò yìí ṣe àpèjúwe a ṣe máa ìdàgbàsókè àwọn Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà Wikipédíà.
s-67 Àwùjọ Wikipédíà ṣe Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà yìí lati ṣe àpèjúwe ọ̀nàn dára jùlọ lati ṣàgbékalẹ́ ọ̀rọ̀, yanjú ìjà àti lati ìtẹ̀síwájú ìlépa wa fún ṣiṣẹda ìmọ ọfẹ.
s-68 pọn dandan lati ka Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà ojú ewé yìí lati bẹ̀ẹ̀rẹ̀ ṣíṣàtúnkọ.
s-69 Orígun máàrún Wikipédíà ṣe àlàyé ránpẹ́ nípa ìlànà Wikipédíà.
s-70 ó ti lẹ̀ jẹ́ wípé Wikipédíà gba lílé ati sáré òfin, àwọn ojú ewé Ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà ti ṣàgbékalẹ́ ohun gbogbo ṣe gbọ́dọ̀ máa lọ.
s-71 Ìmúlò ṣe àlàyé àwọn ìlànà alàtúnkọ gbọ́dọ̀ tẹ̀lé àwùjọ Wikipédíà.
s-72 Bakan náà ni ìtọ́nisọ́nà ṣe àlàyé ọ̀nàn a yàn lááyò lati tẹ̀lé ìlànà yìí.
s-73 A gbọ́dọ̀ máa lo ìtọ́nisọ́nà pẹ̀lú láákáyè.
s-74 Àjọ kòsí fún èrè Wikimedia Foundation ni ó n se alàkóso Wikipédíà pẹ̀lú àwọn òfin kan (wo ibí fún àkójọ Ìmúlò).
s-75 Tún wo Ipa Jimmy Wales ṣùgbọn, Wikipédíà ṣàkóso ara ẹ̀ nipase oníwé àwùjọ.
s-76 Ìmúlò jẹ́ ohun gbogbo alàtúnkọ gbà.
s-77 Osì tún se àpèjúwe ìlànà a gbọ́dọ̀ tẹ̀lé àwùjọ.
s-78 Gbogbo ojú ewé ìmúlò Wikipédíà:
s-79 Gbogbo ìmúlò àti ìtọ́nisọ́nà àti.
s-80 Fún kúkurú ojúlówó àwọn ìmúlò, wo Wikipédíà:
s-81 Àwọn ìmúlò.
s-82 Wikipedia Yorùbá únlo àwọn ìpinu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ fún Wikipedia èdè Gẹ̀ẹ́sì.
s-83 fẹ́ lọ ojúewé ọ̀rọ̀ rẹ̀ láti fọ̀rọ̀wérọ̀ nípa wọn tàbí dámọ̀ràn ìpínu ọ̀nà ìṣiṣẹ́ míràn.
s-84 Ṣíṣàtúnṣe ojúewé yìí látọwọ́ àwọn oníṣe tuntun tàbí àwọn oníṣe aláìtíìforúkọsílẹ̀ jẹ́ tìpa lọ́wọ́lọ́wọ́.
s-85 Ojúewé yìí lọ́wọ́lọ́wọ́ jẹ́ dídá àbò díẹ̀ nítoríẹ̀ àwọn oníṣe aforúkọsílẹ̀ wọ́n ti fẹsẹ̀múlẹ̀ nìkan ni wọ́n le ṣàtúnṣe rẹ̀.
s-86 Kílódé ojúewé ṣe àbò?
s-87 tilẹ jẹ́ ọ̀pọ̀ àwọn àyọkà ni wọ́n le jẹ́ títúnṣe látọwọ́ olúkúlùkù, àbò díẹ̀ pọndandan gbà míi láti dínà ìbàjẹ́ àwọn ojúewé gbajúmọ̀.
s-88 Ìdí fún àbò nínú àkọọ́lẹ̀ àbo.
s-89 àkọsílẹ̀ abáramu nínú àkọọ́lẹ̀ àbò, ojúewé náà le ti jẹ́ yíyí nípò lẹ́yìn ìṣe àbò si.
s-90 Kíni mo le ṣe?
s-91 àkópamọ́ oníṣe kọ́kọ́ wọlẹ́.
s-92 àkópamọ́, le ìkan; lẹ́yìn ọjọ́ 4 àti àtúnṣe 10, ó le ṣàtúnṣe àwọn ojúewé àbò díẹ̀.
s-93 sọ̀rọ̀ nípa ojúewé yìí pẹ̀lú àwọn ẹlòmíràn.
s-94 tọrọ ìjáwọ́ àbò ojúewé náà.
s-95 ka ṣele bẹ̀rẹ̀ síní ṣàtúnṣe Wikipedia.
s-96 ṣàkíyèsí àsìṣe tàbí àbá fún àtúnṣe, le tọrọ àtúnṣe, nípa títẹ klik àjápọ̀ ìsàlẹ̀, tẹ̀lẹ́ àwọn ìlànà ibẹ̀.
s-97 Alámùójútó kan yíò ṣe àtúnṣe náà fun yín.
s-98 jọ̀wọ́ kọ́kọ́ wọ ojúewé ìfọ̀rọ̀wérọ̀ àyọkà náà, bóyá ọ̀rọ̀ ùnlọ nípa rẹ̀.
s-99 Àdírẹ́ẹ̀sì e-mail yín ṣe dandan, ṣùgbọ́n yíò jẹ́ lílò fún ìtúntò ọ̀rọ̀ìpamọ́, gbàgbé ọ̀rọ̀ìpamọ́ yín.
s-100 tún le yàn láti jẹ́ àwọn míràn ó a yín pàdé pẹ̀lú e-mail láti inú àjápọ̀ lórí ojúewé oníṣe tàbí ọ̀rọ̀ yín.

Text viewDownload CoNNL-U