Sentence view

Universal Dependencies - Yoruba - YTB

LanguageYoruba
ProjectYTB
Corpus Parttest


[1] tree
ìbẹ̀rẹ̀ ohun gbogbo Ọlọ́run àwọn ọ̀run àti ayé.
s-1
GEN_1.1
Ní ìbẹ̀rẹ̀ ohun gbogbo Ọlọ́run dá àwọn ọ̀run àti ayé.
In the beginning God created the heaven and the earth.
[2] tree
Ayé rúdurùdu, ó ṣófo, òkùnkùn lójú ibú omi, Ẹ̀mí Ọlọ́run ń rábàbà lójú omi gbogbo.
s-2
GEN_1.2
Ayé sì wà ní rúdurùdu, ó sì ṣófo, òkùnkùn sì wà lójú ibú omi, Ẹ̀mí Ọlọ́run sì ń rábàbà lójú omi gbogbo.
And the earth was without form, and void; and darkness was upon the face of the deep. And the Spirit of God moved upon the face of the waters.
[3] tree
Ọlọ́run , Jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ó , ìmọ́lẹ̀ .
s-3
GEN_1.3
Ọlọ́run sì wí pé, “Jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ kí ó wà,” ìmọ́lẹ̀ sì wà.
And God said, Let there be light: and there was light.
[4] tree
Ọlọ́run i ìmọ́lẹ̀ náà dára, ó ya ìmọ́lẹ̀ náà sọ́tọ̀ kúrò lára òkùnkùn.
s-4
GEN_1.4
Ọlọ́run rí i pé ìmọ́lẹ̀ náà dára, ó sì ya ìmọ́lẹ̀ náà sọ́tọ̀ kúrò lára òkùnkùn.
And God saw the light, that it was good: and God divided the light from the darkness.
[5] tree
Ọlọ́run pe ìmọ́lẹ̀ náà Ọ̀sán àti òkùnkùn Òru. Àsálẹ́ àti òwúrọ̀ jẹ́ ọjọ́ kìn-ín-ní.
s-5
GEN_1.5
Ọlọ́run sì pe ìmọ́lẹ̀ náà ní “Ọ̀sán” àti òkùnkùn ní “Òru.” Àsálẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ kìn-ín-ní.
And God called the light Day, and the darkness he called Night. And the evening and the morning were the first day.
[6] tree
Ọlọ́run Jẹ́ òfurufú ó àárin àwọn omi láti pààlà àárin àwọn omi.
s-6
GEN_1.6
Ọlọ́run sì wí pé “Jẹ́ kí òfurufú kí ó wà ní àárin àwọn omi láti pààlà sí àárin àwọn omi.”
And God said, Let there be a firmament in the midst of the waters, and let it divide the waters from the waters.
[7] tree
Ọlọ́run òfurufú láti ya omi ó òkè òfurufú kúrò lára omi ó orí ilẹ̀. Ó bẹ́ẹ̀.
s-7
GEN_1.7
Ọlọ́run sì dá òfurufú láti ya omi tí ó wà ní òkè òfurufú kúrò lára omi tí ó wà ní orí ilẹ̀. Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
And God made the firmament, and divided the waters which were under the firmament from the waters which were above the firmament: and it was so.
[8] tree
Ọlọ́run pe òfúrufú Ọ̀run, àsálẹ́ àti òwúrọ̀ jẹ́ ọjọ́ kejì.
s-8
GEN_1.8
Ọlọ́run sì pe òfúrufú ní “Ọ̀run,” àsálẹ́ àti òwúrọ̀ sì jẹ́ ọjọ́ kejì.
And God called the firmament Heaven. And the evening and the morning were the second day.
[9] tree
Ọlọ́run , Jẹ́ omi abẹ́ ọ̀run wọ́ papọ̀ ojúkan, ilẹ̀ gbígbẹ farahàn. Ó bẹ́ẹ̀.
s-9
GEN_1.9
Ọlọ́run sì wí pé, “Jẹ́ kí omi abẹ́ ọ̀run wọ́ papọ̀ sí ojúkan, kí ilẹ̀ gbígbẹ sì farahàn.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
And God said, Let the waters under the heaven be gathered together unto one place, and let the dry land appear: and it was so.
[10] tree
Ọlọ́run pe ilẹ̀ gbígbẹ náà Ilẹ̀ àti àpapọ̀ omi Òkun: Ọlórun i ó dára.
s-10
GEN_1.10
Ọlọ́run sì pe ilẹ̀ gbígbẹ náà ní “Ilẹ̀” àti àpapọ̀ omi ní “Òkun:” Ọlórun sì rí i wí pé ó dára.
And God called the dry land Earth; and the gathering together of the waters called he Seas: and God saw that it was good.
[11] tree
Ọlọ́run , Jẹ́ ilẹ̀ ó hu ọ̀gbìn: ewéko yóò máa èṣo àti igi yóò máa so èṣo irú tirẹ̀, ó irúgbìn nínú. Ó bẹ́ẹ̀.
s-11
GEN_1.11
Ọlọ́run sì wí pé, “Jẹ́ kí ilẹ̀ kí ó hu ọ̀gbìn: ewéko tí yóò máa mú èṣo wá àti igi tí yóò máa so èṣo ní irú tirẹ̀, tí ó ní irúgbìn nínú.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
And God said, Let the earth bring forth grass, the herb yielding seed, and the fruit tree yielding fruit after his kind, whose seed is in itself, upon the earth: and it was so.
[12] tree
Ilẹ̀ ọ̀gbìn: ewéko ó ń so èṣo irú tirẹ̀, àti igi ń so èṣo, ó irúgbìn nínú irú tirẹ̀. Ọlọ́run ri ó dára.
s-12
GEN_1.12
Ilẹ̀ sì hù ọ̀gbìn: ewéko tí ó ń so èṣo ní irú tirẹ̀, àti igi tí ń so èṣo, tí ó ní irúgbìn nínú ní irú tirẹ̀. Ọlọ́run sì ri pé ó dára.
And the earth brought forth grass, and herb yielding seed after his kind, and the tree yielding fruit, whose seed was in itself, after his kind: and God saw that it was good.
[13] tree
Àsálẹ́ àti òwúrọ̀ jẹ́ ọjọ́ kẹta.
s-13
GEN_1.13
Àsálẹ́ àti òwúrọ̀ jẹ́ ọjọ́ kẹta.
And the evening and the morning were the third day.
[14] tree
Ọlọ́run Jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ó ojú ọ̀run, làti pààlà àárin ọ̀sán àti òru, wọn ó máa fún àmì láti mọ àwọn àsìkò, àti àwọn ọjọ́ àti àwọn ọdún,
s-14
GEN_1.14
Ọlọ́run sì wí pé “Jẹ́ kí ìmọ́lẹ̀ kí ó wà ní ojú ọ̀run, làti pààlà sí àárin ọ̀sán àti òru, kí wọn ó sì máa wà fún àmì láti mọ àwọn àsìkò, àti àwọn ọjọ́ àti àwọn ọdún,
And God said, Let there be lights in the firmament of the heaven to divide the day from the night; and let them be for signs, and for seasons, and for days, and years:
[15] tree
wọn ó jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ojú ọ̀run, láti tan ìmọ́lẹ̀ orí ilẹ̀. Ó bẹ́ẹ̀.
s-15
GEN_1.15
Kí wọn ó jẹ́ ìmọ́lẹ̀ ní ojú ọ̀run, láti tan ìmọ́lẹ̀ sí orí ilẹ̀.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
And let them be for lights in the firmament of the heaven to give light upon the earth: and it was so.
[16] tree
Ọlọ́run ìmọ́lẹ̀ ńlá-ńlá méjì, ìmọ́lẹ̀ ó tóbi láti ṣe àkóso ọ̀sán àti ìmọ́lẹ̀ ó kéré láti ṣe àkóso òru. Ó àwọn ìràwọ̀ pẹ̀lú.
s-16
GEN_1.16
Ọlọ́run dá ìmọ́lẹ̀ ńlá-ńlá méjì, ìmọ́lẹ̀ tí ó tóbi láti ṣe àkóso ọ̀sán àti ìmọ́lẹ̀ tí ó kéré láti ṣe àkóso òru. Ó sì dá àwọn ìràwọ̀ pẹ̀lú.
And God made two great lights; the greater light to rule the day, and the lesser light to rule the night: he made the stars also.
[17] tree
Ọlọ́run ṣe wọ́n lọ́jọ̀ ojú ọ̀run láti máa tan ìmọ́lẹ̀ si orí ilẹ̀,
s-17
GEN_1.17
Ọlọ́run sì ṣe wọ́n lọ́jọ̀ sí ojú ọ̀run láti máa tan ìmọ́lẹ̀ si orí ilẹ̀,
And God set them in the firmament of the heaven to give light upon the earth,
[18] tree
láti ṣàkóso ọ̀sán àti òru àti láti pààlà àárin ìmọ́lẹ̀ àti òkùnkùn: Ọlọ́run i ó dára.
s-18
GEN_1.18
láti ṣàkóso ọ̀sán àti òru àti láti pààlà sí àárin ìmọ́lẹ̀ àti òkùnkùn: Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.
And to rule over the day and over the night, and to divide the light from the darkness: and God saw that it was good.
[19] tree
Àsálẹ́ àti òwúrọ jẹ́ ọjọ́ kẹrin.
s-19
GEN_1.19
Àsálẹ́ àti òwúrọ jẹ́ ọjọ́ kẹrin.
And the evening and the morning were the fourth day.
[20] tree
Ọlọ́run , Jẹ́ omi ó kún fún àwọn ohun alààyè, àwọn ẹyẹ ó máa òfurufú.
s-20
GEN_1.20
Ọlọ́run sì wí pé, “Jẹ́ kí omi kí ó kún fún àwọn ohun alààyè, kí àwọn ẹyẹ kí ó sì máa fò ní òfurufú.”
And God said, Let the waters bring forth abundantly the moving creature that hath life, and fowl that may fly above the earth in the open firmament of heaven.
[21] tree
Nítorí náà Ọlọ́run àwọn ẹ̀dá alààyè ńlá-ńlá inú òkun, àwọn ohun ẹlẹ́mìí àti àwọn ohun ń rìn onírúurú tiwọn, àti àwọn ẹyẹ abìyẹ́ onírúurú tiwọn. Ọlọ́run i ó dára.
s-21
GEN_1.21
Nítorí náà Ọlọ́run dá àwọn ẹ̀dá alààyè ńlá-ńlá sí inú òkun, àwọn ohun ẹlẹ́mìí àti àwọn ohun tí ń rìn ní onírúurú tiwọn, àti àwọn ẹyẹ abìyẹ́ ní onírúurú tiwọn. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.
And God created great whales, and every living creature that moveth, which the waters brought forth abundantly, after their kind, and every winged fowl after his kind: and God saw that it was good.
[22] tree
Ọlọ́run súre fún wọn, ó , máa i, máa pọ̀ i, kún inú omi òkun, àwọn ẹyẹ náà máa pọ̀ i orí ilẹ̀.
s-22
GEN_1.22
Ọlọ́run súre fún wọn, ó sì wí pé, “Ẹ máa bí sí i, ẹ sì máa pọ̀ sí i, ẹ kún inú omi òkun, kí àwọn ẹyẹ náà sì máa pọ̀ sí i ní orí ilẹ̀.”
And God blessed them, saying, Be fruitful, and multiply, and fill the waters in the seas, and let fowl multiply in the earth.
[23] tree
Àsálẹ́ àti òwúrọ̀ jẹ́ ọjọ́ kárùn-ún.
s-23
GEN_1.23
Àsálẹ́ àti òwúrọ̀ jẹ́ ọjọ́ kárùn-ún.
And the evening and the morning were the fifth day.
[24] tree
Ọlọ́run , ilẹ̀ ó ohun alààyè jáde onírúurú wọn: ẹran ọ̀sìn, àwọn ohun afàyàfà àti àwọn ẹran inú igbó, ọ̀kọ̀ọ̀kan irú tirẹ̀. Ó bẹ́ẹ̀.
s-24
GEN_1.24
Ọlọ́run sì wí pé, “Kí ilẹ̀ kí ó mú ohun alààyè jáde ní onírúurú wọn: ẹran ọ̀sìn, àwọn ohun afàyàfà àti àwọn ẹran inú igbó, ọ̀kọ̀ọ̀kan ní irú tirẹ̀.” Ó sì rí bẹ́ẹ̀.
And God said, Let the earth bring forth the living creature after his kind, cattle, and creeping thing, and beast of the earth after his kind: and it was so.
[25] tree
Ọlọ́run ẹranko inú igbó àti ẹran ọ̀sìn gbogbo irú tirẹ̀ àti gbogbo ohun alààyè ń rìn ilẹ̀ irú tirẹ̀. Ọlọ́run i ó dára.
s-25
GEN_1.25
Ọlọ́run sì dá ẹranko inú igbó àti ẹran ọ̀sìn gbogbo ní irú tirẹ̀ àti gbogbo ohun alààyè tí ń rìn ní ilẹ̀ ní irú tirẹ̀. Ọlọ́run sì rí i pé ó dára.
And God made the beast of the earth after his kind, and cattle after their kind, and every thing that creepeth upon the earth after his kind: and God saw that it was good.
[26] tree
Lẹ́yìn náà ni Ọlọ́run , jẹ́ a ènìyàn àwòrán ara wa, gẹ́gẹ́ àwa ti , wọn ó jọba lórí ẹja òkun, ẹyẹ ojú ọ̀run, ohun ọ̀sìn, gbogbo ilẹ̀ àti lórí ohun gbogbo ń rìn lórí ilẹ̀.
s-26
GEN_1.26
Lẹ́yìn náà ni Ọlọ́run wí pé, “Ẹ jẹ́ kí a dá ènìyàn ní àwòrán ara wa, gẹ́gẹ́ bí àwa ti rí, kí wọn kí ó jọba lórí ẹja òkun, ẹyẹ ojú ọ̀run, ohun ọ̀sìn, gbogbo ilẹ̀ àti lórí ohun gbogbo tí ń rìn lórí ilẹ̀.”
And God said, Let us make man in our image, after our likeness: and let them have dominion over the fish of the sea, and over the fowl of the air, and over the cattle, and over all the earth, and over every creeping thing that creepeth upon the earth.

Edit as listText viewDependency trees